Add parallel Print Page Options

Ti Dafidi. Saamu.

101 Èmi yóò kọrin ìfẹ́ àti òdodo;
    sí ọ Olúwa, èmi yóò máa kọrin ìyìn.
Èmi yóò máa rin ìrìn mi pẹ̀lú ọgbọ́n láìlẹ́ṣẹ̀,
    ìgbà wo ni ìwọ yóò wá sí ọ̀dọ̀ mi?

Èmi yóò máa rìn ní ilé mi
    pẹ̀lú àyà pípé.
Èmi kì yóò gbé ohun búburú sí iwájú mi:
    iṣẹ́ àwọn tí ó yapa ni èmi kórìíra.

    Wọn kì yóò rọ̀ mọ́ mi.
Agídí ọkàn yóò kúrò lọ́dọ̀ mi;
    Èmi kì yóò mọ ènìyàn búburú.

Ẹnikẹ́ni tí ó bá ń sọ̀rọ̀ ẹnìkejì rẹ̀ ní ìkọ̀kọ̀,
    òun ní èmi yóò gé kúrò
ẹni tí ó bá gbé ojú rẹ̀ ga tí ó sì ní ìgbéraga àyà,
    òun ní èmi kì yóò faradà fún.

Ojú mi yóò wà lára àwọn olóòtítọ́ lórí ilẹ̀,
    kí wọn kí ó lè máa bá mi gbé;
ẹni tí ó bá n rin ọ̀nà pípé
    òun ni yóò máa sìn mí.

Ẹni tí ó bá ń ṣe ẹ̀tàn, kì yóò gbé ilé mi,
    kò sí ẹni tí ń ṣèké tí yóò dúró ní iwájú mi.

Ní ojoojúmọ́ ní èmi yóò wá máa pa a lẹ́nu mọ
    gbogbo àwọn ènìyàn búburú ilẹ̀ náà;
èmi yóò gé àwọn olùṣe búburú
    kúrò ní ìlú Olúwa.

101 I will sing of mercy and judgment: unto thee, O Lord, will I sing.

I will behave myself wisely in a perfect way. O when wilt thou come unto me? I will walk within my house with a perfect heart.

I will set no wicked thing before mine eyes: I hate the work of them that turn aside; it shall not cleave to me.

A froward heart shall depart from me: I will not know a wicked person.

Whoso privily slandereth his neighbour, him will I cut off: him that hath an high look and a proud heart will not I suffer.

Mine eyes shall be upon the faithful of the land, that they may dwell with me: he that walketh in a perfect way, he shall serve me.

He that worketh deceit shall not dwell within my house: he that telleth lies shall not tarry in my sight.

I will early destroy all the wicked of the land; that I may cut off all wicked doers from the city of the Lord.

Psalm 101

A Psalm of David.

I will sing of mercy and loving-kindness and justice; to You, O Lord, will I sing.

I will behave myself wisely and give heed to the blameless way—O when will You come to me? I will walk within my house in integrity and with a blameless heart.

I will set no base or wicked thing before my eyes. I hate the work of them who turn aside [from the right path]; it shall not grasp hold of me.

A perverse heart shall depart from me; I will know no evil person or thing.

Whoso privily slanders his neighbor, him will I cut off [from me]; he who has a haughty look and a proud and arrogant heart I cannot and I will not tolerate.

My eyes shall [look with favor] upon the faithful of the land, that they may dwell with me; he who walks blamelessly, he shall minister to me.

He who works deceit shall not dwell in my house; he who tells lies shall not continue in my presence.

Morning after morning I will root up all the wicked in the land, that I may eliminate all the evildoers from the city of the Lord.

Promised Faithfulness to the Lord

A Psalm of David.

101 I will sing of mercy and justice;
To You, O Lord, I will sing praises.

I will behave wisely in a [a]perfect way.
Oh, when will You come to me?
I will (A)walk within my house with a perfect heart.

I will set nothing [b]wicked before my eyes;
(B)I hate the work of those (C)who fall away;
It shall not cling to me.
A perverse heart shall depart from me;
I will not (D)know wickedness.

Whoever secretly slanders his neighbor,
Him I will destroy;
(E)The one who has a haughty look and a proud heart,
Him I will not endure.

My eyes shall be on the faithful of the land,
That they may dwell with me;
He who walks in a [c]perfect way,
He shall serve me.
He who works deceit shall not dwell within my house;
He who tells lies shall not [d]continue in my presence.
(F)Early I will destroy all the wicked of the land,
That I may cut off all the evildoers (G)from the city of the Lord.

Footnotes

  1. Psalm 101:2 blameless
  2. Psalm 101:3 worthless
  3. Psalm 101:6 blameless
  4. Psalm 101:7 Lit. be established