Matiu 10
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
Jesu rán àwọn méjìlá jáde
10 (A)Jesu sì pe àwọn ọmọ-ẹ̀yìn rẹ̀ méjìlá sí ọ̀dọ̀; ó fún wọn ní àṣẹ láti lé ẹ̀mí àìmọ́ jáde àti láti ṣe ìwòsàn ààrùn àti àìsàn gbogbo.
2 Orúkọ àwọn aposteli méjèèjìlá náà ni wọ̀nyí:
ẹni àkọ́kọ́ ni Simoni ẹni ti a ń pè ni Peteru àti arákùnrin rẹ̀ Anderu;
Jakọbu[a] ọmọ Sebede àti arákùnrin rẹ̀ Johanu.
3 Filipi àti Bartolomeu;
Tomasi àti Matiu agbowó òde;
Jakọbu ọmọ Alfeu àti Taddeu;
4 Simoni ọmọ ẹgbẹ́ Sealoti, Judasi Iskariotu, ẹni tí ó da Jesu.
5 (B)Àwọn méjèèjìlá wọ̀nyí ni Jesu ran, ó sì pàṣẹ fún wọn pé: “Ẹ má ṣe lọ sì ọ̀nà àwọn kèfèrí, ẹ má ṣe wọ̀ ìlú àwọn ará Samaria 6 Ẹ kúkú tọ̀ àwọn àgùntàn ilé Israẹli tí ó nù lọ. 7 Bí ẹ̀yin ti ń lọ, ẹ máa wàásù yìí wí pé: ‘Ìjọba ọ̀run kù sí dẹ̀dẹ̀.’ 8 Ẹ máa ṣe ìwòsàn fún àwọn aláìsàn, ẹ si jí àwọn òkú dìde, ẹ sọ àwọn adẹ́tẹ̀ di mímọ́, kí ẹ sì máa lé àwọn ẹ̀mí èṣù jáde. Ọ̀fẹ́ ni ẹ̀yin gbà á, ọ̀fẹ́ ni kí ẹ fi fún ni.
9 “Ẹ má ṣe mú wúrà tàbí fàdákà tàbí idẹ sínú àpò ìgbànú yín; 10 Ẹ má ṣe mú àpò fún ìrìnàjò yín, kí ẹ má ṣe mú ẹ̀wù méjì, tàbí bàtà, tàbí ọ̀pá; oúnjẹ oníṣẹ́ yẹ fún un. 11 Ìlúkílùú tàbí ìletòkíletò tí ẹ̀yin bá wọ̀, ẹ wá ẹni ti ó bá yẹ níbẹ̀ rí, níbẹ̀ ni kí ẹ sì gbé nínú ilé rẹ̀ títí tí ẹ̀yin yóò fi kúrò níbẹ̀. 12 Nígbà tí ẹ̀yin bá sì wọ ilé kan, ẹ kí i wọn. 13 Bí ilé náà bá sì yẹ, kí àlàáfíà yín kí ó bà sórí rẹ̀; ṣùgbọ́n bí kò bá yẹ, kí àlàáfíà yín kí ó padà sọ́dọ̀ yín. 14 Bí ẹnikẹ́ni tí kò bá sì gbà yín, tàbí tí kò gba ọ̀rọ̀ yín, ẹ gbọn eruku ẹ̀ṣẹ̀ yín sílẹ̀ tí ẹ bá ń kúrò ní ilé tàbí ìlú náà. 15 Lóòótọ́ ni mo wí fún yín, yóò sàn fún ìlú Sodomu àti Gomorra ní ọjọ́ ìdájọ́ ju àwọn ìlú náà lọ.
