Add parallel Print Page Options

Ìdáhùn Ọlọ́run sí ìráhùn wòlíì Habakuku

(A)Èmi yóò dúró lórí ibusọ́ mi láti máa wòye
    Èmi yóò sì gbé ara mi ka orí alóre
Èmi yóò si ṣọ́ láti gbọ́ ohun tí yóò sọ fún mi
    àti èsì ti èmi yóò fún ẹ̀sùn yìí nígbà tó bá ń bá mi wí.

Ìdáhùn Olúwa

Nígbà náà ni Olúwa dáhùn pé:

“Kọ ìṣípayá náà sílẹ̀
    kí o sì fi hàn ketekete lórí wàláà
    kí ẹni tí ń kà á, lè máa sáré.
(B)Nítorí ìṣípayá náà jẹ́ tí ìgbà kan tí a múra sílẹ̀ dè;
    yóò máa yára sí ìgbẹ̀yìn
    kí yóò sìsọ èké.
Bí o tilẹ̀ lọ́ra, dúró dè é;
    nítorí, dájúdájú, yóò dé, kí yóò sí pẹ́.”

(C)“Kíyèsi, ọkàn rẹ tí ó gbéga;
    Ìfẹ́ rẹ̀ kò dúró ṣinṣin nínú rẹ̀,
    ṣùgbọ́n olódodo yóò wa nípa ìgbàgbọ́ rẹ̀.
Bẹ́ẹ̀ ni pẹ̀lú, nítorí tí ọtí wáìnì ni ẹ̀tàn,
    agbéraga ènìyàn òun, kò sì ní sinmi
ẹni tí ó sọ ìwọra rẹ di gbígbòòrò bí isà òkú,
    ó sì dàbí ikú, a kò sì le tẹ́ ẹ lọ́rùn,
ó kó gbogbo orílẹ̀-èdè jọ sí ọ̀dọ̀
    ó sì gba gbogbo ènìyàn jọ sí ọ̀dọ̀ rẹ̀.

“Gbogbo àwọn wọ̀nyí kì yóò máa pa òwe sí i tí wọn yóò sì máa kọ orin òwe sí i wí pé,

“ ‘Ègbé ni fún ẹni tí ń mu ohun tí kì í ṣe tirẹ̀ pọ̀ sí i!
    Tí ó sì sọ ara rẹ̀ di ọlọ́rọ̀ nípasẹ̀ ìlọ́nilọ́wọ́gbà!
    Eléyìí yóò ha ti pẹ́ tó?’
Ǹjẹ́ ẹni ti ó yọ ọ́ lẹ́nu, kí yóò ha dìde ní òjijì?
    Àti àwọn tí ó wàhálà rẹ kì yóò jí, kí wọn ó sì dẹ́rùbà ọ́?
    Nígbà náà ni ìwọ yóò wa dí ìkógun fún wọn.
Nítorí ìwọ ti kó orílẹ̀-èdè púpọ̀,
    àwọn ènìyàn tókù yóò sì kó ọ
nítorí ìwọ tí ta ẹ̀jẹ̀ ènìyàn sílẹ̀; nítorí ẹ̀jẹ̀
    Ìwọ tí pa ilẹ̀ àti ìlú ńlá run
    àti gbogbo ènìyàn to ń gbé inú rẹ̀.

“Ègbé ni fún ẹni tí ń jẹ èrè ìjẹkújẹ sí ilé rẹ̀,
    tí o sí gbé ìtẹ́ rẹ̀ lórí ibi gíga,
    kí a ba le gbà á sílẹ̀ kúrò lọ́wọ́ ibi!
10 Ìwọ ti gbìmọ̀ ìtìjú sí ilé rẹ
    nípa kíké ènìyàn púpọ̀ kúrò;
    ìwọ sì ti pàdánù ẹ̀mí rẹ
11 Nítorí tí òkúta yóò kígbe jáde láti inú ògiri wá,
    àti ìtí igi láti inú igi rírẹ́ wá yóò sì dá a lóhùn.

12 “Ègbé ni fún ẹni tí ó fi ẹ̀jẹ̀ kọ́ ìlú,
    tí o sì fi àìṣedéédéé tẹ ìlú ńlá dó?
13 Ọlọ́run àwọn ọmọ-ogun kò ha ti ṣètò rẹ̀ pé
    làálàá àwọn ènìyàn jẹ́ epo fún iná
    kí àwọn orílẹ̀-èdè náà sì máa ṣe wàhálà fún asán?
14 Nítorí tí ayé yóò kún fún ìmọ̀ ògo Olúwa,
    bí omi ti bo Òkun.

