Add parallel Print Page Options

12 Èyí ni òfin mi, pé kí ẹ̀yin kí ó fẹ́ràn ara yín, gẹ́gẹ́ bí mo ti fẹ́ràn yín.

Read full chapter

12 My command is this: Love each other as I have loved you.(A)

Read full chapter

17 Nǹkan wọ̀nyí ni mo pàṣẹ fún yín pé, kí ẹ̀yin kí ó fẹ́ràn ara yín.

Read full chapter

17 This is my command: Love each other.(A)

Read full chapter

23 (A)Èyí sì ni òfin rẹ̀, pé kí àwa gba orúkọ Jesu Kristi Ọmọ rẹ̀ gbọ́, kí a sì fẹ́ràn ara wá gẹ́gẹ́ bí ó tí fi òfin fún wa.

Read full chapter

23 And this is his command: to believe(A) in the name of his Son, Jesus Christ,(B) and to love one another as he commanded us.(C)

Read full chapter

(A)Ǹjẹ́ nísinsin yìí, mo bẹ̀ ọ́, obìnrin ọlọ́lá, kì í ṣe bí ẹni pé èmi ń kọ̀wé òfin tuntun kan sí ọ, bí kò ṣe èyí ti àwa tí ní ní àtètèkọ́ṣe, pé kí àwa fẹ́ràn ara wa.

Read full chapter

And now, dear lady, I am not writing you a new command but one we have had from the beginning.(A) I ask that we love one another.

Read full chapter

18 (A)“ ‘Ìwọ kò gbọdọ̀ gbẹ̀san: má sì ṣe bínú sí èyíkéyìí nínú àwọn ènìyàn rẹ. Ṣùgbọ́n, kí ìwọ kí ó fẹ́ ẹnìkejì rẹ bí ara rẹ, Èmi ni Olúwa.

Read full chapter

18 “‘Do not seek revenge(A) or bear a grudge(B) against anyone among your people,(C) but love your neighbor(D) as yourself.(E) I am the Lord.

Read full chapter

Ṣùgbọ́n nípa ìfẹ́ ará, a kò ní láti tún kọ̀wé sí i yín, ìdí ni pé, Ọlọ́run pàápàá ń kọ́ yín láti fẹ́ràn ara yín.

Read full chapter

Now about your love for one another(A) we do not need to write to you,(B) for you yourselves have been taught by God(C) to love each other.(D)

Read full chapter

22 Níwọ́n bí ẹ̀yin ti wẹ ọkàn yin mọ́ nípa ìgbọ́ràn yín sí òtítọ́ sí ìfẹ́ ará ti kò ní ẹ̀tàn, ẹ fẹ́ ọmọnìkejì yín gidigidi láti ọkàn wá.

Read full chapter

22 Now that you have purified(A) yourselves by obeying(B) the truth so that you have sincere love for each other, love one another deeply,(C) from the heart.[a]

Read full chapter

Footnotes

  1. 1 Peter 1:22 Some early manuscripts from a pure heart

Ìparí àwọn ọ̀rọ̀ ìyànjú náà

13 Kí ìfẹ́ ará kí o wà títí.

Read full chapter

Concluding Exhortations

13 Keep on loving one another as brothers and sisters.(A)

Read full chapter

(A)ẹ sì máa rìn ní ìfẹ́, gẹ́gẹ́ bí Kristi pẹ̀lú ti fẹ́ wa, tí ó sì fi ara rẹ̀ fún wa ní ọrẹ àti ẹbọ fún Ọlọ́run fún òórùn dídùn.

Read full chapter

and walk in the way of love, just as Christ loved us(A) and gave himself up for us(B) as a fragrant offering and sacrifice to God.(C)

Read full chapter

10 (A)Nínú èyí ni ìfẹ́ wà, kì í ṣe pé àwa fẹ́ Ọlọ́run, ṣùgbọ́n òun fẹ́ wá, ó sì rán Ọmọ rẹ̀ láti jẹ́ ètùtù fún ẹ̀ṣẹ̀ wa.

Read full chapter

10 This is love: not that we loved God, but that he loved us(A) and sent his Son as an atoning sacrifice for our sins.(B)

Read full chapter