Luku 12:1
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
Àwọn ìkìlọ̀ àti ọ̀rọ̀ ìyànjú
12 (A)Ó sì ṣe, nígbà tí àìníye ìjọ ènìyàn péjọpọ̀, tó bẹ́ẹ̀ tí wọn ń tẹ ara wọn mọ́lẹ̀, ó bẹ̀rẹ̀ sísọ fún àwọn ọmọ-ẹ̀yìn rẹ̀ pé, “Ẹ máa ṣọ́ra yín nítorí ìwúkàrà àwọn Farisi tí í ṣe àgàbàgebè.
Read full chapter
Luke 12:1
New International Version
Warnings and Encouragements(A)
12 Meanwhile, when a crowd of many thousands had gathered, so that they were trampling on one another, Jesus began to speak first to his disciples, saying: “Be[a] on your guard against the yeast of the Pharisees, which is hypocrisy.(B)
Footnotes
- Luke 12:1 Or speak to his disciples, saying: “First of all, be
Marku 6:14
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
A bẹ́ Johanu onítẹ̀bọmi lórí
14 (A)Láìpẹ́, ọba Herodu gbọ́ nípa Jesu, nítorí níbi gbogbo ni a ti ń sọ̀rọ̀ iṣẹ́ ìyanu rẹ̀. Ọba náà rò pé, “Johanu Onítẹ̀bọmi jíǹde kúrò nínú òkú, nítorí náà ni iṣẹ́ ìyanu ṣe ń ṣe láti ọwọ́ rẹ.”
Read full chapter
Mark 6:14
New International Version
John the Baptist Beheaded(A)(B)
14 King Herod heard about this, for Jesus’ name had become well known. Some were saying,[a] “John the Baptist(C) has been raised from the dead, and that is why miraculous powers are at work in him.”
Footnotes
- Mark 6:14 Some early manuscripts He was saying
Marku 12:13
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
Sísan owó orí fún Kesari
13 (A)(B) Ṣùgbọ́n wọ́n rán àwọn Farisi pẹ̀lú àwọn kan tí í ṣe ọmọ-ẹ̀yìn Herodu wá sọ́dọ̀ Jesu, láti fi ọ̀rọ̀ wá a lẹ́nu wò, títí yóò fi sọ ohun kan kí wọn lè rí fi mú.
Read full chapter
Mark 12:13
New International Version
Paying the Imperial Tax to Caesar(A)
13 Later they sent some of the Pharisees and Herodians(B) to Jesus to catch him(C) in his words.
Copyright: Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní Ẹ̀tọ́ àdàkọ © 2009, 2017 by Biblica, Inc. A lò ó nípa ìgbàyọ̀ǹda láti ọwọ́ Bíbílíkà Inc. Ààbò lórí ẹ̀tọ́ àdàkọ yìí múlẹ̀ jákèjádò àgbáyé. Yoruba Contemporary Bible Copyright © 2009, 2017 by Biblica, Inc.® Used by permission of Biblica, Inc.® All rights reserved worldwide.
Holy Bible, New International Version®, NIV® Copyright ©1973, 1978, 1984, 2011 by Biblica, Inc.® Used by permission. All rights reserved worldwide.
NIV Reverse Interlinear Bible: English to Hebrew and English to Greek. Copyright © 2019 by Zondervan.