Add parallel Print Page Options

(A)“Àti ní àkókò yìí, kí ni mo ní níbí?” ni Olúwa wí.

“Nítorí a ti kó àwọn ènìyàn mi lọ lọ́fẹ̀ẹ́,
    àwọn tí ó sì ń jẹ ọba lórí wọn fi wọ́n ṣẹlẹ́yà,”
    ni Olúwa wí.
“Àti ní ọjọọjọ́
    orúkọ mi ni asọ̀rọ̀-òdì sí nígbà gbogbo.

Read full chapter