16 “Mò ń rán yín lọ gẹ́gẹ́ bí àgùntàn sáàrín ìkookò. Nítorí náà, kí ẹ ní ìṣọ́ra bí ejò, kí ẹ sì ṣe onírẹ̀lẹ̀ bí àdàbà. 17 (C)Ẹ ṣọ́ra lọ́dọ̀ àwọn ènìyàn nítorí wọn yóò fi yín le àwọn ìgbìmọ̀ ìgbèríko lọ́wọ́ wọn yóò sì nà yín nínú Sinagọgu. 18 Nítorí orúkọ mi, a ó mú yín lọ síwájú àwọn baálẹ̀ àti àwọn ọba, bí ẹlẹ́rìí sí wọn àti àwọn aláìkọlà. 19 Nígbà tí wọ́n bá mú yín, ẹ má ṣe ṣàníyàn ohun tí ẹ ó sọ tàbí bí ẹ ó ṣe sọ ọ́. Ní ojú kan náà ni a ó fi ohun tí ẹ̀yin yóò sọ fún yín. 20 Nítorí pé kì í ṣe ẹ̀yin ni ó sọ ọ́, bí kò ṣe Ẹ̀mí Baba yín tí ń sọ̀rọ̀ nípasẹ̀ yín.
21 (D)“Arákùnrin yóò sì fi arákùnrin fún pípa. Baba yóò fi àwọn ọmọ rẹ̀ fún ikú pa. Àwọn ọmọ yóò ṣọ̀tẹ̀ sí òbí wọn, wọn yóò sì mú kí a pa wọ́n. 22 Gbogbo ènìyàn yóò sì kórìíra yín nítorí mi, ṣùgbọ́n gbogbo ẹni tí ó bá dúró ṣinṣin dé òpin ni a ó gbàlà. 23 Nígbà tí wọn bá ṣe inúnibíni sì i yín ní ìlú kan, ẹ sálọ sì ìlú kejì. Lóòótọ́ ni mo wí fún yín, ẹ̀yin kò tì í le la gbogbo ìlú Israẹli já tán kí Ọmọ Ènìyàn tó dé.
24 (E)“Akẹ́kọ̀ọ́ kì í ju olùkọ́ rẹ̀ lọ, bẹ́ẹ̀ ni ọmọ ọ̀dọ̀ kì í ju ọ̀gá rẹ̀ lọ. 25 Ó tọ́ fún akẹ́kọ̀ọ́ láti dàbí olùkọ́ rẹ̀ àti fún ọmọ ọ̀dọ̀ láti rí bí ọ̀gá rẹ̀. Nígbà tí wọ́n bá pe baálé ilé ní Beelsebulu, mélòó mélòó ni ti àwọn ènìyàn ilé rẹ̀!
26 (F)(G) “Nítorí náà, ẹ má ṣe bẹ̀rù wọn, nítorí kò sí ohun tó ń bọ̀ tí kò ní í fi ara hàn, tàbí ohun tó wà ní ìkọ̀kọ̀ tí a kò ní mọ̀ ni gbangba. 27 Ohun tí mo bá wí fún yín ní òkùnkùn, òun ni kí ẹ sọ ní ìmọ́lẹ̀. Èyí tí mo sọ kẹ́lẹ́kẹ́lẹ́ sì etí yín ni kí ẹ kéde rẹ́ lórí òrùlé. 28 Ẹ má ṣe bẹ̀rù àwọn tí ó le pa ara nìkan; ṣùgbọ́n tí wọn kò lè pa ẹ̀mí. Ẹ bẹ̀rù Ẹni tí ó le pa Ẹ̀mí àti ara run ní ọ̀run àpáàdì. 29 Ológoṣẹ́ méjì kọ́ ni à ń tà ní owó idẹ wẹ́wẹ́ kan? Síbẹ̀ kò sí ọ̀kan nínú wọn tí yóò ṣubú lu ilẹ̀ lẹ́yìn Baba yin. 30 Àti pé gbogbo irun orí yín ni a ti kà pé. 31 Nítorí náà, ẹ má ṣe fòyà; ẹ̀yin ní iye lórí ju ọ̀pọ̀ ológoṣẹ́ lọ.
