Print Page Options
Previous Prev Day Next DayNext

Verse of the Day

A daily inspirational and encouraging Bible verse.
Duration: 366 days
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn (BYO)
Version
Luku 2:28-32

28 Nígbà náà ni Simeoni gbé e ní apá rẹ̀, ó fi ìbùkún fún Ọlọ́run, ó ní:

29 “Olúwa Olódùmarè, nígbà yìí ni ó tó jọ̀wọ́ ọmọ ọ̀dọ̀ rẹ lọ́wọ́ lọ,
    ní Àlàáfíà, gẹ́gẹ́ bí ọ̀rọ̀ rẹ:
30 (A)Nítorí tí ojú mi ti rí ìgbàlà rẹ ná,
31     Tí ìwọ ti pèsè sílẹ̀ níwájú ènìyàn gbogbo;
32 (B)ìmọ́lẹ̀ láti mọ́ sí àwọn aláìkọlà,
    àti ògo Israẹli ènìyàn rẹ̀.”

Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn (BYO)

Copyright: Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní Ẹ̀tọ́ àdàkọ © 2009, 2017 by Biblica, Inc. A lò ó nípa ìgbàyọ̀ǹda láti ọwọ́ Bíbílíkà Inc. Ààbò lórí ẹ̀tọ́ àdàkọ yìí múlẹ̀ jákèjádò àgbáyé. Yoruba Contemporary Bible Copyright © 2009, 2017 by Biblica, Inc.® Used by permission of Biblica, Inc.® All rights reserved worldwide.