Add parallel Print Page Options

Ọ̀rọ̀ Olúwa tí ó tọ Sefaniah ọmọ Kuṣi, ọmọ Gedaliah, ọmọ Amariah, ọmọ Hesekiah, ní ìgbà Josiah ọmọ Amoni ọba Juda.

Ìkìlọ̀ fún ìparun tí ń bọ̀

“Èmi yóò mú gbogbo nǹkan kúrò
    lórí ilẹ̀ náà pátápátá,”
    ni Olúwa wí.
“Èmi yóò mú ènìyàn àti ẹranko
    kúrò; èmi yóò mú àwọn ẹyẹ ojú
    ọ̀run kúrò àti ẹja inú Òkun, àti
ohun ìdìgbòlù pẹ̀lú àwọn
    ènìyàn búburú; èmi yóò ké ènìyàn kúrò lórí ilẹ̀ ayé,”
    ni Olúwa wí.

Ìlòdì sí Juda

“Èmi yóò na ọwọ́ mi sórí Juda
    àti sórí gbogbo àwọn ènìyàn tí ń gbé ní Jerusalẹmu.
Èmi yóò sì ké kúrò níhìn-ín-yìí ìyókù àwọn Baali, àti orúkọ àwọn abọ̀rìṣà
    pẹ̀lú àwọn àlùfáà abọ̀rìṣà,
àti àwọn tí ń foríbalẹ̀ lórí òrùlé,
    àwọn tí ń sin ogun ọ̀run,
àwọn tó ń foríbalẹ̀, tí wọ́n sì ń fi Olúwa búra,
    tí wọ́n sì ń fi Moleki búra.
Àwọn tí ó yípadà kúrò lọ́dọ̀ Olúwa;
    Àti àwọn tí kò tí wá Olúwa, bẹ́ẹ̀ ni wọn kò sì béèrè rẹ̀.”

(A)Ẹ dákẹ́ jẹ́ẹ́ níwájú Olúwa Olódùmarè,
    nítorí tí ọjọ́ Olúwa kù sí dẹ̀dẹ̀.
Olúwa ti pèsè ẹbọ kan sílẹ̀,
    ó sì ti ya àwọn alápèjẹ rẹ̀ sí mímọ́.

“Ní ọjọ́ ẹbọ Olúwa,
    Èmi yóò bẹ àwọn olórí wò, àti àwọn
    ọmọ ọba ọkùnrin,
pẹ̀lú gbogbo
    àwọn tí ó wọ àjèjì aṣọ.
Ní ọjọ́ náà, èmi yóò fi ìyà jẹ
    gbogbo àwọn tí ó yẹra láti rìn lórí ìloro ẹnu-ọ̀nà,
tí wọ́n sì kún tẹmpili àwọn ọlọ́run wọn
    pẹ̀lú ìwà ipá àti ẹ̀tàn.

10 “Ní ọjọ́ náà,” ni Olúwa wí,
    “Ohùn ẹkún yóò wà láti ìhà Ibodè ẹja,
    híhu láti ìhà kejì wá àti
    ariwo ńlá láti òkè kékeré wá.
11 Ẹ hu, ẹ̀yin tí ń gbé ní (Maktẹsi) agbègbè ọjà,
    gbogbo àwọn oníṣòwò rẹ̀ ni a ó mú kúrò,
    gbogbo àwọn ẹni tí ó ń ra fàdákà ni a ó sì parun.
12 Ní àkókò wọ̀n-ọn-nì, èmi yóò wá Jerusalẹmu kiri pẹ̀lú fìtílà,
    èmi ó sì fi ìyà jẹ àwọn tí kò ní ìtẹ́lọ́rùn,
    tí wọn sì dàbí àwọn ènìyàn tí ó sinmi sínú gẹ̀dẹ̀gẹ́dẹ̀ wọn,
àwọn tí wọn sì ń wí ní ọkàn wọn pé, ‘Olúwa kì yóò ṣe nǹkan kan
    tí ó jẹ́ rere tàbí tí ó jẹ́ búburú.’
13 Nítorí náà, ọrọ̀ wọn yóò di ìkógun,
    àti ilé wọn yóò sì run.
Àwọn yóò sì kọ́ ilé pẹ̀lú, ṣùgbọ́n
    wọn kì yóò gbé nínú ilé náà,
wọn yóò gbin ọgbà àjàrà,
    ṣùgbọ́n wọn kì yóò mu ọtí
wáìnì láti inú rẹ̀.”

