出埃及記 33
Chinese Contemporary Bible (Traditional)
33 耶和華對摩西說:「我曾向亞伯拉罕、以撒和雅各起誓,應許把迦南賜給他們的後代。現在你和你從埃及領出來的百姓要動身去那裡。 2 我必差遣天使走在你們前面,趕出當地的迦南人、亞摩利人、赫人、比利洗人、希未人和耶布斯人, 3 帶你們進入那奶蜜之鄉。但我不會跟你們一起去,免得我在途中就把你們滅絕了,因為你們是頑固不化的百姓。」
4 百姓聽見這壞消息,都非常哀傷,不再佩戴飾物了。 5 耶和華對摩西說:「你去向以色列百姓宣佈,『你們這些頑固不化的人,我就是跟你們在一起待一刻,都恐怕會滅絕你們。現在你們要摘下自己身上的飾物,我再決定怎樣處置你們。』」 6 因此,以色列百姓從何烈山開始就不再佩戴飾物了。
耶和華的會幕
7 摩西通常把帳幕支搭在營外離百姓較遠的地方,摩西稱帳幕為會幕。凡求問耶和華的,都會去那裡。 8 當摩西離營去會幕的時候,百姓就都一同起來,各人站在自己的帳篷門口目送摩西走進會幕。 9 摩西進入會幕後,便有雲柱降下來,停在會幕門口,耶和華就跟摩西說話。 10 每當百姓看見這景象,他們都站在自己的帳篷門口敬拜耶和華。 11 在會幕內,耶和華跟摩西面對面說話,好像兩個朋友談話一樣。然後,摩西返回營中,但他的年輕助手、嫩的兒子約書亞仍然留在會幕。
耶和華的榮耀
12 摩西對耶和華說:「你吩咐我帶領這些百姓,卻沒有告訴我你將要派誰與我同去,只說,『我憑名字認識你,你在我面前蒙了恩。』 13 我若已經在你面前蒙恩,就求你把你的道路指示我,好讓我認識你,繼續在你面前蒙恩。求你顧念這些百姓是你的子民。」 14 耶和華回答他說:「我必親自與你同去,使你平安穩妥。」 15 摩西說:「你若不與我們同去,就不要讓我們離開這裡。 16 你若不與我們同去,誰會知道我和你的子民在你面前蒙了恩呢?豈不是因為你的同在才使我們不同於地上其他民族嗎?」
17 耶和華回答說:「我答應你的請求,因為你在我面前蒙了恩,我憑名字認識你。」 18 摩西說:「求你向我彰顯你的榮耀。」 19 耶和華說:「我必叫你看見我一切的美善,我要在你面前宣告我的名——耶和華,我要恩待誰就恩待誰,我要憐憫誰就憐憫誰。 20 但你不能看我的臉,因為凡看見的,都不能存活。 21 你要站在我旁邊的磐石上, 22 我的榮耀經過你面前的時候,我會先把你安置在石縫裡,用我的手遮掩你,直到我從你面前走過。 23 然後我會收回我的手,你就可以看見我的背,但看不到我的臉。」
Eksodu 33
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
33 Olúwa sọ fún Mose pé, “Fi ìhín yìí sílẹ̀, ìwọ àti àwọn ènìyàn tí o mú gòkè láti Ejibiti wá, kí ẹ sì gòkè lọ sí ilẹ̀ tí èmi ti pinnu ní ìbúra fún Abrahamu, Isaaki àti Jakọbu wí pé, ‘Èmi yóò fi fún irú-ọmọ rẹ.’ 2 Èmi yóò rán angẹli ṣáájú yín, èmi yóò sì lé àwọn Kenaani, àwọn ará Amori, àwọn ará Hiti, àwọn ará Peresi, àwọn ará Hifi àti àwọn ará Jebusi jáde. 3 (A)Ẹ gòkè lọ sí ilẹ̀ tí ó ń sàn fún wàrà àti oyin. Ṣùgbọ́n èmi kò ní lọ pẹ̀lú yín, nítorí ènìyàn ọlọ́rùn líle ni ẹ̀yin, kí èmi má ba à run yín ní ọ̀nà.”