32 “Ẹnikẹ́ni tí ó bá jẹ́wọ́ mi níwájú ènìyàn, òun náà ni èmi yóò jẹ́wọ́ rẹ̀ níwájú Baba mi ní ọ̀run. 33 Ṣùgbọ́n ẹni tí ó bá sẹ́ mí níwájú àwọn ènìyàn, òun náà ni èmi náà yóò sọ wí pé n kò mọ̀ níwájú Baba mi ní ọ̀run.
34 (H)“Ẹ má ṣe rò pé mo mú àlàáfíà wá sí ayé, Èmi kò mú àlàáfíà wá bí kò ṣe idà. 35 Nítorí èmi wá láti ya
“ ‘ọmọkùnrin ní ipa sí baba rẹ̀,
ọmọbìnrin ní ipa sí ìyá rẹ̀,
àti aya ọmọ sí ìyakọ rẹ̀…
36 Ará ilé ènìyàn ni yóò sì máa ṣe ọ̀tá rẹ̀.’
37 (I)“Ẹni tí ó bá fẹ́ baba rẹ̀ tàbí ìyá rẹ̀ jù mí lọ, kò yẹ ní tèmi, ẹni tí ó ba fẹ́ ọmọkùnrin tàbí ọmọbìnrin rẹ̀ jù mí lọ, kò yẹ ní tèmi; 38 Ẹni tí kò bá gbé àgbélébùú rẹ̀ kí ó tẹ̀lé mi kò yẹ ní tèmi. 39 Ẹni tí ó bá wa ẹ̀mí rẹ̀ yóò sọ ọ́ nù, ṣùgbọ́n ẹni tí ó bá sọ ẹ̀mí rẹ̀ nú nítorí tèmi ni yóò rí i.
40 (J)“Ẹni tí ó bá gbà yín, ó gbà mí, ẹni tí ó bá sì gbà mí gba ẹni tí ó rán mi. 41 Ẹni tí ó ba gba wòlíì, nítorí pé ó jẹ́ wòlíì yóò jẹ èrè wòlíì, ẹni tí ó bá sì gba olódodo nítorí ti ó jẹ́ ènìyàn olódodo, yóò jẹ èrè olódodo. 42 Ẹnikẹ́ni tí ó bá fi ago omi tútù fún ọ̀kan nínú àwọn onírẹ̀lẹ̀ wọ̀nyí mu nítorí tí ó jẹ́ ọmọ-ẹ̀yìn mi, lóòótọ́ ni mo wí fún yín, kò ní pàdánù èrè rẹ̀.”
Footnotes
- 10.2 Jakọbu ẹni tí ó jẹ́ aposteli Kristi.
Matthew 10
Evangelical Heritage Version
Jesus Sends Out the Twelve
10 Jesus called his twelve disciples to himself and gave them authority to drive out unclean spirits and to heal every disease and every sickness. 2 These are the names of the twelve apostles: first, Simon (who is called Peter) and his brother Andrew; James the son of Zebedee and his brother John; 3 Philip and Bartholomew; Thomas and Matthew the tax collector; James the son of Alphaeus, and Thaddaeus; 4 Simon the Zealot and Judas Iscariot, who betrayed him.
5 Jesus sent these twelve out and commanded them, “Do not go among the Gentiles, and do not enter any town of the Samaritans. 6 Go instead to the lost sheep of the house of Israel. 7 As you go, preach this message: ‘The kingdom of heaven is near!’ 8 Heal the sick. Raise the dead. Cleanse lepers. Drive out demons. Freely you have received; freely give. 9 Do not take gold, silver, or bronze in your money belts. 10 Do not take a bag for the journey, or two coats, sandals, or a staff, because the worker deserves his support. 11 Whenever you enter a town or village, find out who is worthy and stay there until you leave. 12 As you enter the household, give it your greeting. 13 If the household is worthy, let your peace rest on it. But if it is not worthy, let your peace return to you. 14 If anyone does not receive you or listen to your words, shake the dust off your feet as you leave that house or that town. 15 Amen I tell you: It will be more bearable for the land of Sodom and Gomorrah on the day of judgment than for that town.
