Jobu 20
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
Ìdáhùn Sofari
20 Ìgbà náà ní Sofari, ará Naama dáhùn, ó sì wí pé:
2 “Nítorí náà ní ìrò inú mi dá mi lóhùn,
àti nítorí èyí náà ní mo sì yára si gidigidi.
3 Mo ti gbọ́ ẹ̀san ẹ̀gàn mi, ẹ̀mí òye
mi sì dá mi lóhùn.
4 “Ìwọ kò mọ̀ èyí rí ní ìgbà àtijọ́,
láti ìgbà tí a sọ ènìyàn lọ́jọ̀ sílé ayé,
5 pé, orin ayọ̀ ènìyàn búburú, ìgbà kúkúrú ni,
àti pé, ní ìṣẹ́jú kan ní ayọ̀ àgàbàgebè?
6 Bí ọláńlá rẹ̀ tilẹ̀ gòkè dé ọ̀run,
ti orí rẹ̀ sì kan àwọsánmọ̀;
7 Ṣùgbọ́n yóò ṣègbé láéláé bí ìgbẹ́ ara rẹ̀;
àwọn tí ó ti rí i rí yóò wí pé, ‘Òun ha dà?’
8 Yóò fò lọ bí àlá, a kì yóò sì rí i,
àní a ó lé e lọ bi ìran òru.
9 Ojú tí ó ti rí i rí kì yóò sì rí i mọ́,
bẹ́ẹ̀ ni ibùjókòó rẹ̀ kì yóò sì ri i mọ́.
10 Àwọn ọmọ rẹ̀ yóò máa wá àti rí ojúrere lọ́dọ̀ tálákà,
ọwọ́ rẹ̀ yóò sì kó ọrọ̀ wọn padà.
11 Egungun rẹ̀ kún fún agbára ìgbà èwe rẹ̀,
tí yóò bá a dùbúlẹ̀ nínú erùpẹ̀.
12 “Bí ìwà búburú tilẹ̀ dún ní ẹnu rẹ̀,
bí ó tilẹ̀ pa á mọ́ nísàlẹ̀ ahọ́n rẹ̀,
13 bí ó tilẹ̀ dá a sì, tí kò si kọ̀ ọ́ sílẹ̀,
tí ó pa á mọ́ síbẹ̀ ní ẹnu rẹ̀,
14 Ṣùgbọ́n oúnjẹ rẹ̀ nínú ikùn rẹ̀ ti yípadà,
ó jásí òróró paramọ́lẹ̀ nínú rẹ̀;
15 Ó ti gbé ọrọ̀ mì, yóò sì tún bí i jáde;
Ọlọ́run yóò pọ̀ ọ́ yọ jáde láti inú rẹ̀ wá.
16 Ó ti fà oró paramọ́lẹ̀ mú;
ahọ́n ejò olóró ní yóò pa á.
17 Kì yóò rí odò wọ̀n-ọn-nì,
ìṣàn omi, odò tí ń ṣàn fún oyin àti ti òrí-àmọ́.
18 Ohun tí ó ṣiṣẹ́ fún ni yóò mú un padà, kí yóò sì gbé e mì;
gẹ́gẹ́ bí ọrọ̀ tí ó ní, kì yóò sì ìgbádùn nínú rẹ̀.
19 Nítorí tí ó fi owó rẹ̀ ni tálákà lára, ó sì ti kẹ́hìndà wọ́n;
Nítorí ti ó fi agbára gbé ilé tí òun kò kọ́.
20 “Nítorí òun kò mọ̀ ìwà pẹ̀lẹ́ nínú ara rẹ̀,
kì yóò sì gbà nínú èyí tí ọkàn rẹ̀ fẹ́ sílẹ̀.
21 Ohun kan kò kù fún jíjẹ́ rẹ̀;
Nítorí náà ọ̀rọ̀ rẹ̀ kì yóò dúró pẹ́.
22 Nínú ànító rẹ̀, ìdààmú yóò dé bá a;
àwọn ènìyàn búburú yóò dáwọ́jọ lé e lórí.
23 Yóò sì ṣe, nígbà tí ó bá fẹ́ jẹun,
Ọlọ́run yóò fà ríru ìbínú rẹ̀ sí í lórí, nígbà tó bá ń jẹun lọ́wọ́,
yóò sì rọ òjò ìbínú rẹ̀ lé e lórí.
24 Bi o tilẹ̀ sá kúrò lọ́wọ́ ohun ìjà ìrìn;
ọrun akọ irin ní yóò ta a po yọ.
25 O fà á yọ, ó sì jáde kúrò lára;
idà dídán ní ń jáde láti inú òróòro wá.
Ẹ̀rù ńlá ń bẹ ní ara rẹ̀;
26 òkùnkùn biribiri ní a ti pamọ́ fún ìṣúra rẹ̀.
Iná ti a kò fẹ́ ní yóò jó o run
yóò sì jẹ èyí tí ó kù nínú àgọ́ rẹ̀ run.
