Font Size
Onidajọ 19:1
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
Onidajọ 19:1
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
Ọmọ Lefi kan àti àlè rẹ̀
19 Ní ọjọ́ wọ̀n-ọn-nì Israẹli kò ní ọba.
Ọ̀kan nínú àwọn ọmọ Lefi tí ń gbé ibi tí ó sápamọ́ nínú àwọn agbègbè òkè Efraimu, mú àlè kan láti Bẹtilẹhẹmu ní Juda.
Read full chapter
Onidajọ 19:2
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
Onidajọ 19:2
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
2 Ṣùgbọ́n àlè rẹ̀ náà sì ṣe panṣágà sí i, òun fi sílẹ̀, ó sì padà lọ sí ilé baba rẹ̀ ní Bẹtilẹhẹmu ti Juda, ó sì wà ní ibẹ̀ ní ìwọ̀n oṣù mẹ́rin,
Read full chapter
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn (BYO)
Copyright: Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní Ẹ̀tọ́ àdàkọ © 2009, 2017 by Biblica, Inc. A lò ó nípa ìgbàyọ̀ǹda láti ọwọ́ Bíbílíkà Inc. Ààbò lórí ẹ̀tọ́ àdàkọ yìí múlẹ̀ jákèjádò àgbáyé. Yoruba Contemporary Bible Copyright © 2009, 2017 by Biblica, Inc.® Used by permission of Biblica, Inc.® All rights reserved worldwide.