16 “Look, I am sending you out as sheep among wolves. So be as shrewd as snakes and as innocent as doves. 17 Be on guard against people. They will hand you over to councils, and they will whip you in their synagogues. 18 You will be brought into the presence of governors and kings for my sake, as a testimony to them and to the Gentiles. 19 Whenever they hand you over, do not be worried about how you will respond or what you will say, because what you say will be given to you in that hour. 20 In fact you will not be the ones speaking, but the Spirit of your Father will be speaking through you.
21 “Brother will hand over his brother to death, and a father will do the same with his child. Children will rise up against parents and have them put to death. 22 You will be hated by all people because of my name, but whoever endures to the end will be saved. 23 And when they persecute you in one town, flee to the next. Amen I tell you: You will not finish going through the cities of Israel before the Son of Man comes.
24 “A disciple is not above his teacher, nor is a servant above his master. 25 It is enough for the disciple to be like his teacher and the servant like his master. If the master of the house was called Beelzebul, how much more the members of his household!
26 “So do not be afraid of them, because there is nothing concealed that will not be revealed, and nothing hidden that will not be made known. 27 What I tell you in the dark, speak in the daylight; and what you hear whispered in your ear, proclaim from the housetops. 28 Do not fear those who kill the body but cannot kill the soul. Rather, fear the one who is able to destroy both soul and body in hell.
29 “Are not two sparrows sold for a small coin?[a] Yet not one of them will fall to the ground without the knowledge and consent of your Father. 30 And even the hairs of your head are all numbered. 31 So do not be afraid. You are worth more than many sparrows.
32 “Everyone who confesses me before others, I will also confess before my Father who is in heaven. 33 But whoever denies me before others, I will also deny before my Father who is in heaven.
34 “Do not think that I came to bring peace to the earth. I did not come to bring peace, but a sword. 35 For I came to turn a man against his father, a daughter against her mother, and a daughter-in-law against her mother-in-law. 36 A man’s enemies will be the members of his own household.[b]
37 “Whoever loves father or mother more than me is not worthy of me, and whoever loves son or daughter more than me is not worthy of me. 38 Whoever does not take up his cross and follow me is not worthy of me. 39 Whoever finds his life will lose it, and whoever loses his life for my sake will find it.
40 “Whoever receives you receives me, and whoever receives me receives him who sent me. 41 Whoever receives a prophet because he is a prophet will receive a prophet’s reward. Whoever receives a righteous man because he is a righteous man will receive a righteous man’s reward. 42 Whoever gives one of these little ones even a cup of cold water to drink because he is my disciple—Amen I tell you—he will never lose his reward.”
Footnotes
- Matthew 10:29 Greek assarion, less than a half hour’s wage
- Matthew 10:36 Micah 7:6
Matthew 10
New International Version
Jesus Sends Out the Twelve(A)(B)(C)(D)(E)
10 Jesus called his twelve disciples to him and gave them authority to drive out impure spirits(F) and to heal every disease and sickness.(G)
2 These are the names of the twelve apostles: first, Simon (who is called Peter) and his brother Andrew; James son of Zebedee, and his brother John; 3 Philip and Bartholomew; Thomas and Matthew the tax collector; James son of Alphaeus, and Thaddaeus; 4 Simon the Zealot and Judas Iscariot, who betrayed him.(H)
5 These twelve Jesus sent out with the following instructions: “Do not go among the Gentiles or enter any town of the Samaritans.(I) 6 Go rather to the lost sheep of Israel.(J) 7 As you go, proclaim this message: ‘The kingdom of heaven(K) has come near.’ 8 Heal the sick, raise the dead, cleanse those who have leprosy,[a] drive out demons. Freely you have received; freely give.
