Add parallel Print Page Options

(A)Ẹ dákẹ́ jẹ́ẹ́ níwájú Olúwa Olódùmarè,
    nítorí tí ọjọ́ Olúwa kù sí dẹ̀dẹ̀.
Olúwa ti pèsè ẹbọ kan sílẹ̀,
    ó sì ti ya àwọn alápèjẹ rẹ̀ sí mímọ́.

Read full chapter

13 (A)Ẹ̀ dákẹ́, gbogbo ẹran-ara níwájú Olúwa: nítorí a jí i láti ibùgbé mímọ́ rẹ̀ wá.”

Read full chapter