15 “Ègbé ni fún ẹni tí ó fi ohun mímu fún aládùúgbò rẹ̀,
    tí ó sì fi ọtí-lílé rẹ̀ fún un, tí o sì jẹ́ kó mu àmupara,
    kí ìwọ kí ó ba lè wo ìhòhò wọn”
16 Ìtìjú yóò bò ọ́ dípò ògo, ìwọ náà mu pẹ̀lú
    kí ìhòhò rẹ kí ó lè hàn,
ago ọwọ́ ọ̀tún Olúwa, yóò yípadà sí ọ,
    ìtìjú yóò sì bo ògo rẹ.
17 Nítorí ìwà ipá tí ó tí hù sí Lebanoni yóò bò ọ́,
    àti ìparun àwọn ẹranko yóò dẹ́rùbà ọ́ mọ́lẹ̀
Nítorí ìwọ tí ta ẹ̀jẹ̀ ènìyàn sílẹ̀;
    ìwọ tí pa ilẹ̀ náà àti ìlú ńlá run àti gbogbo àwọn tí ń gbé inú rẹ̀.

18 “Èrè kí ni òrìṣà ni, tí oníṣọ̀nà rẹ̀ fi gbẹ́ ẹ,
    ère dídá ti ń kọ ni èké?
Nítorí ti ẹni ti ó dá a gbẹ́kẹ̀ rẹ̀ lé ohun tí ó fúnrarẹ̀ dá;
    ó sì mọ ère tí kò le fọhùn.
19 Ègbé ni fún ẹni ti ń sọ fún igi pé, ‘di alààyè?’
    Fún òkúta tí kò lè fọhùn pé, ‘Dìde’
Ǹjẹ́ òun lè tọ́ ni sí ọ̀nà?
    Wúrà àti fàdákà ni a fi bò ó yíká;
    kò sì sí èémí kan nínú rẹ.”

20 (D)Ṣùgbọ́n Olúwa wà nínú tẹmpili mímọ́ rẹ̀;
    Ẹ jẹ́ kí gbogbo ayé parọ́rọ́ níwájú rẹ.

The Just Shall Live by Faith

I will (A)stand my watch
And set myself on the rampart,
And watch to see what He will say to me,
And what I will answer when I am corrected.

The Just Live by Faith

Then the Lord answered me and said:

(B)“Write the vision
And make it plain on tablets,
That he may run who reads it.
For (C)the vision is yet for an appointed time;
But at the end it will speak, and it will (D)not lie.
Though it tarries, (E)wait for it;
Because it will (F)surely come,
It will not tarry.

“Behold the proud,
His soul is not upright in him;
But the (G)just shall live by his faith.

Woe to the Wicked

“Indeed, because he transgresses by wine,
He is a proud man,
And he does not stay at home.
Because he (H)enlarges his desire as [a]hell,
And he is like death, and cannot be satisfied,
He gathers to himself all nations
And heaps up for himself all peoples.

“Will not all these (I)take up a proverb against him,
And a taunting riddle against him, and say,
‘Woe to him who increases
What is not his—how long?
And to him who loads himself with [b]many pledges’?
Will not [c]your creditors rise up suddenly?
Will they not awaken who oppress you?
And you will become their booty.
(J)Because you have plundered many nations,
All the remnant of the people shall plunder you,
Because of men’s [d]blood
And the violence of the land and the city,
And of all who dwell in it.

“Woe to him who covets evil gain for his house,
That he may (K)set his nest on high,
That he may be delivered from the [e]power of disaster!
10 You give shameful counsel to your house,
Cutting off many peoples,
And sin against your soul.
11 For the stone will cry out from the wall,
And the beam from the timbers will answer it.

12 “Woe to him who builds a town with bloodshed,
Who establishes a city by iniquity!
13 Behold, is it not of the Lord of hosts
That the peoples labor [f]to feed the fire,
And nations weary themselves in vain?
14 For the earth will be filled
With the knowledge of the glory of the Lord,
As the waters cover the sea.

15 “Woe to him who gives drink to his neighbor,
[g]Pressing him to your (L)bottle,
Even to make him drunk,
That you may look on [h]his nakedness!
16 You are filled with shame instead of glory.
You also—drink!
And [i]be exposed as uncircumcised!
The cup of the Lord’s right hand will be turned against you,
And utter shame will be on your glory.
17 For the violence done to Lebanon will cover you,
And the plunder of beasts which made them afraid,
Because of men’s blood
And the violence of the land and the city,
And of all who dwell in it.