9 “Do not get any gold or silver or copper to take with you in your belts(L)— 10 no bag for the journey or extra shirt or sandals or a staff, for the worker is worth his keep.(M) 11 Whatever town or village you enter, search there for some worthy person and stay at their house until you leave. 12 As you enter the home, give it your greeting.(N) 13 If the home is deserving, let your peace rest on it; if it is not, let your peace return to you. 14 If anyone will not welcome you or listen to your words, leave that home or town and shake the dust off your feet.(O) 15 Truly I tell you, it will be more bearable for Sodom and Gomorrah(P) on the day of judgment(Q) than for that town.(R)
16 “I am sending you out like sheep among wolves.(S) Therefore be as shrewd as snakes and as innocent as doves.(T) 17 Be on your guard; you will be handed over to the local councils(U) and be flogged in the synagogues.(V) 18 On my account you will be brought before governors and kings(W) as witnesses to them and to the Gentiles. 19 But when they arrest you, do not worry about what to say or how to say it.(X) At that time you will be given what to say, 20 for it will not be you speaking, but the Spirit of your Father(Y) speaking through you.
21 “Brother will betray brother to death, and a father his child; children will rebel against their parents(Z) and have them put to death.(AA) 22 You will be hated by everyone because of me,(AB) but the one who stands firm to the end will be saved.(AC) 23 When you are persecuted in one place, flee to another. Truly I tell you, you will not finish going through the towns of Israel before the Son of Man comes.(AD)
24 “The student is not above the teacher, nor a servant above his master.(AE) 25 It is enough for students to be like their teachers, and servants like their masters. If the head of the house has been called Beelzebul,(AF) how much more the members of his household!
26 “So do not be afraid of them, for there is nothing concealed that will not be disclosed, or hidden that will not be made known.(AG) 27 What I tell you in the dark, speak in the daylight; what is whispered in your ear, proclaim from the roofs. 28 Do not be afraid of those who kill the body but cannot kill the soul. Rather, be afraid of the One(AH) who can destroy both soul and body in hell. 29 Are not two sparrows sold for a penny? Yet not one of them will fall to the ground outside your Father’s care.[b] 30 And even the very hairs of your head are all numbered.(AI) 31 So don’t be afraid; you are worth more than many sparrows.(AJ)
32 “Whoever acknowledges me before others,(AK) I will also acknowledge before my Father in heaven. 33 But whoever disowns me before others, I will disown before my Father in heaven.(AL)
34 “Do not suppose that I have come to bring peace to the earth. I did not come to bring peace, but a sword. 35 For I have come to turn
“‘a man against his father,
a daughter against her mother,
a daughter-in-law against her mother-in-law(AM)—
36 a man’s enemies will be the members of his own household.’[c](AN)
37 “Anyone who loves their father or mother more than me is not worthy of me; anyone who loves their son or daughter more than me is not worthy of me.(AO) 38 Whoever does not take up their cross and follow me is not worthy of me.(AP) 39 Whoever finds their life will lose it, and whoever loses their life for my sake will find it.(AQ)
40 “Anyone who welcomes you welcomes me,(AR) and anyone who welcomes me welcomes the one who sent me.(AS) 41 Whoever welcomes a prophet as a prophet will receive a prophet’s reward, and whoever welcomes a righteous person as a righteous person will receive a righteous person’s reward. 42 And if anyone gives even a cup of cold water to one of these little ones who is my disciple, truly I tell you, that person will certainly not lose their reward.”(AT)
Footnotes
- Matthew 10:8 The Greek word traditionally translated leprosy was used for various diseases affecting the skin.
- Matthew 10:29 Or will; or knowledge
- Matthew 10:36 Micah 7:6
Matthew 10
New American Standard Bible
The Twelve Disciples; Instructions for Service
10 Jesus (A)summoned His twelve disciples and gave them authority over unclean spirits, to cast them out, and to (B)heal every disease and every sickness.
