Font Size
Johanu 7:7
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
Johanu 7:7
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
7 (A)Ayé kò lè kórìíra yín; ṣùgbọ́n èmi ni ó kórìíra, nítorí tí mo jẹ́rìí gbé é pé, iṣẹ́ rẹ̀ burú.
Read full chapter
1 Johanu 3:13
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
1 Johanu 3:13
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
13 (A)Kì ẹnu má ṣe yà yín, ẹ̀yin ará mi, bí ayé bá kórìíra yín.
Read full chapter
Matiu 10:22
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
Matiu 10:22
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
22 Gbogbo ènìyàn yóò sì kórìíra yín nítorí mi, ṣùgbọ́n gbogbo ẹni tí ó bá dúró ṣinṣin dé òpin ni a ó gbàlà.
Read full chapter
Matiu 24:9
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
Matiu 24:9
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
9 (A)“Nígbà náà ni a ó sì dá a yín lóró. A ó pa yín, a ó sì kórìíra yín ni gbogbo orílẹ̀-èdè, nítorí pé ẹ̀yin jẹ́ tèmi.
Read full chapter
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn (BYO)
Copyright: Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní Ẹ̀tọ́ àdàkọ © 2009, 2017 by Biblica, Inc. A lò ó nípa ìgbàyọ̀ǹda láti ọwọ́ Bíbílíkà Inc. Ààbò lórí ẹ̀tọ́ àdàkọ yìí múlẹ̀ jákèjádò àgbáyé. Yoruba Contemporary Bible Copyright © 2009, 2017 by Biblica, Inc.® Used by permission of Biblica, Inc.® All rights reserved worldwide.