Add parallel Print Page Options

Èsì Elifasi

22 Ìgbà náà ni Elifasi, ará Temani, dáhùn wí pé:

(A)“Ènìyàn lè è ṣe rere fún Ọlọ́run?
    Bí ọlọ́gbọ́n ti í ṣe rere fún ara rẹ̀?
Ohun ayọ̀ ha ni fún Olódùmarè pé olódodo ni ìwọ?
    Tàbí èrè kí ni fún un ti ìwọ mú ọ̀nà rẹ̀ pé?

“Yóò ha bá ọ wí bí, nítorí ìbẹ̀rù
    Ọlọ́run rẹ? Yóò ha bá ọ lọ sínú ìdájọ́ bí?
Ìwà búburú rẹ kò ha tóbi,
    àti ẹ̀ṣẹ̀ rẹ láìníye?
Nítòótọ́ ìwọ béèrè fún ààbò ni ọwọ́ arákùnrin rẹ láìnídìí,
    ìwọ sì tú oníhòhò ní aṣọ wọn.
Ìwọ kò fi omi fún aláàárẹ̀ mu,
    ìwọ sì háwọ́ oúnjẹ fún ẹni tí ebi ń pa.
Bí ó ṣe ti alágbára nì, òun ni ó ní ilẹ̀,
    ọlọ́lá sì tẹ̀dó sínú rẹ̀.
Ìwọ ti rán àwọn opó padà lọ ní ọwọ́ òfo;
    Apá àwọn ọmọ aláìní baba ti di ṣiṣẹ́.
10 Nítorí náà ni ìdẹ̀kùn ṣe yí ọ káàkiri,
    àti ìbẹ̀rù òjijì ń yọ ọ́ lẹ́nu,
11 Èéṣe tí òkùnkùn fi pọ̀ tó bẹ́ẹ̀ tí ìwọ kò fi lè ríran;
    Èéṣe tí ọ̀pọ̀lọpọ̀ omi sì bò ọ́ mọ́lẹ̀.

12 “Ọlọ́run kò ha jẹ́ ẹni gíga ọ̀run?
    Sá wo orí àwọn ìràwọ̀ bí wọ́n ti ga tó!
13 Ìwọ sì wí pé, Ọlọ́run ti ṣe mọ̀?
    Òun ha lè ṣe ìdájọ́ láti inú òkùnkùn wá bí?
14 Ǹjẹ́ àwọsánmọ̀ tí ó nípọn jẹ ìbora fún un,
    tí kò fi lè ríran; ó sì ń rìn nínú àyíká ọ̀run.
15 Ǹjẹ́ ìwọ fẹ́ rin ipa ọ̀nà ìgbàanì tí àwọn
    ènìyàn búburú tí rìn?
16 A ké wọn lulẹ̀ kúrò nínú ayé láìpé ọjọ́ wọn;
    ìpìlẹ̀ wọn ti da bí odò ṣíṣàn;
17 Àwọn ẹni tí ó wí fún Ọlọ́run pé, ‘Lọ kúrò lọ́dọ̀ wa!
    Kí ni Olódùmarè yóò ṣe fún wọn?’
18 Síbẹ̀ ó fi ohun rere kún ilé wọn!
    Ṣùgbọ́n ìmọ̀ ènìyàn búburú jìnnà sí mi!
19 Àwọn olódodo rí ìparun wọn, wọ́n sì yọ̀,
    àwọn aláìlẹ́ṣẹ̀ sì fi wọ́n rẹ́rìn-ín ẹlẹ́yà pé,
20 ‘Lóòtítọ́ àwọn ọ̀tá wa ni a ké kúrò,
    iná yóò sì jó oró wọn run.’

21 “Fa ara rẹ súnmọ́ Ọlọ́run, ìwọ ó sì rí àlàáfíà;
    nípa èyí ni rere yóò wá bá ọ.
22 Èmi bẹ̀ ọ́, gba òfin láti ẹnu rẹ̀ wá,
    kí o sì to ọ̀rọ̀ rẹ̀ sí àyà rẹ.
23 Bí ìwọ bá yípadà sọ́dọ̀ Olódùmarè, a sì gbé ọ ró:
    Bí ìwọ bá sì mú ẹ̀ṣẹ̀ jìnnà réré kúrò nínú àgọ́ rẹ,
24 Tí ìwọ bá tẹ́ wúrà dáradára sílẹ̀
    lórí erùpẹ̀ àti wúrà ofiri lábẹ́ òkúta odò,
25 Nígbà náà ní Olódùmarè yóò jẹ́ wúrà rẹ,
    àní yóò sì jẹ́ fàdákà fún ọ ní ọ̀pọ̀lọpọ̀.
26 Lóòtítọ́ nígbà náà ní ìwọ ó ní inú dídùn nínú Olódùmarè,
    ìwọ ó sì gbé ojú rẹ sókè sọ́dọ̀ Ọlọ́run.
27 Bí ìwọ bá gbàdúrà rẹ sọ́dọ̀ rẹ̀, yóò sì gbọ́ tìrẹ,
    ìwọ ó sì san ẹ̀jẹ́ rẹ.
28 Ìwọ ó sì gbìmọ̀ ohun kan pẹ̀lú, yóò sì fi ìdí múlẹ̀ fún ọ;
    ìmọ́lẹ̀ yóò sì mọ́ sípa ọ̀nà rẹ.
29 Nígbà tí ipa ọ̀nà rẹ bá lọ sísàlẹ̀,
    nígbà náà ni ìwọ o wí pé, ‘Ìgbésókè ń bẹ!’
    Ọlọ́run yóò sì gba onírẹ̀lẹ̀ là!
30 Yóò gba ẹni tí kì í ṣe aláìjẹ̀bi là,
    a ó sì gbà á nípa mímọ́ ọwọ́ rẹ̀.”