18 “What profit is the image, that its maker should carve it,
The molded image, a teacher of lies,
That the maker of its mold should trust in it,
To make mute idols?
19 Woe to him who says to wood, ‘Awake!’
To silent stone, ‘Arise! It shall teach!’
Behold, it is overlaid with gold and silver,
Yet in it there is no breath at all.

20 “But(M) the Lord is in His holy temple.
Let all the earth keep silence before Him.”

Footnotes

  1. Habakkuk 2:5 Or Sheol
  2. Habakkuk 2:6 Syr., Vg. thick clay
  3. Habakkuk 2:7 Lit. those who bite you
  4. Habakkuk 2:8 Or bloodshed
  5. Habakkuk 2:9 Lit. hand of evil
  6. Habakkuk 2:13 Lit. for what satisfies fire, for what is of no lasting value
  7. Habakkuk 2:15 Lit. Attaching or Joining
  8. Habakkuk 2:15 Lit. their
  9. Habakkuk 2:16 DSS, LXX reel!; Syr., Vg. fall fast asleep!

Mobarog ako sa akong bantayanan ug magpahimutang ako diha sa mga tore; ako motan-aw aron pagsuta kon unsay iyang isulti kanako, ug unsa nga tubag ang akong ihatag niining mga reklamo.

Ang Tubag sa Ginoo

Ug ang Ginoo mitubag, “Isulat ang gipadayag himoa kini klaro sa papan nga bato, aron ang mensahero modagan uban niini. Kay ang gipadayag magpaabut sa gitakda nga panahon; nagsulti kini mahitungod sa katapusan ug dili kini mapamatud-an nga bakak. Bisan tuod madugay kini, paabuta kini; muabut gayud kini ug dili malangay. Lantawa ang mga kaaway mapagarbohon; ang iyang tinguha dli tarong-apan ang matarong nga tawo mabuhi sa pagkamatinud-anon. Tinuod, ang bino moluib kaniya; siya aroganti ug dili makapahulay. Tungod kay siya hakog sama sa lubnganan, ug sama sa kamatayon dili gayud matagbaw, iyang gitipon diha niya ang kanasuran ug gihimo niyang binihag ang tanang katawhan. Dili ba ang tanan magatamay man niya uban ang bugal-bugal ug panghimaraot. Nagaingon, ‘Alaot sila nga nagatigom sa kinawat nga mga butang ug naghimo niyang sapian pinaagi sa pangilkil. Hangtud kanus-a man sila magpadayon.’

“Dili ba unya ang inyong tig-pautang mobangon? Dili ba sila unya momata ug mopakurog ninyo? Ug unya sila mahimo kaninyo nga inyong makaon. Kay inyong gikurakot ang inyong kanasuran, ang mga tawo nga nahabilin mokarakot sab nimo. Kay ikaw imong gipaagas ang dugo sa tawo; imong giguba ang yuta ug ang mga siyudad ug ang tanan niini.”

“Alaot siya nga nagtukod ug balay gikan sa dili maayong kinitaan, nagpahiluna sa iyang saag sa itaas aron lang makalingkawas sa pagkupot sa kalag-lagan! 10 Imong giplanohan ang pagkaguba sa mga tawo, nagpaka-ulaw sa imong balay ug nagpildi sa imong kinabuhi. 11 Ang mga bato sa paril mosinggit, ug ang mga sagbayan sa gitrabahong kahoy mopalanug niini.

12 “Alaot siya nga nagtukod sa siyudad diha sa gipaagas nga dugo, ug nagaugmad sa lungsod sa inhustisya. 13 Dili ba nga ang Makagagahum nga Dios mao may Naglatid niini. Nga ang paghago sa tawo sugnod lang alang sa kalayo, nga ang kanasuran naningkamot alang sa wala?” 14 Kay ang kalibotan mapuno sa kahibalo sa himaya sa Ginoo ingon nga ang tubig nagtakob sa kadagatan.

15 “Alaot siya nga naghatag ug mainom sa iyang silingan, gibubo sa sudlanang panit sa bino hangtud nga kini mahubog, haron siya makatan-aw sa hubo niining lawas. 16 Mapuno ikaw sa kaulawan inay sa himaya. Karon na usab ang imong turno! Inom ug ang imong pagkahubo ipadayag. Ang kupa gikan sa tuong kamot sa Ginoo, miabot sa palibot nimo, ug ang kaulawan motakub sa imong himaya. 17 Ang kapungot nga imong gibuhat sa Lebanon makapahingangha kanimo, ug ang kadaut sa mga hayupan makapahadlok kanimo. Kay gipaagasan mo ug dugo sa tawo; kay gilumpag mo ang kayutaan ug mga siyudad ug ang tanan niini.