Ọjọ́ ńlá Olúwa

14 “Ọjọ́ ńlá Olúwa kù sí dẹ̀dẹ̀,
    ó kù sí dẹ̀dẹ̀ ó sì ń yára bọ̀
kánkán. Ẹ tẹ́tí sílẹ̀, ohùn ẹkún
    àwọn alágbára ní ọjọ́ Olúwa yóò korò púpọ̀,
15 Ọjọ́ náà yóò jẹ́ ọjọ́ ìbínú,
    ọjọ́ ìrora àti ìpọ́njú,
ọjọ́ òfò àti idà ọjọ́ ìdahoro
    ọjọ́ òkùnkùn àti ìtẹ̀ba,
    ọjọ́ kurukuru àti òkùnkùn biribiri,
16 ọjọ́ ìpè àti ìpè ogun
    sí àwọn ìlú olódi
    àti sí àwọn ilé ìṣọ́ gíga.

17 “Èmi yóò sì mú ìpọ́njú wá sórí
    ènìyàn, wọn yóò sì máa rìn gẹ́gẹ́ bí afọ́jú,
    nítorí àwọn ti dẹ́ṣẹ̀ sí Olúwa.
Ẹ̀jẹ̀ wọn ni a ó sì tú jáde bí eruku
    àti ẹran-ara wọn bí ìgbẹ́.
18 Bẹ́ẹ̀ ni fàdákà tàbí wúrà wọn
    kì yóò sì le gbà wọ́n là
    ní ọjọ́ ìbínú Olúwa.”

Ṣùgbọ́n gbogbo ayé ni a ó fi iná
    ìjowú rẹ̀ parun,
nítorí òun yóò fi ìyára fi òpin sí
    gbogbo àwọn tí ń gbé ní ilẹ̀ ayé.

The word of the Lord which came unto Zephaniah the son of Cushi, the son of Gedaliah, the son of Amariah, the son of Hizkiah, in the days of Josiah the son of Amon, king of Judah.

I will utterly consume all things from off the land, saith the Lord.

I will consume man and beast; I will consume the fowls of the heaven, and the fishes of the sea, and the stumbling blocks with the wicked: and I will cut off man from off the land, saith the Lord.

I will also stretch out mine hand upon Judah, and upon all the inhabitants of Jerusalem; and I will cut off the remnant of Baal from this place, and the name of the Chemarims with the priests;

And them that worship the host of heaven upon the housetops; and them that worship and that swear by the Lord, and that swear by Malcham;

And them that are turned back from the Lord; and those that have not sought the Lord, nor enquired for him.

Hold thy peace at the presence of the Lord God: for the day of the Lord is at hand: for the Lord hath prepared a sacrifice, he hath bid his guests.

And it shall come to pass in the day of the Lord's sacrifice, that I will punish the princes, and the king's children, and all such as are clothed with strange apparel.

In the same day also will I punish all those that leap on the threshold, which fill their masters' houses with violence and deceit.

10 And it shall come to pass in that day, saith the Lord, that there shall be the noise of a cry from the fish gate, and an howling from the second, and a great crashing from the hills.

11 Howl, ye inhabitants of Maktesh, for all the merchant people are cut down; all they that bear silver are cut off.

12 And it shall come to pass at that time, that I will search Jerusalem with candles, and punish the men that are settled on their lees: that say in their heart, The Lord will not do good, neither will he do evil.

13 Therefore their goods shall become a booty, and their houses a desolation: they shall also build houses, but not inhabit them; and they shall plant vineyards, but not drink the wine thereof.

14 The great day of the Lord is near, it is near, and hasteth greatly, even the voice of the day of the Lord: the mighty man shall cry there bitterly.

