Add parallel Print Page Options

A sọ àsọtẹ́lẹ̀ nípa ìdáǹdè Jerusalẹmu

37 Nígbà tí ọba Hesekiah gbọ́ èyí, ó fa aṣọ rẹ̀ ya, ó sì fi aṣọ ọ̀fọ̀ bo ara rẹ̀, ó sì wọ inú tẹmpili Olúwa lọ. Òun sì rán Eliakimu alákòóso ààfin, Ṣebna akọ̀wé, àti aṣíwájú àwọn àlùfáà, gbogbo wọn nínú aṣọ ọ̀fọ̀ lọ sí ọ̀dọ̀ wòlíì Isaiah ọmọ Amosi. Wọ́n sọ fún un pé, “Báyìí ni Hesekiah wí: ọjọ́ òní jẹ́ ọjọ́ ìbànújẹ́, ìbáwí àti ẹ̀gàn gẹ́gẹ́ bí ìgbà ìbí àwọn ọmọdé tí kò sì ṣí agbára láti bí wọn. Ó lè jẹ́ pé Olúwa Ọlọ́run rẹ yóò gbọ́ ọ̀rọ̀ ọ̀gágun ẹni tí ọ̀gá rẹ̀ ọba Asiria ti rán láti fi Ọlọ́run alààyè ṣe ẹlẹ́yà, àti pé òun ni yóò bá a wí nítorí àwọn ọ̀rọ̀ tí Olúwa Ọlọ́run rẹ ti gbọ́. Nítorí náà gbàdúrà fún àwọn tí ó ṣẹ́kù tí wọ́n sì wà láààyè.”

Nígbà tí àwọn ìjòyè ọba Hesekiah dé ọ̀dọ̀ Isaiah, Isaiah sọ fún wọn pé, “Ẹ sọ fún ọ̀gá yín pé, ‘Ohun tí Olúwa sọ nìyìí: Má ṣe bẹ̀rù ohun tí ẹ ti gbọ́ gbogbo ọ̀rọ̀ tí ọba Asiria tí ó wà nínú ìdè ti fi sọ̀rọ̀-òdì sí mi. Tẹ́tí sílẹ̀! Èmi yóò fi ẹ̀mí kan sínú rẹ̀ tó bẹ́ẹ̀ tí ó fi jẹ́ pé bí o bá ti gbọ́ ìròyìn kan, òun yóò padà sí orílẹ̀-èdè rẹ̀, níbẹ̀ ni n ó sì ti jẹ́ kí wọn ké e lulẹ̀ pẹ̀lú idà.’ ”

Nígbà tí ọ̀gágun gbọ́ pé ọba Asiria ti fi Lakiṣi sílẹ̀, ó padà sẹ́yìn, ó sì bá ọba tí ń bá Libina jà.

Ní àkókò yìí Sennakeribu gbọ́ ìròyìn kan pé Tirakah ará Kuṣi ọba Ejibiti ń jáde bọ̀ wá bá òun jà. Nígbà tí ó gbọ́ èyí, ó rán oníṣẹ́ sí Hesekiah pẹ̀lú ọ̀rọ̀ wọ̀nyí: 10 “Ẹ sọ fún Hesekiah ọba Juda pé: Má ṣe jẹ́ kí òrìṣà tí ìwọ gbẹ́kẹ̀lé tàn ọ́ jẹ nígbà tí ó sọ pé, ‘a kì yóò jọ̀wọ́ Jerusalẹmu fún ọba Asiria.’ 11 Dájúdájú, ìwọ ti gbọ́ ohun tí ọba Asiria ti ṣe sí àwọn orílẹ̀-èdè, tí ó pa wọ́n run pátápátá. Ǹjẹ́ a ó ha dá ọ nídè bí? 12 Ǹjẹ́ àwọn òrìṣà àwọn orílẹ̀-èdè tí àwọn baba ńlá mi parun ha gbà wọ́n sílẹ̀ bí àwọn òrìṣà Gosani, Harani, Reṣefu àti àwọn ènìyàn Edeni tí wọ́n wà ní Teli-Assari? 13 Níbo ni ọba Hamati wà, ọba Arpadi, ọba ìlú Sefarfaimi tàbí Hena tàbí Iffa?”

Àdúrà Hesekiah

14 Hesekiah gba ìwé náà lọ́wọ́ àwọn oníṣẹ́ ó sì kà á. Lẹ́yìn náà ni ó gòkè lọ sí tẹmpili Olúwa ó sì tẹ́ ìwé náà sílẹ̀ níwájú Olúwa. 15 Hesekiah sì gbàdúrà sí Olúwa: 16 Olúwa àwọn ọmọ-ogun, Ọlọ́run Israẹli, tí ó gúnwà láàrín àwọn kérúbù, ìwọ nìkan ni Ọlọ́run lórí i gbogbo ìjọba orílẹ̀ ayé. Ìwọ ti dá ọ̀run àti ayé. 17 Tẹ́tí sílẹ̀, ìwọ Olúwa, kí o gbọ́, ya ojú rẹ, Ìwọ Olúwa, kí o rí i; tẹ́tí sí gbogbo ọ̀rọ̀ tí Sennakeribu rán láti fi àbùkù kan Ọlọ́run alààyè.

