Añadir traducción en paralelo Imprimir Opciones de la página

30 (A)Bí ó ti ń sọ nǹkan wọ̀nyí, ọ̀pọ̀ ènìyàn gbà á gbọ́.

Read full chapter

42 (A)Àwọn ènìyàn púpọ̀ níbẹ̀ sì gbà á gbọ́.

Read full chapter

Àwọn alábojútó pinnu láti pa Jesu

45 Nítorí náà ni ọ̀pọ̀ àwọn Júù tí ó wá sọ́dọ̀ Maria, tí wọ́n rí ohun tí Jesu ṣe, ṣe gbà á gbọ́.

Read full chapter