2 (C)Now the names of the twelve apostles are these: The first, (D)Simon, who is called Peter, and his brother (E)Andrew; and [a](F)James the son of Zebedee, and his brother [b]John; 3 (G)Philip and [c]Bartholomew; (H)Thomas and (I)Matthew the tax collector; [d](J)James the son of Alphaeus, and (K)Thaddaeus; 4 Simon the [e]Zealot, and (L)Judas Iscariot, the one who also betrayed Him.
5 (M)These twelve Jesus sent out after instructing them, saying, “Do not go on a road [f]to Gentiles, and do not enter a city of (N)Samaritans; 6 but rather go to (O)the lost sheep of the house of Israel. 7 And as you go, [g]preach, saying, ‘(P)The kingdom of heaven has come near.’ 8 Heal the sick, raise the dead, cleanse those with leprosy, cast out demons. Freely you received, freely give. 9 (Q)Do not acquire gold, or silver, or copper for your money belts, 10 or a [h]bag for your journey, or even two [i]tunics, or sandals, or a staff; for (R)the worker is deserving of his [j]support. 11 And whatever city or village you enter, inquire who is worthy in it, and stay [k]at his house until you leave that city. 12 As you enter the [l]house, (S)give it your [m]greeting. 13 If the house is worthy, see that your blessing of peace comes upon it. But if it is not worthy, [n]take back your blessing of peace. 14 And whoever does not receive you nor listen to your words, as you leave that house or city, (T)shake the dust off your feet. 15 Truly I say to you, (U)it will be more tolerable for the land of (V)Sodom and Gomorrah on (W)the day of judgment, than for that city.
A Hard Road Ahead of Them
16 “(X)Behold, I am sending you out as sheep in the midst of wolves; so be as (Y)wary as serpents, and as (Z)innocent as doves. 17 But be on guard against people, for they will hand you over to the (AA)courts and flog you (AB)in their synagogues; 18 and you will even be brought before governors and kings on My account, as a testimony to them and to the Gentiles. 19 (AC)But when they hand you over, (AD)do not worry about how or what you are to say; for what you are to say will be given you in that hour. 20 For (AE)it is not you who are speaking, but it is the Spirit of your Father who is speaking [o]in you.
21 “Now (AF)brother will betray brother to death, and a father his child; and (AG)children will rise up against parents and [p]cause them to be put to death. 22 And (AH)you will be hated by all because of My name, but (AI)it is the one who has endured to the end who will be saved.
23 “But whenever they (AJ)persecute you in [q]one city, flee to the [r]next; for truly I say to you, you will not finish going through the cities of Israel (AK)until the Son of Man comes.
The Meaning of Discipleship
24 “(AL)A [s]disciple is not above his teacher, nor a slave above his master. 25 It is enough for the disciple that he may become like his teacher, and the slave like his master. (AM)If they have called the head of the house [t](AN)Beelzebul, how much more will they insult the members of his household!
26 “So do not (AO)fear them, (AP)for there is nothing concealed that will not be revealed, or hidden that will not be known. 27 (AQ)What I tell you in the darkness, tell in the light; and what you hear whispered in your ear, proclaim (AR)on the housetops. 28 And do not be afraid of those who kill the body but are unable to kill the soul; but rather (AS)fear Him who is able to destroy both soul and body in [u](AT)hell. 29 (AU)Are two sparrows not sold for an [v]assarion? And yet not one of them will fall to the ground apart from your Father. 30 But (AV)even the hairs of your head are all counted. 31 So do not fear; (AW)you are more valuable than a great number of sparrows.
32 “Therefore, (AX)everyone who [w]confesses Me before people, I will also confess [x]him before My Father who is in heaven. 33 But (AY)whoever denies Me before people, I will also deny him before My Father who is in heaven.
34 “(AZ)Do not think that I came to [y]bring peace on the earth; I did not come to [z]bring peace, but a sword. 35 For I came to (BA)turn a man against his father, and a daughter against her mother, and a daughter-in-law against her mother-in-law; 36 and (BB)a person’s enemies will be the members of his household.