4 Nígbà tí àwọn ènìyàn náà gbọ́ ọ̀rọ̀ ìparun wọ̀nyí, wọ́n bẹ̀rẹ̀ sì ní kùn, ẹnìkankan kò sì le è wọ ohun ọ̀ṣọ́ rẹ̀. 5 Nítorí Olúwa ti wí fún Mose pé, “Sọ fún àwọn ọmọ Israẹli pé, ‘Ènìyàn ọlọ́rùn líle ní ẹ̀yin, bí èmi bá lè wá sí àárín yín ni ìṣẹ́jú kan, èmi lè pa yín run. Ní ṣinṣin yìí, bọ́ ohun ọ̀ṣọ́ rẹ kúrò, èmi yóò sì gbèrò ohun tí èmi yóò ṣe pẹ̀lú rẹ.’ ” 6 Bẹ́ẹ̀ àwọn ọmọ Israẹli bọ́ ohun ọ̀ṣọ́ wọn kúrò lára wọn ní òkè Horebu.
Àgọ́ àjọ
7 Mose máa ń gbé àgọ́ náà, ó sì pa á sí ìta ibùdó, ó jìnnà díẹ̀ sí ibùdó, ó pè é ni “Àgọ́ àjọ.” Ẹnikẹ́ni tí ó bá ń béèrè Olúwa yóò lọ sí ibi àgọ́ àjọ náà ní ìta ibùdó. 8 Nígbàkúgbà tí Mose bá jáde lọ sí ibi àgọ́, gbogbo ènìyàn á dìde, wọ́n á sì dúró sí ẹnu-ọ̀nà àgọ́ wọn, wọn yóò máa wo Mose títí yóò fi wọ inú àgọ́ náà. 9 Bí Mose ṣe wọ inú àgọ́ náà, ọ̀wọ́n àwọsánmọ̀ yóò sọ̀kalẹ̀, yóò sì dúró sí ẹnu ọnà, nígbà tí Olúwa ń sọ̀rọ̀ pẹ̀lú Mose. 10 Nígbàkígbà tí àwọn ènìyàn bá rí i ti ọ̀wọ́n àwọsánmọ̀ bá dúró ní ẹnu-ọ̀nà àgọ́, gbogbo wọn yóò dìde wọn yóò sì sìn, olúkúlùkù ní ẹnu-ọ̀nà àgọ́ rẹ̀. 11 (B)Olúwa máa ń bá Mose sọ̀rọ̀ lójúkojú, gẹ́gẹ́ bí i pé ènìyàn ń bá ọ̀rẹ́ rẹ̀ sọ̀rọ̀. Nígbà náà ni Mose yóò tún padà lọ sí ibùdó, ṣùgbọ́n ọ̀dọ́mọkùnrin Joṣua ìránṣẹ́ rẹ̀ ọmọ Nuni kò fi àgọ́ sílẹ̀.
Mose àti ògo Olúwa
12 Mose sọ fún Olúwa pé, “Ìwọ ti ń sọ fún mi, ‘Darí àwọn ènìyàn wọ̀nyí,’ ṣùgbọ́n ìwọ kò jẹ́ kí ń mọ ẹni tí ìwọ yóò rán pẹ̀lú mi. Ìwọ ti wí pé, ‘Èmi mọ̀ ọ́n nípa orúkọ, ìwọ sì ti rí ojúrere mi pẹ̀lú.’ 13 Bí ìwọ bá ní inú dídùn pẹ̀lú mi, kọ́ mi ní ọ̀nà rẹ, kí èmi kí ó lè mọ̀ ọ́n, kí n sì le máa wá ojúrere rẹ pẹ̀lú. Rántí wí pé orílẹ̀-èdè yìí ènìyàn rẹ ni.”
14 Olúwa dáhùn wí pé, “Ojú mi yóò máa bá ọ lọ, èmi yóò sì fún ọ ní ìsinmi.”
15 Nígbà náà ni, Mose wí fún un pé, “Bí ojú rẹ kò bá bá wa lọ, má ṣe rán wa gòkè láti ìhín lọ. 16 Báwo ni ẹnikẹ́ni yóò ṣe mọ̀ pé inú rẹ dùn pẹ̀lú mi àti pẹ̀lú àwọn ènìyàn rẹ àyàfi ti o bá bá wa lọ? Kí ni yóò lè yà mí àti àwọn ènìyàn rẹ kúrò lára gbogbo ènìyàn tí ó wà ní ayé?”
