Saamu 143
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
Saamu ti Dafidi.
143 Olúwa gbọ́ àdúrà mi,
fetísí igbe mi fún àánú;
nínú òtítọ́ àti òdodo rẹ, wá fún ìrànlọ́wọ́ mi
2 (A)Má ṣe mú ìránṣẹ́ rẹ wá sí ìdájọ́,
nítorí kò sí ẹnìkan tí ó wà láààyè
tí ó ṣe òdodo níwájú rẹ.
3 Ọ̀tá ń lépa mi,
ó fún mi pamọ́ ilẹ̀;
ó mú mi gbé nínú òkùnkùn
bí àwọn tí ó ti kú ti pẹ́.
4 Nítorí náà ẹ̀mí mi ṣe rẹ̀wẹ̀sì nínú mi;
ọkàn mi nínú mi ṣì pòruurù.
5 Èmi rántí ọjọ́ tí ó ti pẹ́;
èmi ń ṣe àṣàrò lórí gbogbo iṣẹ́ rẹ
mo sì ṣe àkíyèsí ohun tí ọwọ́ rẹ ti ṣe.
6 Èmi na ọwọ́ mi jáde sí ọ:
òǹgbẹ rẹ gbẹ ọkàn mi bí i ìyàngbẹ ilẹ̀. Sela.
7 Dá mi lóhùn kánkán, Olúwa;
ó rẹ ẹ̀mí mi tán.
Má ṣe pa ojú rẹ mọ́ kúrò lára mi
kí èmi má ba à dàbí àwọn tí ó lọ sínú ihò
8 Mú mi gbọ́ ìṣeun ìfẹ́ rẹ ní òwúrọ̀:
nítorí ìwọ ni mo gbẹ́kẹ̀lé.
Fi ọ̀nà tí èmi i bá rìn hàn mí,
nítorí èmi gbé ọkàn mi sókè sí ọ.
9 Gbà mí kúrò lọ́wọ́ àwọn ọ̀tá mi, Olúwa,
nítorí èmi fi ara mi pamọ́ sínú rẹ.
10 Kọ́ mi láti ṣe ìfẹ́ rẹ,
nítorí ìwọ ni Ọlọ́run mi
jẹ́ kí ẹ̀mí rẹ dídára
darí mi sí ilẹ̀ tí ó tẹ́jú.
11 Nítorí orúkọ rẹ, Olúwa, sọ mi di ààyè;
nínú òdodo rẹ, mú ọkàn mi jáde nínú wàhálà.
12 Nínú ìfẹ́ rẹ tí kì í kùnà, ké àwọn ọ̀tá mi kúrò,
run gbogbo àwọn tí ń ni ọkàn mi lára,
nítorí pé èmi ni ìránṣẹ́ rẹ.
Psalm 143
New International Version
Psalm 143
A psalm of David.
1 Lord, hear my prayer,(A)
listen to my cry for mercy;(B)
in your faithfulness(C) and righteousness(D)
come to my relief.
2 Do not bring your servant into judgment,
for no one living is righteous(E) before you.
3 The enemy pursues me,
he crushes me to the ground;
he makes me dwell in the darkness(F)
like those long dead.(G)
4 So my spirit grows faint within me;
my heart within me is dismayed.(H)
5 I remember(I) the days of long ago;
I meditate(J) on all your works
and consider what your hands have done.
6 I spread out my hands(K) to you;
I thirst for you like a parched land.[a]
7 Answer me quickly,(L) Lord;
my spirit fails.(M)
Do not hide your face(N) from me
or I will be like those who go down to the pit.
8 Let the morning bring me word of your unfailing love,(O)
for I have put my trust in you.
Show me the way(P) I should go,
for to you I entrust my life.(Q)
9 Rescue me(R) from my enemies,(S) Lord,
for I hide myself in you.
10 Teach me(T) to do your will,
for you are my God;(U)
may your good Spirit
lead(V) me on level ground.(W)
Footnotes
- Psalm 143:6 The Hebrew has Selah (a word of uncertain meaning) here.
詩篇 143
Chinese Union Version Modern Punctuation (Traditional)
仇敵逼迫求主救脫
143 大衛的詩。
1 耶和華啊,求你聽我的禱告,留心聽我的懇求,憑你的信實和公義應允我!