Eliphaz Accuses Job of Wickedness

22 Then (A)Eliphaz the Temanite answered and said:

“Can(B) a man be profitable to God,
Though he who is wise may be profitable to himself?
Is it any pleasure to the Almighty that you are righteous?
Or is it gain to Him that you make your ways blameless?

“Is it because of your fear of Him that He corrects you,
And enters into judgment with you?
Is not your wickedness great,
And your iniquity without end?
For you have (C)taken pledges from your brother for no reason,
And stripped the naked of their clothing.
You have not given the weary water to drink,
And you (D)have withheld bread from the hungry.
But the [a]mighty man possessed the land,
And the honorable man dwelt in it.
You have sent widows away empty,
And the [b]strength of the fatherless was crushed.
10 Therefore snares are all around you,
And sudden fear troubles you,
11 Or darkness so that you cannot see;
And an abundance of (E)water covers you.

12 “Is not God in the height of heaven?
And see the highest stars, how lofty they are!
13 And you say, (F)‘What does God know?
Can He judge through the deep darkness?
14 (G)Thick clouds cover Him, so that He cannot see,
And He walks above the circle of heaven.’
15 Will you keep to the old way
Which wicked men have trod,
16 Who (H)were cut down before their time,
Whose foundations were swept away by a flood?
17 (I)They said to God, ‘Depart from us!
What can the Almighty do to [c]them?’
18 Yet He filled their houses with good things;
But the counsel of the wicked is far from me.

19 “The(J) righteous see it and are glad,
And the innocent laugh at them:
20 ‘Surely our [d]adversaries are cut down,
And the fire consumes their remnant.’

21 “Now acquaint yourself with Him, and (K)be at peace;
Thereby good will come to you.
22 Receive, please, (L)instruction from His mouth,
And (M)lay up His words in your heart.
23 If you return to the Almighty, you will be built up;
You will remove iniquity far from your tents.
24 Then you will (N)lay your gold in the dust,
And the gold of Ophir among the stones of the brooks.
25 Yes, the Almighty will be your [e]gold
And your precious silver;
26 For then you will have your (O)delight in the Almighty,
And lift up your face to God.
27 (P)You will make your prayer to Him,
He will hear you,
And you will pay your vows.
28 You will also declare a thing,
And it will be established for you;
So light will shine on your ways.
29 When they cast you down, and you say, ‘Exaltation will come!
Then (Q)He will save the humble person.
30 He will even deliver one who is not innocent;
Yes, he will be delivered by the purity of your hands.”

Footnotes

  1. Job 22:8 Lit. man of arm
  2. Job 22:9 Lit. arms
  3. Job 22:17 LXX, Syr. us
  4. Job 22:20 LXX substance is
  5. Job 22:25 Ancient vss. suggest defense; MT gold, as in v. 24

Eliphaz

22 Then Eliphaz the Temanite(A) replied:

“Can a man be of benefit to God?(B)
    Can even a wise person benefit him?(C)
What pleasure(D) would it give the Almighty if you were righteous?(E)
    What would he gain if your ways were blameless?(F)

“Is it for your piety that he rebukes you
    and brings charges against you?(G)
Is not your wickedness great?
    Are not your sins(H) endless?(I)
You demanded security(J) from your relatives for no reason;(K)
    you stripped people of their clothing, leaving them naked.(L)
You gave no water(M) to the weary
    and you withheld food from the hungry,(N)
though you were a powerful man, owning land(O)
    an honored man,(P) living on it.(Q)
And you sent widows(R) away empty-handed(S)
    and broke the strength of the fatherless.(T)
10 That is why snares(U) are all around you,(V)
    why sudden peril terrifies you,(W)
11 why it is so dark(X) you cannot see,
    and why a flood of water covers you.(Y)