37 “(BC)The one who loves father or mother more than Me is not worthy of Me; and the one who loves son or daughter more than Me is not worthy of Me. 38 And (BD)the one who does not take his cross and follow after Me is not worthy of Me. 39 (BE)The one who has found his [aa]life will lose it, and the one who has lost his [ab]life on My account will find it.
The Reward for Service
40 “(BF)The one who [ac]receives you [ad]receives Me, and (BG)the one who [ae]receives Me [af]receives Him who sent Me. 41 (BH)The one who [ag]receives a prophet in the name of a prophet shall receive a prophet’s reward; and the one who [ah]receives a righteous person in the name of a righteous person shall receive a righteous person’s reward. 42 And (BI)whoever gives one of these [ai]little ones just a cup of cold water to drink in the name of a disciple, truly I say to you, he shall by no means lose his reward.”
Footnotes
- Matthew 10:2 Or Jacob
- Matthew 10:2 Gr Joannes, for Heb Johanan
- Matthew 10:3 I.e., son of Talmai (Aram)
- Matthew 10:3 Or Jacob
- Matthew 10:4 Or Cananaean
- Matthew 10:5 Lit of
- Matthew 10:7 Or proclaim
- Matthew 10:10 Or knapsack; or beggar’s bag
- Matthew 10:10 A long shirt worn next to the skin
- Matthew 10:10 Lit nourishment
- Matthew 10:11 Lit there until
- Matthew 10:12 Or household
- Matthew 10:12 I.e., the familiar Heb blessing, “Peace be to this house!”
- Matthew 10:13 Lit your peace is to return to you
- Matthew 10:20 Or by you
- Matthew 10:21 Lit put them to death
- Matthew 10:23 Lit this
- Matthew 10:23 Lit other
- Matthew 10:24 Or student
- Matthew 10:25 Two early mss Beezebul; meaning uncertain, perhaps lord prince, referring to Satan
- Matthew 10:28 Gr Gehenna
- Matthew 10:29 A Roman copper coin, worth about 1/16 of a laborer’s daily wage
- Matthew 10:32 Lit will confess in Me
- Matthew 10:32 Lit in him
- Matthew 10:34 Lit cast
- Matthew 10:34 Lit cast
- Matthew 10:39 Or soul
- Matthew 10:39 Or soul
- Matthew 10:40 Or welcomes
- Matthew 10:40 Or welcomes
- Matthew 10:40 Or welcomes
- Matthew 10:40 Or welcomes
- Matthew 10:41 Or welcomes
- Matthew 10:41 Or welcomes
- Matthew 10:42 Possibly someone of low social standing
Matthew 10
King James Version
10 And when he had called unto him his twelve disciples, he gave them power against unclean spirits, to cast them out, and to heal all manner of sickness and all manner of disease.
2 Now the names of the twelve apostles are these; The first, Simon, who is called Peter, and Andrew his brother; James the son of Zebedee, and John his brother;
3 Philip, and Bartholomew; Thomas, and Matthew the publican; James the son of Alphaeus, and Lebbaeus, whose surname was Thaddaeus;
4 Simon the Canaanite, and Judas Iscariot, who also betrayed him.
5 These twelve Jesus sent forth, and commanded them, saying, Go not into the way of the Gentiles, and into any city of the Samaritans enter ye not:
6 But go rather to the lost sheep of the house of Israel.
7 And as ye go, preach, saying, The kingdom of heaven is at hand.
8 Heal the sick, cleanse the lepers, raise the dead, cast out devils: freely ye have received, freely give.
9 Provide neither gold, nor silver, nor brass in your purses,
10 Nor scrip for your journey, neither two coats, neither shoes, nor yet staves: for the workman is worthy of his meat.
11 And into whatsoever city or town ye shall enter, enquire who in it is worthy; and there abide till ye go thence.
12 And when ye come into an house, salute it.
13 And if the house be worthy, let your peace come upon it: but if it be not worthy, let your peace return to you.
14 And whosoever shall not receive you, nor hear your words, when ye depart out of that house or city, shake off the dust of your feet.
