Añadir traducción en paralelo Imprimir Opciones de la página

39 Ẹni tí ó bá wa ẹ̀mí rẹ̀ yóò sọ ọ́ nù, ṣùgbọ́n ẹni tí ó bá sọ ẹ̀mí rẹ̀ nú nítorí tèmi ni yóò rí i.

Read full chapter

39 Whoever finds their life will lose it, and whoever loses their life for my sake will find it.(A)

Read full chapter

35 (A)Nítorí ẹni tó bá gbìyànjú láti gba ẹ̀mí ara rẹ̀ là, yóò sọ ọ́ nù. Iye àwọn tí ó sọ ẹ̀mí wọn nù nìkan nítorí í tèmi àti nítorí ìhìnrere, òun náà ni yóò gbà á là.

Read full chapter

35 For whoever wants to save their life[a] will lose it, but whoever loses their life for me and for the gospel will save it.(A)

Read full chapter

Notas al pie

  1. Mark 8:35 The Greek word means either life or soul; also in verses 36 and 37.

24 (A)Nítorí ẹnikẹ́ni tí ó bá fẹ́ gba ọkàn rẹ̀ là, yóò sọ ọ́ nù: ṣùgbọ́n ẹnikẹ́ni tí ó bá sọ ọkàn rẹ̀ nù nítorí mi, òun náà ni yóò sì gbà á là.

Read full chapter

24 For whoever wants to save their life will lose it, but whoever loses their life for me will save it.(A)

Read full chapter

26 (A)“Bí ẹnìkan bá tọ̀ mí wá, tí kò sì kórìíra baba àti ìyá, àti aya, àti ọmọ, àti arákùnrin, àti arábìnrin, àní àti ọkàn ara rẹ̀ pẹ̀lú, kò lè ṣe ọmọ-ẹ̀yìn mi.

Read full chapter

26 “If anyone comes to me and does not hate father and mother, wife and children, brothers and sisters—yes, even their own life—such a person cannot be my disciple.(A)

Read full chapter