15 That day is a day of wrath, a day of trouble and distress, a day of wasteness and desolation, a day of darkness and gloominess, a day of clouds and thick darkness,

16 A day of the trumpet and alarm against the fenced cities, and against the high towers.

17 And I will bring distress upon men, that they shall walk like blind men, because they have sinned against the Lord: and their blood shall be poured out as dust, and their flesh as the dung.

18 Neither their silver nor their gold shall be able to deliver them in the day of the Lord's wrath; but the whole land shall be devoured by the fire of his jealousy: for he shall make even a speedy riddance of all them that dwell in the land.

Ang pulong sa Ginoo nga miabot kang Zepahnia nga anak ni Cushi, ang anak ni Gedalia, ang anak ni Amaria, ang anak ni Hezekia, sa panahon sa paghari ni Josia, anak ni Amon hari sa Juda:

Paghukom sa tibuok kalibutan sa adlaw sa Ginoo

“Akong silhigon pahilayo ang tanang mga butang gikan sa nawong sa kalibutan,” nagaingon ang Ginoo. “Akong silhigon pahilayo ang tawo ug ang kahayupan akong silhigon ang mga langam sa kalangitan ug ang mga isda sa kadagatan—ang mga idolo nga maoy hinungdan nga ang mga dautan manga pandol. Kong ako nang gun-ubon ang katawhan sa dagway sa kalibutan,” nagaingon ang Ginoo.

“Ituyhad ko ang akong mga kamot batok sa Juda ug batok sa nga nagpuyo sa Jerusalem. Akong gun-ubon ang matag-usa nga nahabilin sa nagsimba ni Baal niining dapita. Ang mga ngalan sa makidiyos-diyos nga kaparian— Sila nga nagyukbo diha sa mga atop nga nagsimba sa panon sa kabituonan, sila nga nakyukbo ug nagsaad sa Ginoo ug nagasaad usab kang Molek. [a] Sila nga mitalikod sa pagsunod sa Ginoo ug wala magapangita sa Ginoo ug magapangutana kaniya.

“Pagpakahilom kamo sa atubanga sa Makakagahum nga Ginoo, kay ang adlaw sa Ginoo haduol na. Ang Ginoo nagaandam ug mga halad; gibalaan niya ang iyang gidapit. Sa adlaw unya sa sakripisyo sa Ginoo, akong silotan ang mga opisyales ug ang mga anak sa hari ug ang tanang nga binistihan sa langyaw nga sapot. Niadto unyang adlawa akong silotan kadtong milikay sa pagtunob sa ganghaan, nga nagapuno sa templo sa ilang mga dios sa kadautan ug pagpamlimbong.

10 “Niadto unyang adlawa,” nagaingon ang Ginoo, “may tuaw didto sa Ganghaang Isda, nagminatay gikan sa unang kuarter, ug ang dahunog sa grabing pagka-igo gikan sa kabukiran. 11 Pagminatay, kamo nga nagpuyo sa distrito sa mga tindahan, ang tanan ninyong mga negosyanti wagtangon. Ang tanan nga nagpatigayon ug plata pagagun-obon.

12 “Niadto unyang taknaa akong susihon ang Jerusalem uban sa mga lampara ug silotan ko kadtong wala magpakabana, nga nahisama lamang sa bino nga lawog na, nga naghunahuna nga ang Ginoo wala gayoy buhaton maayo man o dautan. 13 Ang ilang bahandi makurakot, ilang kabalayan pagagub-on. Bisag maghimo silag balay dili sila makapuyo niin; bisag magtanom silag kaparasan, dili sila makainom sa bino niini.”

Ang Makalilisang nga Adlaw sa Pagsilot

14 Ang dako nga adlaw sa Ginoo haduol-duol ug muabot sa madali Ang hilak sa adlaw sa Ginoo mapait; ang gamhanang manggugubat missinggit sa singgit alang sa gubat. 15 Kana nga adlaw mao ang adlaw sa kapungot ang adlaw sa kasakit ug paghigwaos, adlaw sa kasamok ug pagkalumpag, adlaw sa kangitngit ug kaguol, adlaw sa mga panganod ug kangitngit. 16 Adlaw sa trumpeta ug singgit sa gubat batok sa kinutaang mga siyudad ug batok sa mga masigkakilid nga tore.

