Font Size
Johanu 5:29
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
Johanu 5:29
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
29 (A)Wọn ó sì jáde wá; àwọn tí ó ṣe rere, sí àjíǹde ìyè; àwọn tí ó sì ṣe búburú sí àjíǹde ìdájọ́.
Read full chapter
Johanu 11:24
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
Johanu 11:24
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
24 (A)Marta wí fún un pé, “Mo mọ̀ pé yóò jíǹde ní àjíǹde ìkẹyìn.”
Read full chapter
Johanu 6:54
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
Johanu 6:54
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
54 Ẹnikẹ́ni tí ó bá jẹ ara mi, tí ó bá sì mu ẹ̀jẹ̀ mi, ó ní ìyè tí kò nípẹ̀kun; Èmi o sì jí i dìde níkẹyìn ọjọ́.
Read full chapter
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn (BYO)
Copyright: Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní Ẹ̀tọ́ àdàkọ © 2009, 2017 by Biblica, Inc. A lò ó nípa ìgbàyọ̀ǹda láti ọwọ́ Bíbílíkà Inc. Ààbò lórí ẹ̀tọ́ àdàkọ yìí múlẹ̀ jákèjádò àgbáyé. Yoruba Contemporary Bible Copyright © 2009, 2017 by Biblica, Inc.® Used by permission of Biblica, Inc.® All rights reserved worldwide.