Saamu 103
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
Ti Dafidi.
103 Yin Olúwa, ìwọ ọkàn mi; àti gbogbo ohun tí ó wà nínú mi, yín orúkọ rẹ̀ mímọ́.
2 Yin Olúwa, ìwọ ọkàn mi, kí o má ṣe gbàgbé gbogbo oore rẹ̀
3 Ẹni tí ó dárí gbogbo ẹ̀ṣẹ̀ rẹ̀ jì ọ́
tí ó sì wo gbogbo ààrùn rẹ̀ sàn,
4 Ẹni tí ó ra ẹ̀mí rẹ padà kúrò nínú kòtò ikú
ẹni tí ó fi ìṣeun ìfẹ́ àti ìyọ́nú dé ọ ní adé,
5 Ẹni tí ó fi ohun dídára tẹ́ ọ lọ́rùn
kí ìgbà èwe rẹ̀ lè di ọ̀tún bí ti ẹyẹ idì.
6 Olúwa ń ṣe òdodo àti ìdájọ́ fún
gbogbo àwọn tí a ni lára.
7 Ó fi ọ̀nà rẹ̀ hàn fún Mose, iṣẹ́ rẹ̀ fun àwọn ọmọ Israẹli;
8 (A)Olúwa ni aláàánú àti olóore,
ó lọ́ra láti bínú, ó sì pọ̀ ní ìfẹ́.
9 Òun kì í bá ni wí ní ìgbà gbogbo
bẹ́ẹ̀ ni kì í pa ìbínú rẹ mọ́ láéláé;
10 Òun kì í ṣe sí wa gẹ́gẹ́ bí ẹ̀ṣẹ̀ wa
bẹ́ẹ̀ ni kì í san án fún wa gẹ́gẹ́
bí àìṣedéédéé wa.
11 Nítorí bí ọ̀run ṣe ga sílẹ̀,
bẹ́ẹ̀ ni ìfẹ́ rẹ̀ tóbi sí àwọn tí ó bẹ̀rù rẹ̀.
12 Bí ìlà-oòrùn ti jìnnà sí ìwọ̀-oòrùn
bẹ́ẹ̀ ni ó ṣe mú ìrékọjá wá jìnnà sí wa.
13 Bí baba ti ń ṣe ìyọ́nú sí àwọn ọmọ rẹ̀,
bẹ́ẹ̀ ni Olúwa ń ṣe ìyọ́nú sí àwọn tí ó bẹ̀rù rẹ̀;
14 Nítorí tí ó mọ dídá wa,
ó rántí pé erùpẹ̀ ni wá.
15 Bí ó ṣe ti ènìyàn ni, ọjọ́ rẹ̀ dàbí koríko,
ó gbilẹ̀ bí ìtànná ewéko igbó;
16 Afẹ́fẹ́ fẹ́ kọjá lọ lórí rẹ̀,
kò sì rántí ibùjókòó rẹ̀ mọ́.
17 (B)Ṣùgbọ́n láti ayérayé ni ìfẹ́
Olúwa ti wà pẹ̀lú àwọn tí ó bẹ̀rù rẹ̀,
àti òdodo rẹ̀ wà láti ọmọdọ́mọ
18 Sí àwọn tí ó pa májẹ̀mú rẹ̀ mọ́
àti àwọn tí ó rántí òfin rẹ̀ láti ṣe wọ́n.
19 Olúwa ti pèsè ìtẹ́ rẹ̀ nínú ọ̀run,
ìjọba rẹ̀ ní ó sì borí ohun gbogbo.
20 Yin Olúwa, ẹ̀yin angẹli rẹ̀,
tí ó ní ipá, tí ó pa òfin ọ̀rọ̀ rẹ̀ mọ́
21 Yin Olúwa, ẹ̀yin ogun ọ̀run rẹ̀ gbogbo,
ẹ̀yin ìránṣẹ́ rẹ̀ tí ń ṣe ìfẹ́ rẹ̀.
22 Yin Olúwa, gbogbo iṣẹ́ rẹ̀ ní
ibi gbogbo ìjọba rẹ̀.
Yin Olúwa, ìwọ ọkàn mi.
Psalm 103
Amplified Bible, Classic Edition
Psalm 103
[A Psalm] of David.
1 Bless (affectionately, gratefully praise) the Lord, O my soul; and all that is [deepest] within me, bless His holy name!
2 Bless (affectionately, gratefully praise) the Lord, O my soul, and forget not [one of] all His benefits—
3 Who forgives [every one of] all your iniquities, Who heals [each one of] all your diseases,
4 Who redeems your life from the pit and corruption, Who beautifies, dignifies, and crowns you with loving-kindness and tender mercy;
5 Who satisfies your mouth [your necessity and desire at your personal age and situation] with good so that your youth, renewed, is like the eagle’s [strong, overcoming, soaring]!(A)
6 The Lord executes righteousness and justice [not for me only, but] for all who are oppressed.
7 He made known His ways [of righteousness and justice] to Moses, His acts to the children of Israel.
8 The Lord is merciful and gracious, slow to anger and plenteous in mercy and loving-kindness.(B)
9 He will not always chide or be contending, neither will He keep His anger forever or hold a grudge.
10 He has not dealt with us after our sins nor rewarded us according to our iniquities.
11 For as the heavens are high above the earth, so great are His mercy and loving-kindness toward those who reverently and worshipfully fear Him.
12 As far as the east is from the west, so far has He removed our transgressions from us.
13 As a father loves and pities his children, so the Lord loves and pities those who fear Him [with reverence, worship, and awe].