17 Olúwa sì sọ fún Mose pé, “Èmi yóò ṣe ohun gbogbo tí ìwọ ti béèrè, nítorí inú mi dún sí o, èmi sì mọ̀ ọ́n nípa orúkọ rẹ̀.”
18 Mose sì wí pé “Nísinsin yìí fi ògo rẹ hàn mí.”
19 (C)Olúwa sì wí pé, “Èmi yóò sì mú gbogbo ìre mí kọjá níwájú rẹ, Èmi yóò sì pòkìkí orúkọ Olúwa níwájú rẹ. Èmi yóò ṣàánú fún ẹni tí èmi yóò ṣàánú fún, èmi yóò sì ṣoore-ọ̀fẹ́ fún ẹni tí èmi yóò ṣoore-ọ̀fẹ́ fún. 20 Ṣùgbọ́n,” ó wí pé, “Ìwọ kò le è rí ojú mi, nítorí kò sí ènìyàn kan tí ń rí mi, tí ó lè yè.”
21 Olúwa sì wí pé, “Ibìkan wà lẹ́gbẹ̀ẹ́ ọ̀dọ̀ mi, níbi tí o ti lè dúró lórí àpáta. 22 Nígbà tí ògo mi bá kọjá, èmi yóò gbé ọ sínú pàlàpálá àpáta, èmi yóò sì bò ọ́ pẹ̀lú ọwọ́ mi títí èmi yóò fi rékọjá. 23 Nígbà tí èmi yóò mú ọwọ́ mi kúrò, ìwọ yóò sì rí ẹ̀yìn mi; ṣùgbọ́n ojú mi ni o kò ní rí.”
Exodus 33
Christian Standard Bible Anglicised
The Tent Outside the Camp
33 The Lord spoke to Moses: ‘Go up from here, you and the people you brought up from the land of Egypt, to the land I promised to Abraham, Isaac, and Jacob, saying: I will give it to your offspring.(A) 2 I will send an angel ahead of you and will drive out the Canaanites, Amorites, Hethites, Perizzites,[a] Hivites, and Jebusites.(B) 3 Go up to a land flowing with milk and honey. But I will not go up with you because you are a stiff-necked people; otherwise, I might destroy you on the way.’(C) 4 When the people heard this bad news, they mourned and didn’t put on their jewellery.(D)
5 For the Lord said to Moses, ‘Tell the Israelites: You are a stiff-necked people. If I went up with you for a single moment, I would destroy you. Now take off your jewellery, and I will decide what to do with you.’ 6 So the Israelites remained stripped of their jewellery from Mount Horeb onward.
7 Now Moses took a tent and pitched it outside the camp, at a distance from the camp; he called it the tent of meeting. Anyone who wanted to consult the Lord would go to the tent of meeting that was outside the camp.(E) 8 Whenever Moses went out to the tent, all the people would stand up, each one at the door of his tent, and they would watch Moses until he entered the tent. 9 When Moses entered the tent, the pillar of cloud would come down and remain at the entrance to the tent, and the Lord would speak with Moses.(F) 10 As all the people saw the pillar of cloud remaining at the entrance to the tent, they would stand up, then bow in worship, each one at the door of his tent. 11 The Lord would speak with Moses face to face, just as a man speaks with his friend, then Moses would return to the camp. His assistant, the young man Joshua son of Nun, would not leave the inside of the tent.(G)
The Lord’s Glory
12 Moses said to the Lord, ‘Look, you have told me, “Lead this people up,” but you have not let me know whom you will send with me. You said, “I know you by name,(H) and you have also found favour with me.” 13 Now if I have indeed found favour with you, please teach me your ways,(I) and I will know you, so that I may find favour with you. Now consider that this nation is your people.’(J)
14 And he replied, ‘My presence will go with you, and I will give you rest.’(K)
15 ‘If your presence does not go,’ Moses responded to him, ‘don’t make us go up from here. 16 How will it be known that I and your people have found favour with you unless you go with us? I and your people will be distinguished by this from all the other people on the face of the earth.’(L)
17 The Lord answered Moses, ‘I will do this very thing you have asked, for you have found favour with me, and I know you by name.’