18 “Unsa may kapuslanan sa idolo nga gikulit sa magkukulit? O imahen nga nagtudlo ug bakak? Kay siya nga naghimo niini misalig sa iyang hinimo; naghimo siya ug idolo nga dili makasulti. 19 Alaot siya nga moingo sa kahoy, dali ug pagpakabuhi, o sa walay kinabuhi nga bato, pagmata! Makahatag ba kini ug paggiya? Giputos kini bulawan ug plata; wala kini gininhawa. 20 Ang Ginoo anaa sa iyang balaang templo. Itugot nga ang tibuok kalibutan magpakahilum sa iyang atubangan.”

I will stand at my watch(A)
    and station myself on the ramparts;(B)
I will look to see what he will say(C) to me,
    and what answer I am to give to this complaint.[a](D)

The Lord’s Answer

Then the Lord replied:

“Write(E) down the revelation
    and make it plain on tablets
    so that a herald[b] may run with it.
For the revelation awaits an appointed time;(F)
    it speaks of the end(G)
    and will not prove false.
Though it linger, wait(H) for it;
    it[c] will certainly come
    and will not delay.(I)

“See, the enemy is puffed up;
    his desires are not upright—
    but the righteous person(J) will live by his faithfulness[d](K)
indeed, wine(L) betrays him;
    he is arrogant(M) and never at rest.
Because he is as greedy as the grave
    and like death is never satisfied,(N)
he gathers to himself all the nations
    and takes captive(O) all the peoples.

“Will not all of them taunt(P) him with ridicule and scorn, saying,

“‘Woe to him who piles up stolen goods
    and makes himself wealthy by extortion!(Q)
    How long must this go on?’
Will not your creditors suddenly arise?
    Will they not wake up and make you tremble?
    Then you will become their prey.(R)
Because you have plundered many nations,
    the peoples who are left will plunder you.(S)
For you have shed human blood;(T)
    you have destroyed lands and cities and everyone in them.(U)

“Woe to him who builds(V) his house by unjust gain,(W)
    setting his nest(X) on high
    to escape the clutches of ruin!
10 You have plotted the ruin(Y) of many peoples,
    shaming(Z) your own house and forfeiting your life.
11 The stones(AA) of the wall will cry out,
    and the beams of the woodwork will echo it.

12 “Woe to him who builds a city with bloodshed(AB)
    and establishes a town by injustice!
13 Has not the Lord Almighty determined
    that the people’s labor is only fuel for the fire,(AC)
    that the nations exhaust themselves for nothing?(AD)
14 For the earth will be filled with the knowledge of the glory(AE) of the Lord
    as the waters cover the sea.(AF)

15 “Woe to him who gives drink(AG) to his neighbors,
    pouring it from the wineskin till they are drunk,
    so that he can gaze on their naked bodies!
16 You will be filled with shame(AH) instead of glory.(AI)
    Now it is your turn! Drink(AJ) and let your nakedness be exposed[e]!(AK)
The cup(AL) from the Lord’s right hand is coming around to you,
    and disgrace will cover your glory.
17 The violence(AM) you have done to Lebanon will overwhelm you,
    and your destruction of animals will terrify you.(AN)
For you have shed human blood;(AO)
    you have destroyed lands and cities and everyone in them.

18 “Of what value(AP) is an idol(AQ) carved by a craftsman?
    Or an image(AR) that teaches lies?
For the one who makes it trusts in his own creation;
    he makes idols that cannot speak.(AS)
19 Woe to him who says to wood, ‘Come to life!’
    Or to lifeless stone, ‘Wake up!’(AT)
Can it give guidance?
    It is covered with gold and silver;(AU)
    there is no breath in it.”(AV)

20 The Lord is in his holy temple;(AW)
    let all the earth be silent(AX) before him.

Footnotes

  1. Habakkuk 2:1 Or and what to answer when I am rebuked
  2. Habakkuk 2:2 Or so that whoever reads it
  3. Habakkuk 2:3 Or Though he linger, wait for him; / he
  4. Habakkuk 2:4 Or faith
  5. Habakkuk 2:16 Masoretic Text; Dead Sea Scrolls, Aquila, Vulgate and Syriac (see also Septuagint) and stagger