17 “Akong dadon ang tumang kasakit sa tanang katawhan nga magduhiraw sila sama kanila nga mga buta, tungod kay nakasala sila sa Ginoo. Ang ilang duha ipaagas sama sa mga abo ug ang sulod sa ilang ginhawaan sama sa tae. 18 Wala sa plata o sa bulawan ang makaluwas kanila gikan sa adlaw sa kapungot sa Ginoo. Sa kalayo sa iyang pagka-abubhuan, ang tibuok kalibutan pagalamyon, kay siya magahimo ug hinanali nga katapusan sa tanang nagpuyo sa kalibutan.”

Footnotes

  1. 1:5 Molek: sa Hebreo, Malcam, nga mao pa ang lain nga ngalan ni Molec.

The word of the Lord that came to Zephaniah son of Cushi, the son of Gedaliah, the son of Amariah, the son of Hezekiah, during the reign of Josiah(A) son of Amon(B) king of Judah:

Judgment on the Whole Earth in the Day of the Lord

“I will sweep away everything
    from the face of the earth,”(C)
declares the Lord.
“I will sweep away both man and beast;(D)
    I will sweep away the birds in the sky(E)
    and the fish in the sea—
    and the idols that cause the wicked to stumble.”[a]

“When I destroy all mankind
    on the face of the earth,”(F)
declares the Lord,(G)
“I will stretch out my hand(H) against Judah
    and against all who live in Jerusalem.
I will destroy every remnant of Baal worship in this place,(I)
    the very names of the idolatrous priests(J)
those who bow down on the roofs
    to worship the starry host,(K)
those who bow down and swear by the Lord
    and who also swear by Molek,[b](L)
those who turn back from following(M) the Lord
    and neither seek(N) the Lord nor inquire(O) of him.”

Be silent(P) before the Sovereign Lord,
    for the day of the Lord(Q) is near.
The Lord has prepared a sacrifice;(R)
    he has consecrated those he has invited.

“On the day of the Lord’s sacrifice
    I will punish(S) the officials
    and the king’s sons(T)
and all those clad
    in foreign clothes.
On that day I will punish
    all who avoid stepping on the threshold,[c](U)
who fill the temple of their gods
    with violence and deceit.(V)

10 “On that day,(W)
    declares the Lord,
“a cry will go up from the Fish Gate,(X)
    wailing(Y) from the New Quarter,
    and a loud crash from the hills.
11 Wail,(Z) you who live in the market district[d];
    all your merchants will be wiped out,
    all who trade with[e] silver will be destroyed.(AA)
12 At that time I will search Jerusalem with lamps
    and punish those who are complacent,(AB)
    who are like wine left on its dregs,(AC)
who think, ‘The Lord will do nothing,(AD)
    either good or bad.’(AE)
13 Their wealth will be plundered,(AF)
    their houses demolished.
Though they build houses,
    they will not live in them;
though they plant vineyards,
    they will not drink the wine.”(AG)

14 The great day of the Lord(AH) is near(AI)
    near and coming quickly.
The cry on the day of the Lord is bitter;
    the Mighty Warrior shouts his battle cry.
15 That day will be a day of wrath—
    a day of distress and anguish,
        a day of trouble and ruin,
    a day of darkness(AJ) and gloom,
        a day of clouds and blackness(AK)
16     a day of trumpet and battle cry(AL)
against the fortified cities
    and against the corner towers.(AM)

17 “I will bring such distress(AN) on all people
    that they will grope about like those who are blind,(AO)
    because they have sinned against the Lord.
Their blood will be poured out(AP) like dust
    and their entrails like dung.(AQ)
18 Neither their silver nor their gold
    will be able to save them
    on the day of the Lord’s wrath.”(AR)

In the fire of his jealousy(AS)
    the whole earth will be consumed,(AT)
for he will make a sudden end
    of all who live on the earth.(AU)

Footnotes

  1. Zephaniah 1:3 The meaning of the Hebrew for this line is uncertain.
  2. Zephaniah 1:5 Hebrew Malkam
  3. Zephaniah 1:9 See 1 Samuel 5:5.
  4. Zephaniah 1:11 Or the Mortar
  5. Zephaniah 1:11 Or in