27 Ọ̀run yóò fi ẹ̀ṣẹ̀ rẹ hàn,
ayé yóò sì dìde dúró sí i.
28 Ìbísí ilé rẹ̀ yóò kọjá lọ, àti ohun
ìní rẹ̀ yóò sàn dànù lọ ni ọjọ́ ìbínú Ọlọ́run.
29 Èyí ni ìpín ènìyàn búburú láti ọ̀dọ̀ Ọlọ́run wá,
àti ogún tí a yàn sílẹ̀ fún un láti ọ̀dọ̀ Ọlọ́run.”
Job 20
New King James Version
Zophar’s Sermon on the Wicked Man
20 Then (A)Zophar the Naamathite answered and said:
2 “Therefore my anxious thoughts make me answer,
Because of the turmoil within me.
3 I have heard the rebuke [a]that reproaches me,
And the spirit of my understanding causes me to answer.
4 “Do you not know this of (B)old,
Since man was placed on earth,
5 (C)That the triumphing of the wicked is short,
And the joy of the hypocrite is but for a (D)moment?
6 (E)Though his haughtiness mounts up to the heavens,
And his head reaches to the clouds,
7 Yet he will perish forever like his own refuse;
Those who have seen him will say, ‘Where is he?’
8 He will fly away (F)like a dream, and not be found;
Yes, he (G)will be chased away like a vision of the night.
9 The eye that saw him will see him no more,
Nor will his place behold him anymore.
10 His children will seek the favor of the poor,
And his hands will restore his wealth.
11 His bones are full of (H)his youthful vigor,
(I)But it will lie down with him in the dust.
12 “Though evil is sweet in his mouth,
And he hides it under his tongue,
13 Though he spares it and does not forsake it,
But still keeps it in his [b]mouth,
14 Yet his food in his stomach turns sour;
It becomes cobra venom within him.
15 He swallows down riches
And vomits them up again;
God casts them out of his belly.
16 He will suck the poison of cobras;
The viper’s tongue will slay him.
17 He will not see (J)the streams,
The rivers flowing with honey and cream.
18 He will restore that for which he labored,
And will not swallow it down;
From the proceeds of business
He will get no enjoyment.
19 For he has [c]oppressed and forsaken the poor,
He has violently seized a house which he did not build.
20 “Because(K) he knows no quietness in his [d]heart,
He will not save anything he desires.
21 Nothing is left for him to eat;
Therefore his well-being will not last.
22 In his self-sufficiency he will be in distress;
Every hand of [e]misery will come against him.
23 When he is about to fill his stomach,
God will cast on him the fury of His wrath,
And will rain it on him while he is eating.
24 (L)He will flee from the iron weapon;
A bronze bow will pierce him through.
25 It is drawn, and comes out of the body;
Yes, (M)the glittering point comes out of his [f]gall.
(N)Terrors come upon him;
26 Total darkness is reserved for his treasures.
(O)An unfanned fire will consume him;
It shall go ill with him who is left in his tent.
27 The heavens will reveal his iniquity,
And the earth will rise up against him.
28 The increase of his house will depart,
And his goods will flow away in the day of His (P)wrath.
29 (Q)This is the portion from God for a wicked man,
The heritage appointed to him by God.”
Job 20
New International Version
Zophar
20 Then Zophar the Naamathite(A) replied:
2 “My troubled thoughts prompt me to answer
because I am greatly disturbed.(B)
3 I hear a rebuke(C) that dishonors me,
and my understanding inspires me to reply.
4 “Surely you know how it has been from of old,(D)
ever since mankind[a] was placed on the earth,
5 that the mirth of the wicked(E) is brief,
the joy of the godless(F) lasts but a moment.(G)
6 Though the pride(H) of the godless person reaches to the heavens(I)
and his head touches the clouds,(J)
7 he will perish forever,(K) like his own dung;
those who have seen him will say, ‘Where is he?’(L)
8 Like a dream(M) he flies away,(N) no more to be found,
banished(O) like a vision of the night.(P)
9 The eye that saw him will not see him again;
his place will look on him no more.(Q)
10 His children(R) must make amends to the poor;
his own hands must give back his wealth.(S)
11 The youthful vigor(T) that fills his bones(U)
will lie with him in the dust.(V)
12 “Though evil(W) is sweet in his mouth
and he hides it under his tongue,(X)
13 though he cannot bear to let it go
and lets it linger in his mouth,(Y)
14 yet his food will turn sour in his stomach;(Z)
it will become the venom of serpents(AA) within him.
15 He will spit out the riches(AB) he swallowed;
God will make his stomach vomit(AC) them up.
16 He will suck the poison(AD) of serpents;
the fangs of an adder will kill him.(AE)
17 He will not enjoy the streams,
the rivers(AF) flowing with honey(AG) and cream.(AH)
18 What he toiled for he must give back uneaten;(AI)
he will not enjoy the profit from his trading.(AJ)
19 For he has oppressed the poor(AK) and left them destitute;(AL)
he has seized houses(AM) he did not build.