18 Then Moses said, ‘Please, let me see your glory.’(M)
19 He said, ‘I will cause all my goodness to pass in front of you, and I will proclaim the name “the Lord” before you. I will be gracious to whom I will be gracious, and I will have compassion on whom I will have compassion.’(N) 20 But he added, ‘You cannot see my face, for humans cannot see(O) me and live.’ 21 The Lord said, ‘Here is a place near me. You are to stand on the rock, 22 and when my glory passes by, I will put you in the crevice of the rock and cover you with my hand until I have passed by.(P) 23 Then I will take my hand away, and you will see my back, but my face will not be seen.’
Footnotes
- 33:2 Sam, LXX add Girgashites
Exodus 33
New International Version
33 Then the Lord said to Moses, “Leave this place, you and the people you brought up out of Egypt, and go up to the land I promised on oath(A) to Abraham, Isaac and Jacob, saying, ‘I will give it to your descendants.’(B) 2 I will send an angel(C) before you and drive out the Canaanites, Amorites, Hittites, Perizzites, Hivites and Jebusites.(D) 3 Go up to the land flowing with milk and honey.(E) But I will not go with you, because you are a stiff-necked(F) people and I might destroy(G) you on the way.”
4 When the people heard these distressing words, they began to mourn(H) and no one put on any ornaments. 5 For the Lord had said to Moses, “Tell the Israelites, ‘You are a stiff-necked people.(I) If I were to go with you even for a moment, I might destroy(J) you. Now take off your ornaments and I will decide what to do with you.’” 6 So the Israelites stripped off their ornaments at Mount Horeb.(K)
The Tent of Meeting
7 Now Moses used to take a tent and pitch it outside the camp some distance away, calling it the “tent of meeting.”(L) Anyone inquiring(M) of the Lord would go to the tent of meeting outside the camp. 8 And whenever Moses went out to the tent, all the people rose and stood at the entrances to their tents,(N) watching Moses until he entered the tent. 9 As Moses went into the tent, the pillar of cloud(O) would come down and stay at the entrance, while the Lord spoke(P) with Moses. 10 Whenever the people saw the pillar of cloud standing at the entrance to the tent, they all stood and worshiped, each at the entrance to their tent.(Q) 11 The Lord would speak to Moses face to face,(R) as one speaks to a friend. Then Moses would return to the camp, but his young aide Joshua(S) son of Nun did not leave the tent.
Moses and the Glory of the Lord
12 Moses said to the Lord, “You have been telling me, ‘Lead these people,’(T) but you have not let me know whom you will send with me. You have said, ‘I know you by name(U) and you have found favor(V) with me.’ 13 If you are pleased with me, teach me your ways(W) so I may know you and continue to find favor with you. Remember that this nation is your people.”(X)
14 The Lord replied, “My Presence(Y) will go with you, and I will give you rest.”(Z)
15 Then Moses said to him, “If your Presence(AA) does not go with us, do not send us up from here. 16 How will anyone know that you are pleased with me and with your people unless you go with us?(AB) What else will distinguish me and your people from all the other people on the face of the earth?”(AC)
17 And the Lord said to Moses, “I will do the very thing you have asked,(AD) because I am pleased with you and I know you by name.”(AE)
18 Then Moses said, “Now show me your glory.”(AF)
19 And the Lord said, “I will cause all my goodness to pass(AG) in front of you, and I will proclaim my name,(AH) the Lord, in your presence. I will have mercy on whom I will have mercy, and I will have compassion on whom I will have compassion.(AI) 20 But,” he said, “you cannot see my face, for no one may see(AJ) me and live.”
21 Then the Lord said, “There is a place near me where you may stand on a rock. 22 When my glory passes by, I will put you in a cleft in the rock(AK) and cover you with my hand(AL) until I have passed by. 23 Then I will remove my hand and you will see my back; but my face must not be seen.”
Éxodo 33
Reina Valera Contemporánea
Dios promete estar presente
33 El Señor le dijo a Moisés:
«Anda, vete ya de aquí, con el pueblo que sacaste de Egipto, y llévalos a la tierra que prometí darles a Abrahán,(A) Isaac(B) y Jacob,(C) cuando dije: “Se la daré a tu descendencia.” 2 Yo enviaré un ángel para que vaya delante de ti, y expulsaré a los cananeos y a los amorreos, a los hititas y a los ferezeos, y a los jivitas y jebuseos. 3 Esa tierra fluye leche y miel. Pero yo no iré contigo, porque eres un pueblo de dura cerviz y bien podría yo consumirte en el camino.»