14 For He knows our frame, He [earnestly] remembers and imprints [on His heart] that we are dust.
15 As for man, his days are as grass; as a flower of the field, so he flourishes.
16 For the wind passes over it and it is gone, and its place shall know it no more.
17 But the mercy and loving-kindness of the Lord are from everlasting to everlasting upon those who reverently and worshipfully fear Him, and His righteousness is to children’s children—(C)
18 To such as keep His covenant [hearing, receiving, loving, and obeying it] and to those who [earnestly] remember His commandments to do them [imprinting them on their hearts].
19 The Lord has established His throne in the heavens, and His kingdom rules over all.
20 Bless (affectionately, gratefully praise) the Lord, you His angels, you mighty ones who do His commandments, hearkening to the voice of His word.
21 Bless (affectionately, gratefully praise) the Lord, all you His hosts, you His ministers who do His pleasure.
22 Bless the Lord, all His works in all places of His dominion; bless (affectionately, gratefully praise) the Lord, O my soul!
Psalm 103
King James Version
103 Bless the Lord, O my soul: and all that is within me, bless his holy name.
2 Bless the Lord, O my soul, and forget not all his benefits:
3 Who forgiveth all thine iniquities; who healeth all thy diseases;
4 Who redeemeth thy life from destruction; who crowneth thee with lovingkindness and tender mercies;
5 Who satisfieth thy mouth with good things; so that thy youth is renewed like the eagle's.
6 The Lord executeth righteousness and judgment for all that are oppressed.
7 He made known his ways unto Moses, his acts unto the children of Israel.
8 The Lord is merciful and gracious, slow to anger, and plenteous in mercy.
9 He will not always chide: neither will he keep his anger for ever.
10 He hath not dealt with us after our sins; nor rewarded us according to our iniquities.
11 For as the heaven is high above the earth, so great is his mercy toward them that fear him.
12 As far as the east is from the west, so far hath he removed our transgressions from us.
13 Like as a father pitieth his children, so the Lord pitieth them that fear him.
14 For he knoweth our frame; he remembereth that we are dust.
15 As for man, his days are as grass: as a flower of the field, so he flourisheth.
16 For the wind passeth over it, and it is gone; and the place thereof shall know it no more.
17 But the mercy of the Lord is from everlasting to everlasting upon them that fear him, and his righteousness unto children's children;
18 To such as keep his covenant, and to those that remember his commandments to do them.
19 The Lord hath prepared his throne in the heavens; and his kingdom ruleth over all.
20 Bless the Lord, ye his angels, that excel in strength, that do his commandments, hearkening unto the voice of his word.
21 Bless ye the Lord, all ye his hosts; ye ministers of his, that do his pleasure.
22 Bless the Lord, all his works in all places of his dominion: bless the Lord, O my soul.
Psalm 103
New International Version
Psalm 103
Of David.
1 Praise the Lord,(A) my soul;(B)
all my inmost being, praise his holy name.(C)
2 Praise the Lord,(D) my soul,
and forget not(E) all his benefits—
3 who forgives all your sins(F)
and heals(G) all your diseases,
4 who redeems your life(H) from the pit
and crowns you with love and compassion,(I)
5 who satisfies(J) your desires with good things
so that your youth is renewed(K) like the eagle’s.(L)
7 He made known(O) his ways(P) to Moses,
his deeds(Q) to the people of Israel:
8 The Lord is compassionate and gracious,(R)
slow to anger, abounding in love.
9 He will not always accuse,
nor will he harbor his anger forever;(S)
10 he does not treat us as our sins deserve(T)
or repay us according to our iniquities.
11 For as high as the heavens are above the earth,
so great is his love(U) for those who fear him;(V)
12 as far as the east is from the west,
so far has he removed our transgressions(W) from us.
13 As a father has compassion(X) on his children,
so the Lord has compassion on those who fear him;
14 for he knows how we are formed,(Y)
he remembers that we are dust.(Z)
15 The life of mortals is like grass,(AA)
they flourish like a flower(AB) of the field;
16 the wind blows(AC) over it and it is gone,
and its place(AD) remembers it no more.
17 But from everlasting to everlasting
the Lord’s love is with those who fear him,
and his righteousness with their children’s children(AE)—
18 with those who keep his covenant(AF)
and remember(AG) to obey his precepts.(AH)
20 Praise the Lord,(AK) you his angels,(AL)
you mighty ones(AM) who do his bidding,(AN)
who obey his word.
21 Praise the Lord, all his heavenly hosts,(AO)
you his servants(AP) who do his will.
22 Praise the Lord, all his works(AQ)
everywhere in his dominion.
Praise the Lord, my soul.(AR)
Copyright: Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní Ẹ̀tọ́ àdàkọ © 2009, 2017 by Biblica, Inc. A lò ó nípa ìgbàyọ̀ǹda láti ọwọ́ Bíbílíkà Inc. Ààbò lórí ẹ̀tọ́ àdàkọ yìí múlẹ̀ jákèjádò àgbáyé. Yoruba Contemporary Bible Copyright © 2009, 2017 by Biblica, Inc.® Used by permission of Biblica, Inc.® All rights reserved worldwide.
Copyright © 1954, 1958, 1962, 1964, 1965, 1987 by The Lockman Foundation
Holy Bible, New International Version®, NIV® Copyright ©1973, 1978, 1984, 2011 by Biblica, Inc.® Used by permission. All rights reserved worldwide.
NIV Reverse Interlinear Bible: English to Hebrew and English to Greek. Copyright © 2019 by Zondervan.

