Add parallel Print Page Options

(A)Kí ó tó di pé mo dá ọ láti inú ni mo ti mọ̀ ọ́n,
    kí ó sì tó di pé a bí ọ ni mo ti yà ọ́ sọ́tọ̀.
    Mo yàn ọ́ gẹ́gẹ́ bí wòlíì fún àwọn orílẹ̀-èdè.

Read full chapter

15 (A)Ṣùgbọ́n nígbà tí ó wú Ọlọ́run ẹni tí ó yà mí sọ́tọ̀ láti inú ìyá mi wá, tí ó sì pé mi nípa oore-ọ̀fẹ́ rẹ̀.

Read full chapter