12 “Is not God in the heights of heaven?(Z)
    And see how lofty are the highest stars!
13 Yet you say, ‘What does God know?(AA)
    Does he judge through such darkness?(AB)
14 Thick clouds(AC) veil him, so he does not see us(AD)
    as he goes about in the vaulted heavens.’(AE)
15 Will you keep to the old path
    that the wicked(AF) have trod?(AG)
16 They were carried off before their time,(AH)
    their foundations(AI) washed away by a flood.(AJ)
17 They said to God, ‘Leave us alone!
    What can the Almighty do to us?’(AK)
18 Yet it was he who filled their houses with good things,(AL)
    so I stand aloof from the plans of the wicked.(AM)
19 The righteous see their ruin and rejoice;(AN)
    the innocent mock(AO) them, saying,
20 ‘Surely our foes are destroyed,(AP)
    and fire(AQ) devours their wealth.’

21 “Submit to God and be at peace(AR) with him;(AS)
    in this way prosperity will come to you.(AT)
22 Accept instruction from his mouth(AU)
    and lay up his words(AV) in your heart.(AW)
23 If you return(AX) to the Almighty, you will be restored:(AY)
    If you remove wickedness far from your tent(AZ)
24 and assign your nuggets(BA) to the dust,
    your gold(BB) of Ophir(BC) to the rocks in the ravines,(BD)
25 then the Almighty will be your gold,(BE)
    the choicest silver for you.(BF)
26 Surely then you will find delight in the Almighty(BG)
    and will lift up your face(BH) to God.(BI)
27 You will pray to him,(BJ) and he will hear you,(BK)
    and you will fulfill your vows.(BL)
28 What you decide on will be done,(BM)
    and light(BN) will shine on your ways.(BO)
29 When people are brought low(BP) and you say, ‘Lift them up!’
    then he will save the downcast.(BQ)
30 He will deliver even one who is not innocent,(BR)
    who will be delivered through the cleanness of your hands.”(BS)

Eliphaz Speaks: Job's Wickedness Is Great

22 Then (A)Eliphaz the Temanite answered and said:

(B)“Can a man be profitable to God?
    Surely he who is wise is profitable to himself.
Is it any pleasure to the Almighty if you are in the right,
    or is it gain to him if you (C)make your ways blameless?
Is it for your fear of him that he reproves you
    and (D)enters into judgment with you?
Is not your evil abundant?
    There is no end to your iniquities.
For you have (E)exacted pledges of your brothers for nothing
    (F)and stripped the naked of their clothing.
You have given no water to the weary to drink,
    and you have (G)withheld bread from the hungry.
(H)The man with power possessed the land,
    and (I)the favored man lived in it.
You have (J)sent widows away empty,
    and (K)the arms of (L)the fatherless were crushed.
10 Therefore (M)snares are all around you,
    and sudden terror overwhelms you,
11 or (N)darkness, so that you cannot see,
    and a (O)flood of (P)water covers you.

12 “Is not God high in the heavens?
    See (Q)the highest stars, how lofty they are!
13 But you say, (R)‘What does God know?
    Can he judge through (S)the deep darkness?
14 (T)Thick clouds veil him, so that he does not see,
    and he walks on the vault of heaven.’
15 Will you keep to the old way
    that wicked men have trod?
16 They were snatched away (U)before their time;
    their foundation was washed away.[a]
17 They said to God, (V)‘Depart from us,’
    and (W)‘What can the Almighty do to us?’[b]
18 Yet he filled their houses with good things—
    but (X)the counsel of the wicked is far from me.
19 (Y)The righteous see it and are glad;
    the innocent one (Z)mocks at them,
20 saying, ‘Surely our adversaries are cut off,
    and what they left (AA)the fire has consumed.’

21 (AB)“Agree with God, and (AC)be at peace;
    thereby good will come to you.
22 Receive instruction from (AD)his mouth,
    and (AE)lay up his words in your heart.
23 If you (AF)return to the Almighty you will be (AG)built up;
    if you (AH)remove injustice far from your tents,
24 if you lay gold in (AI)the dust,
    and gold of (AJ)Ophir among the stones of the torrent-bed,
25 then the Almighty will be your gold
    and your precious silver.
26 For then you (AK)will delight yourself in the Almighty
    and (AL)lift up your face to God.
27 You will (AM)make your prayer to him, and he will hear you,
    and you will (AN)pay your vows.
28 You will decide on a matter, and it will be established for you,
    and (AO)light will shine on your ways.
29 For when they are humbled you say, ‘It is because of pride’;[c]
    but he saves (AP)the lowly.
30 He (AQ)delivers even the one who is not innocent,
    who will be delivered through (AR)the cleanness of your hands.”

Footnotes

  1. Job 22:16 Or their foundation was poured out as a stream (or river)
  2. Job 22:17 Hebrew them
  3. Job 22:29 Or you say, ‘It is exaltation’