2 求你不要審問僕人,因為在你面前,凡活著的人沒有一個是義的。
3 原來仇敵逼迫我,將我打倒在地,使我住在幽暗之處,像死了許久的人一樣。
4 所以我的靈在我裡面發昏,我的心在我裡面悽慘。
5 我追想古時之日,思想你的一切作為,默念你手的工作。
6 我向你舉手,我的心渴想你,如乾旱之地盼雨一樣。(細拉)
7 耶和華啊,求你速速應允我,我心神耗盡!不要向我掩面,免得我像那些下坑的人一樣。
8 求你使我清晨得聽你慈愛之言,因我倚靠你;求你使我知道當行的路,因我的心仰望你。
9 耶和華啊,求你救我脫離我的仇敵,我往你那裡藏身。
10 求你指教我遵行你的旨意,因你是我的神。你的靈本為善,求你引我到平坦之地。
11 耶和華啊,求你為你的名將我救活,憑你的公義將我從患難中領出來。
12 憑你的慈愛剪除我的仇敵,滅絕一切苦待我的人,因我是你的僕人。
Psalm 143
King James Version
143 Hear my prayer, O Lord, give ear to my supplications: in thy faithfulness answer me, and in thy righteousness.
2 And enter not into judgment with thy servant: for in thy sight shall no man living be justified.
3 For the enemy hath persecuted my soul; he hath smitten my life down to the ground; he hath made me to dwell in darkness, as those that have been long dead.
4 Therefore is my spirit overwhelmed within me; my heart within me is desolate.
5 I remember the days of old; I meditate on all thy works; I muse on the work of thy hands.
6 I stretch forth my hands unto thee: my soul thirsteth after thee, as a thirsty land. Selah.
7 Hear me speedily, O Lord: my spirit faileth: hide not thy face from me, lest I be like unto them that go down into the pit.
8 Cause me to hear thy lovingkindness in the morning; for in thee do I trust: cause me to know the way wherein I should walk; for I lift up my soul unto thee.
9 Deliver me, O Lord, from mine enemies: I flee unto thee to hide me.
10 Teach me to do thy will; for thou art my God: thy spirit is good; lead me into the land of uprightness.
11 Quicken me, O Lord, for thy name's sake: for thy righteousness' sake bring my soul out of trouble.
12 And of thy mercy cut off mine enemies, and destroy all them that afflict my soul: for I am thy servant.
Psalm 143
New King James Version
An Earnest Appeal for Guidance and Deliverance
A Psalm of David.
143 Hear my prayer, O Lord,
Give ear to my supplications!
In Your faithfulness answer me,
And in Your righteousness.
2 Do not enter into judgment with Your servant,
(A)For in Your sight no one living is righteous.
3 For the enemy has persecuted my soul;
He has crushed my life to the ground;
He has made me dwell in [a]darkness,
Like those who have long been dead.
4 (B)Therefore my spirit is overwhelmed within me;
My heart within me is distressed.
5 (C)I remember the days of old;
I meditate on all Your works;
I [b]muse on the work of Your hands.
6 I spread out my hands to You;
(D)My soul longs for You like a thirsty land. Selah
7 Answer me speedily, O Lord;
My spirit fails!
Do not hide Your face from me,
(E)Lest I [c]be like those who [d]go down into the pit.
8 Cause me to hear Your lovingkindness (F)in the morning,
For in You do I trust;
(G)Cause me to know the way in which I should walk,
For (H)I lift up my soul to You.
9 Deliver me, O Lord, from my enemies;
[e]In You I take shelter.
10 (I)Teach me to do Your will,
For You are my God;
(J)Your Spirit is good.
Lead me in (K)the land of uprightness.
11 (L)Revive me, O Lord, for Your name’s sake!
For Your righteousness’ sake bring my soul out of trouble.
12 In Your mercy (M)cut[f] off my enemies,
And destroy all those who afflict my soul;
For I am Your servant.
Footnotes
- Psalm 143:3 dark places
- Psalm 143:5 ponder
- Psalm 143:7 become
- Psalm 143:7 Die
- Psalm 143:9 LXX, Vg. To You I flee
- Psalm 143:12 put an end to
Copyright: Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní Ẹ̀tọ́ àdàkọ © 2009, 2017 by Biblica, Inc. A lò ó nípa ìgbàyọ̀ǹda láti ọwọ́ Bíbílíkà Inc. Ààbò lórí ẹ̀tọ́ àdàkọ yìí múlẹ̀ jákèjádò àgbáyé. Yoruba Contemporary Bible Copyright © 2009, 2017 by Biblica, Inc.® Used by permission of Biblica, Inc.® All rights reserved worldwide.
Holy Bible, New International Version®, NIV® Copyright ©1973, 1978, 1984, 2011 by Biblica, Inc.® Used by permission. All rights reserved worldwide.
NIV Reverse Interlinear Bible: English to Hebrew and English to Greek. Copyright © 2019 by Zondervan.
Copyright © 2011 by Global Bible Initiative
Scripture taken from the New King James Version®. Copyright © 1982 by Thomas Nelson. Used by permission. All rights reserved.

