Saamu 3
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
Saamu ti Dafidi. Nígbà ti ó sá fún ọmọ rẹ̀ Absalomu.
3 Olúwa, báwo ni àwọn ọ̀tá mi ṣe pọ̀ tó báyìí!
Báwo ni àwọn ti ó dìde sí mi ṣe pọ̀ tó!
2 Ọ̀pọ̀lọpọ̀ ni ó ń sọ ní ti tèmi, pé
“Ọlọ́run kò nígbà á là.” Sela.
3 Ṣùgbọ́n ìwọ ni asà yí mi ká, Olúwa;
ìwọ fi ògo fún mi, ìwọ sì gbé orí mi sókè.
4 Olúwa ni mo kígbe sókè sí,
ó sì dá mi lóhùn láti orí òkè mímọ́ rẹ̀ wá. Sela.
5 Èmi dùbúlẹ̀, mo sì sùn;
mo sì tún padà jí, nítorí Olúwa ni ó ń gbé mi ró.
6 Èmi kì yóò bẹ̀rù ẹgbẹgbẹ̀rún ènìyàn
tí wọ́n rọ̀gbà yí mi ká.
7 Dìde, Olúwa!
Gbà mí, Ọlọ́run mi!
Lu gbogbo àwọn ọ̀tá mi ní àgbọ̀n;
kí o sì ká eyín àwọn ènìyàn búburú.
8 Láti ọ̀dọ̀ Olúwa ni ìgbàlà ti wá.
Kí ìbùkún rẹ wà lórí àwọn ènìyàn rẹ. Sela.
Psalm 3
New King James Version
The Lord Helps His Troubled People
A Psalm of David (A)when he fled from Absalom his son.
3 Lord, how they have increased who trouble me!
Many are they who rise up against me.
2 Many are they who say of me,
“There is no help for him in God.” Selah
3 But You, O Lord, are (B)a shield [a]for me,
My glory and (C)the One who lifts up my head.
4 I cried to the Lord with my voice,
And (D)He heard me from His (E)holy hill. Selah
5 (F)I lay down and slept;
I awoke, for the Lord sustained me.
6 (G)I will not be afraid of ten thousands of people
Who have set themselves against me all around.
7 Arise, O Lord;
Save me, O my God!
(H)For You have struck all my enemies on the cheekbone;
You have broken the teeth of the ungodly.
8 (I)Salvation belongs to the Lord.
Your blessing is upon Your people. Selah
Footnotes
- Psalm 3:3 Lit. around
Psalm 3
English Standard Version
Save Me, O My God
A Psalm of David, (A)when he fled from Absalom his son.
3 O Lord, (B)how many are my foes!
Many are (C)rising against me;
2 many are saying of my soul,
(D)“There is no salvation for him in God.” Selah[a]
3 But you, O Lord, are (E)a shield (F)about me,
my glory, and (G)the lifter of my head.
4 I (H)cried aloud to the Lord,
and he (I)answered me from his (J)holy hill. Selah
5 I (K)lay down and slept;
I woke again, for the Lord sustained me.
6 I (L)will not be afraid of many thousands of people
who have (M)set themselves against me all around.
7 (N)Arise, O Lord!
Save me, O my God!
For you (O)strike all my enemies on the cheek;
you (P)break the teeth of the wicked.
8 (Q)Salvation belongs to the Lord;
your blessing be on your people! Selah
Footnotes
- Psalm 3:2 The meaning of the Hebrew word Selah, used frequently in the Psalms, is uncertain. It may be a musical or liturgical direction
Псалми 3
Библия, нов превод от оригиналните езици (с неканоничните книги)
Утринна молитва на преследвания праведник
3 (A)Псалом на Давид, когато бягаше от сина си Авесалом.
2 [a] Господи, колко са многобройни враговете ми!
Мнозина въстават против мене.
3 Мнозина казват за мене:
„За него няма спасение от Бога.“
4 (B)Но Ти, Господи, си щит за мене,
моя слава, и Ти изправяш главата ми.
5 Призовавам Господа
и Той ми отговаря от святата Си планина.
6 (C)Лягам, спя
и ставам, защото Господ ме закриля.
7 Няма да се уплаша от десетки хиляди хора,
които отвред са се опълчили против мене.
8 (D)Стани, Господи! Спаси ме, Боже мой!
Защото Ти удряш по лицето всички мои врагове,
трошиш зъбите на нечестивите.
9 (E)Спасението е от Господа.
Твоето благословение да дойде върху народа Ти.
Psalm 3
New International Version
Psalm 3[a]
A psalm of David. When he fled from his son Absalom.(A)
1 Lord, how many are my foes!
How many rise up against me!
2 Many are saying of me,
“God will not deliver him.(B)”[b]
3 But you, Lord, are a shield(C) around me,
my glory, the One who lifts my head high.(D)
4 I call out to the Lord,(E)
and he answers me from his holy mountain.(F)
5 I lie down and sleep;(G)
I wake again,(H) because the Lord sustains me.
6 I will not fear(I) though tens of thousands
assail me on every side.(J)
Copyright: Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní Ẹ̀tọ́ àdàkọ © 2009, 2017 by Biblica, Inc. A lò ó nípa ìgbàyọ̀ǹda láti ọwọ́ Bíbílíkà Inc. Ààbò lórí ẹ̀tọ́ àdàkọ yìí múlẹ̀ jákèjádò àgbáyé. Yoruba Contemporary Bible Copyright © 2009, 2017 by Biblica, Inc.® Used by permission of Biblica, Inc.® All rights reserved worldwide.
Scripture taken from the New King James Version®. Copyright © 1982 by Thomas Nelson. Used by permission. All rights reserved.
The ESV® Bible (The Holy Bible, English Standard Version®), © 2001 by Crossway, a publishing ministry of Good News Publishers. ESV Text Edition: 2025.
Copyright by © Българско библейско дружество 2013. Използвани с разрешение.
Holy Bible, New International Version®, NIV® Copyright ©1973, 1978, 1984, 2011 by Biblica, Inc.® Used by permission. All rights reserved worldwide.
NIV Reverse Interlinear Bible: English to Hebrew and English to Greek. Copyright © 2019 by Zondervan.