20 “Surely he will have no respite from his craving;(AN)
he cannot save himself by his treasure.(AO)
21 Nothing is left for him to devour;
his prosperity will not endure.(AP)
22 In the midst of his plenty, distress will overtake him;(AQ)
the full force of misery will come upon him.(AR)
23 When he has filled his belly,(AS)
God will vent his burning anger(AT) against him
and rain down his blows on him.(AU)
24 Though he flees(AV) from an iron weapon,
a bronze-tipped arrow pierces him.(AW)
25 He pulls it out of his back,
the gleaming point out of his liver.
Terrors(AX) will come over him;(AY)
26 total darkness(AZ) lies in wait for his treasures.
A fire(BA) unfanned will consume him(BB)
and devour what is left in his tent.(BC)
27 The heavens will expose his guilt;
the earth will rise up against him.(BD)
28 A flood will carry off his house,(BE)
rushing waters[b] on the day of God’s wrath.(BF)
29 Such is the fate God allots the wicked,
the heritage appointed for them by God.”(BG)
Job 20
English Standard Version
Zophar Speaks: The Wicked Will Suffer
20 Then (A)Zophar the Naamathite answered and said:
2 “Therefore my (B)thoughts answer me,
because of my haste within me.
3 I hear censure that insults me,
and out of my understanding a spirit answers me.
4 Do you not know this from of old,
(C)since man was placed on earth,
5 (D)that the exulting of the wicked is short,
and the joy of the godless but for a moment?
6 (E)Though his height mount up to the heavens,
and his head reach to the clouds,
7 he will perish forever like his own (F)dung;
those who have seen him will say, (G)‘Where is he?’
8 He will fly away like (H)a dream and not be found;
he will be chased away like a vision of the night.
9 (I)The eye that saw him will see him no more,
nor will his place any more behold him.
10 His children will seek the favor of the poor,
and his hands will (J)give back his wealth.
11 His bones are full of his (K)youthful vigor,
but it will lie (L)down with him in the dust.
12 “Though evil is sweet in his mouth,
though he hides it (M)under his tongue,
13 though he is loath to let it go
and holds it in his mouth,
14 yet his food is turned in his stomach;
it is the venom of (N)cobras within him.
15 He swallows down riches and vomits them up again;
God casts them out of his belly.
16 He will suck the poison of cobras;
(O)the tongue of a viper will kill him.
17 He will not look upon (P)the rivers,
the streams flowing with (Q)honey and (R)curds.
18 He will (S)give back the fruit of his toil
and will not (T)swallow it down;
from the profit of his trading
he will get no enjoyment.
19 For he has crushed and abandoned the poor;
he has seized a house that he did not build.
20 “Because he (U)knew no (V)contentment in his belly,
(W)he will not let anything in which he delights escape him.
21 There was nothing left after he had eaten;
therefore his prosperity will not endure.
22 In the fullness of his sufficiency he will be in distress;
the hand of everyone in misery will come against him.
23 To fill his belly to the full,
God[a] will send his burning anger against him
and rain it upon him (X)into his body.
24 (Y)He will flee from an iron weapon;
(Z)a bronze arrow will strike (AA)him through.
25 It (AB)is drawn forth and comes out of his body;
(AC)the glittering point comes out of his (AD)gallbladder;
(AE)terrors come upon him.
26 Utter darkness is laid up for his treasures;
(AF)a fire not fanned will devour him;
what is left in his tent will be consumed.
27 (AG)The heavens will reveal his iniquity,
and the earth will rise up against him.
28 The possessions of his house will be carried away,
dragged off in the day of God's[b] wrath.
29 (AH)This is the wicked man's portion from God,
(AI)the heritage decreed for him by God.”
Copyright: Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní Ẹ̀tọ́ àdàkọ © 2009, 2017 by Biblica, Inc. A lò ó nípa ìgbàyọ̀ǹda láti ọwọ́ Bíbílíkà Inc. Ààbò lórí ẹ̀tọ́ àdàkọ yìí múlẹ̀ jákèjádò àgbáyé. Yoruba Contemporary Bible Copyright © 2009, 2017 by Biblica, Inc.® Used by permission of Biblica, Inc.® All rights reserved worldwide.
Scripture taken from the New King James Version®. Copyright © 1982 by Thomas Nelson. Used by permission. All rights reserved.
Holy Bible, New International Version®, NIV® Copyright ©1973, 1978, 1984, 2011 by Biblica, Inc.® Used by permission. All rights reserved worldwide.
NIV Reverse Interlinear Bible: English to Hebrew and English to Greek. Copyright © 2019 by Zondervan.
The ESV® Bible (The Holy Bible, English Standard Version®), © 2001 by Crossway, a publishing ministry of Good News Publishers. ESV Text Edition: 2025.


