Add parallel Print Page Options

22 (A)“Ojú ni fìtílà ara. Bí ojú rẹ bá mọ́lẹ̀ kedere, gbogbo ara rẹ yóò jẹ́ kìkì ìmọ́lẹ̀. 23 Ṣùgbọ́n bí ojú rẹ kò bá dára, gbogbo ara rẹ ni yóò kún fún òkùnkùn. Bí ìmọ́lẹ̀ ti ó wà nínú rẹ bá wá jẹ́ òkùnkùn, òkùnkùn náà yóò ti pọ̀ tó!

Read full chapter

22 “The eye is the lamp of the body. If your eyes are healthy,[a] your whole body will be full of light. 23 But if your eyes are unhealthy,[b] your whole body will be full of darkness. If then the light within you is darkness, how great is that darkness!

Read full chapter

Footnotes

  1. Matthew 6:22 The Greek for healthy here implies generous.
  2. Matthew 6:23 The Greek for unhealthy here implies stingy.