15 Verily I say unto you, It shall be more tolerable for the land of Sodom and Gomorrha in the day of judgment, than for that city.
16 Behold, I send you forth as sheep in the midst of wolves: be ye therefore wise as serpents, and harmless as doves.
17 But beware of men: for they will deliver you up to the councils, and they will scourge you in their synagogues;
18 And ye shall be brought before governors and kings for my sake, for a testimony against them and the Gentiles.
19 But when they deliver you up, take no thought how or what ye shall speak: for it shall be given you in that same hour what ye shall speak.
20 For it is not ye that speak, but the Spirit of your Father which speaketh in you.
21 And the brother shall deliver up the brother to death, and the father the child: and the children shall rise up against their parents, and cause them to be put to death.
22 And ye shall be hated of all men for my name's sake: but he that endureth to the end shall be saved.
23 But when they persecute you in this city, flee ye into another: for verily I say unto you, Ye shall not have gone over the cities of Israel, till the Son of man be come.
24 The disciple is not above his master, nor the servant above his lord.
25 It is enough for the disciple that he be as his master, and the servant as his lord. If they have called the master of the house Beelzebub, how much more shall they call them of his household?
26 Fear them not therefore: for there is nothing covered, that shall not be revealed; and hid, that shall not be known.
27 What I tell you in darkness, that speak ye in light: and what ye hear in the ear, that preach ye upon the housetops.
28 And fear not them which kill the body, but are not able to kill the soul: but rather fear him which is able to destroy both soul and body in hell.
29 Are not two sparrows sold for a farthing? and one of them shall not fall on the ground without your Father.
30 But the very hairs of your head are all numbered.
31 Fear ye not therefore, ye are of more value than many sparrows.
32 Whosoever therefore shall confess me before men, him will I confess also before my Father which is in heaven.
33 But whosoever shall deny me before men, him will I also deny before my Father which is in heaven.
34 Think not that I am come to send peace on earth: I came not to send peace, but a sword.
35 For I am come to set a man at variance against his father, and the daughter against her mother, and the daughter in law against her mother in law.
36 And a man's foes shall be they of his own household.
37 He that loveth father or mother more than me is not worthy of me: and he that loveth son or daughter more than me is not worthy of me.
38 And he that taketh not his cross, and followeth after me, is not worthy of me.
39 He that findeth his life shall lose it: and he that loseth his life for my sake shall find it.
40 He that receiveth you receiveth me, and he that receiveth me receiveth him that sent me.
41 He that receiveth a prophet in the name of a prophet shall receive a prophet's reward; and he that receiveth a righteous man in the name of a righteous man shall receive a righteous man's reward.
42 And whosoever shall give to drink unto one of these little ones a cup of cold water only in the name of a disciple, verily I say unto you, he shall in no wise lose his reward.
Copyright: Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní Ẹ̀tọ́ àdàkọ © 2009, 2017 by Biblica, Inc. A lò ó nípa ìgbàyọ̀ǹda láti ọwọ́ Bíbílíkà Inc. Ààbò lórí ẹ̀tọ́ àdàkọ yìí múlẹ̀ jákèjádò àgbáyé. Yoruba Contemporary Bible Copyright © 2009, 2017 by Biblica, Inc.® Used by permission of Biblica, Inc.® All rights reserved worldwide.
The Holy Bible, Evangelical Heritage Version®, EHV®, © 2019 Wartburg Project, Inc. All rights reserved.
Holy Bible, New International Version®, NIV® Copyright ©1973, 1978, 1984, 2011 by Biblica, Inc.® Used by permission. All rights reserved worldwide.
NIV Reverse Interlinear Bible: English to Hebrew and English to Greek. Copyright © 2019 by Zondervan.
New American Standard Bible®, Copyright © 1960, 1971, 1977, 1995, 2020 by The Lockman Foundation. All rights reserved.

