Font Size
Johanu 6:29
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
Johanu 6:29
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
29 (A)Jesu dáhùn, ó sì wí fún wọn pé, “Èyí ni iṣẹ́ Ọlọ́run pé, kí ẹ̀yin gba ẹni tí ó rán an gbọ́.”
Read full chapter
Johanu 13:34
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
Johanu 13:34
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
34 (A)“Òfin tuntun kan ni mo fi fún yín, kí ẹ̀yin kí ó fẹ́ ọmọnìkejì yín; gẹ́gẹ́ bí èmi ti fẹ́ràn yín, kí ẹ̀yin kí ó sì fẹ́ràn ọmọnìkejì yín.
Read full chapter
Johanu 15:17
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
Johanu 15:17
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
17 Nǹkan wọ̀nyí ni mo pàṣẹ fún yín pé, kí ẹ̀yin kí ó fẹ́ràn ara yín.
Read full chapter
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn (BYO)
Copyright: Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní Ẹ̀tọ́ àdàkọ © 2009, 2017 by Biblica, Inc. A lò ó nípa ìgbàyọ̀ǹda láti ọwọ́ Bíbílíkà Inc. Ààbò lórí ẹ̀tọ́ àdàkọ yìí múlẹ̀ jákèjádò àgbáyé. Yoruba Contemporary Bible Copyright © 2009, 2017 by Biblica, Inc.® Used by permission of Biblica, Inc.® All rights reserved worldwide.