4 Cuando el pueblo se enteró de esta mala noticia, se vistieron de luto y ninguno se puso sus joyas. 5 Y es que el Señor le había dicho a Moisés: «Diles a los hijos de Israel: “Ustedes son un pueblo de dura cerviz. Si acaso los acompañara, en cualquier momento podría acabar con ustedes.” Así que, quítense ahora sus joyas, para que yo sepa lo que tengo que hacer.» 6 Y así, desde que partieron del monte Horeb los hijos de Israel se despojaron de sus joyas.
7 Moisés tomó el tabernáculo y lo plantó lejos, fuera del campamento, y lo llamó «Tabernáculo de Reunión». Todo el que buscaba al Señor iba hasta el tabernáculo de reunión, el cual estaba fuera del campamento. 8 Cada vez que Moisés iba al tabernáculo, todo el pueblo se levantaba y se quedaba de pie, a la entrada de su tienda, y seguían a Moisés con la mirada, hasta que él entraba en el tabernáculo. 9 Al entrar Moisés en el tabernáculo, la columna de nube descendía y se quedaba a la entrada del tabernáculo, y entonces el Señor hablaba con Moisés. 10 Y cuando todo el pueblo veía la columna de nube a la entrada del tabernáculo, se levantaba cada uno e iba a la entrada de su tienda para adorar. 11 Y el Señor hablaba con Moisés cara a cara, como habla cualquiera con su compañero. Después Moisés volvía al campamento, pero el joven Josué hijo de Nun, su servidor, nunca se apartaba del tabernáculo.
12 Moisés le dijo entonces al Señor:
«Mira, tú me has dicho: “Llévate de aquí a este pueblo”; pero no me has dicho a quién vas a enviar conmigo. Lejos de eso, insistes: “Yo te conozco. Sé quién eres, y te has ganado mi favor.” 13 Ahora bien, si en verdad me he ganado tu favor, te ruego que me hagas saber qué planes tienes. Así sabré si en verdad me he ganado tu favor. ¡Toma en cuenta que esta gente es tu pueblo!»
14 Y el Señor le dijo:
«Mi presencia irá contigo, y te haré descansar.»
15 Pero Moisés respondió:
«Si tú no vas a venir conmigo, no nos saques de aquí. 16 ¿Cómo vamos a saber tu pueblo y yo que en verdad me he ganado tu favor? ¡Lo sabremos sólo si vienes con nosotros, y sólo si tu pueblo y yo somos apartados de todos los pueblos que hay sobre la faz de la tierra!»
17 El Señor le dijo a Moisés:
«Tan cierto es que te has ganado mi favor, y que te conozco por nombre, que voy a hacer lo que me has pedido.»
18 Entonces Moisés dijo:
«Te ruego que me muestres tu gloria.»
19 Y el Señor le respondió:
«Voy a hacer que todo mi bien pase delante de ti, y delante de ti voy a proclamar mi nombre, que es EL SEÑOR. Porque soy misericordioso con quien quiero ser misericordioso, y soy clemente con quien quiero ser clemente.»(D)
20 El señor dijo también:
«Mi rostro no podrás verlo, porque nadie puede ver mi rostro y seguir viviendo.»
21 Y añadió:
«¡Mira! Aquí en la roca, junto a mí, hay un lugar. Quédate allí; 22 y cuando pase mi gloria, yo te pondré en una hendidura de la roca y te cubriré con mi mano mientras paso. 23 Después de eso apartaré mi mano, y podrás ver mis espaldas, pero no mi rostro.»
Copyright: Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní Ẹ̀tọ́ àdàkọ © 2009, 2017 by Biblica, Inc. A lò ó nípa ìgbàyọ̀ǹda láti ọwọ́ Bíbílíkà Inc. Ààbò lórí ẹ̀tọ́ àdàkọ yìí múlẹ̀ jákèjádò àgbáyé. Yoruba Contemporary Bible Copyright © 2009, 2017 by Biblica, Inc.® Used by permission of Biblica, Inc.® All rights reserved worldwide.
Copyright © 2024 by Holman Bible Publishers.
Holy Bible, New International Version®, NIV® Copyright ©1973, 1978, 1984, 2011 by Biblica, Inc.® Used by permission. All rights reserved worldwide.
NIV Reverse Interlinear Bible: English to Hebrew and English to Greek. Copyright © 2019 by Zondervan.
Copyright © 2009, 2011 by Sociedades Bíblicas Unidas