Add parallel Print Page Options

17 Lóòótọ́ ni mo wí fún yín, ọ̀pọ̀ àwọn wòlíì àti ènìyàn Ọlọ́run ti fẹ́ rí ohun tí ẹ̀yin ti rí, ki wọ́n sì gbọ́ ohun tí ẹ ti gbọ́, ṣùgbọ́n kò ṣe é ṣe fún wọn.

Read full chapter

17 For truly I tell you, many prophets and righteous people longed to see what you see(A) but did not see it, and to hear what you hear but did not hear it.

Read full chapter

13 (A)Gbogbo àwọn wọ̀nyí ni ó kú nínú ìgbàgbọ́, láìrí àwọn ìlérí náà gbà, ṣùgbọ́n tí wọn rí wọn ni òkèrè réré, tí wọ́n sì gbá wọn mú, tí wọ́n sì jẹ́wọ́ pé àlejò àti àjèjì ni àwọn lórí ilẹ̀ ayé.

Read full chapter

13 All these people were still living by faith when they died. They did not receive the things promised;(A) they only saw them and welcomed them from a distance,(B) admitting that they were foreigners and strangers on earth.(C)

Read full chapter