18 “Òtítọ́ ni Olúwa pé àwọn ọba Asiria ti sọ àwọn ènìyàn àti ilẹ̀ wọn di asán. 19 Wọ́n ti da àwọn òrìṣà wọn sínú iná wọ́n sì ti pa wọ́n run, nítorí àwọn wọ̀nyí kì í ṣe ọlọ́run bí kò ṣe igi àti òkúta lásán, tí a ti ọwọ́ ènìyàn ṣe. 20 Nísinsin yìí, ìwọ Olúwa, Ọlọ́run wa, gbà wá lọ́wọ́ rẹ̀, tí ó fi jẹ́ pé gbogbo ìjọba ilẹ̀ ayé yóò fi mọ̀ pé Ìwọ, Ìwọ nìkan, Olúwa ni Ọlọ́run.”

Ìṣubú Sennakeribu

21 Lẹ́yìn náà Isaiah ọmọ Amosi rán iṣẹ́ kan sí Hesekiah: “Èyí ni ohun tí Olúwa, Ọlọ́run Israẹli sọ pé: Nítorí pé ìwọ ti gbàdúrà sí mi nípa Sennakeribu ọba Asiria, 22 èyí ni ọ̀rọ̀ tí Olúwa ti sọ nípa rẹ̀:

“Wúńdíá ọmọbìnrin Sioni
    ti kẹ́gàn rẹ, ó sì ti fi ọ ṣe ẹlẹ́yà.
Ọmọbìnrin Jerusalẹmu
    ti mi orí rẹ̀ bí ó ti ń sálọ.
23 Ta ni ìwọ ti bú tí ìwọ sì ti sọ̀rọ̀-òdì sí?
    Sí ta ní ìwọ ti gbé ohùn rẹ sókè
tí o sì gbé ojú rẹ sókè ní ìgbéraga?
    Sí Ẹni Mímọ́ Israẹli!
24 Nípa àwọn ìránṣẹ́ rẹ
    Ìwọ ti sọ̀rọ̀ búburú sí Olúwa.
Tì wọ sì wí pé,
    ‘Pẹ̀lú ọ̀pọ̀ kẹ̀kẹ́ mi
ni èmi sì fi dé orí àwọn òkè ńlá,
    sí ibi gíga jùlọ Lebanoni.
Èmi a sì ké igi kedari gíga rẹ̀ lulẹ̀,
    àti ààyò igi firi rẹ̀.
Èmi ti dé ibi rẹ̀ tí ó ga jùlọ,
    igbó rẹ̀ tí ó dára jùlọ.
25 Èmi ti gbẹ́ kànga ní ilẹ̀ àjèjì
    mo sì mu omi ní ibẹ̀,
pẹ̀lú àtẹ́lẹsẹ̀ mi
    Èmi ti gbẹ́ gbogbo omi àwọn odò Ejibiti.’

26 “Ṣé o kò tí ì gbọ́?
    Tipẹ́tipẹ́ ni mo ti fìdí rẹ̀ mulẹ̀.
Láti ìgbà pípẹ́ ni mo ti ṣètò rẹ̀;
    ní àkókò yìí ni mo mú wá sí ìmúṣẹ,
pé o ti sọ àwọn ìlú olódi di
    àkójọpọ̀ àwọn òkúta
27 Àwọn ènìyàn, tí agbára ti wọ̀ lẹ́wù,
    ni wọ́n banújẹ́ tí a sì dójútì.
Wọ́n dàbí ohun ọ̀gbìn nínú pápá,
    gẹ́gẹ́ bí ọ̀jẹ̀lẹ̀ èhíhù tuntun,
gẹ́gẹ́ bí i koríko tí ó ń hù lórí òrùlé,
    tí ó jóná kí ó tó dàgbàsókè.

28 “Ṣùgbọ́n mo mọ ibi tí o wà
    àti ìgbà tí o wá tí o sì lọ
    àti bí inú rẹ ṣe ru sí mi.
29 Nítorí pé inú rẹ ru sí mi
    àti nítorí pé orí kunkun rẹ ti
dé etí ìgbọ́ mi,
    Èmi yóò fi ìwọ̀ mi sí ọ ní imú,
àti ìjẹ mi sí ọ lẹ́nu,
    èmi yóò sì jẹ́ kí o padà
    láti ọ̀nà tí o gbà wá.

30 “Èyí ni yóò ṣe ààmì fún ọ Ìwọ Hesekiah:

“Ní ọdún yìí, ìwọ yóò jẹ ohun tí ó hù fúnrarẹ̀,
    àti ní ọdún kejì ohun tí ó jáde láti ara rẹ.
Ṣùgbọ́n ní ọdún kẹta, ẹ gbìn kí ẹ sì kórè,
    ẹ gbin ọgbà àjàrà kí ẹ sì jẹ èso wọn.
31 Lẹ́ẹ̀kan sí i, àṣẹ́kù láti ilé Juda
    yóò ta gbòǹgbò nísàlẹ̀ yóò sì ṣo èso lókè.
32 Nítorí láti Jerusalẹmu ni àwọn àṣẹ́kù yóò ti wá,
    àti láti òkè Sioni ni ikọ̀ àwọn tí ó sálà.
    Ìtara Olúwa àwọn ọmọ-ogun ni yóò mú èyí ṣẹ.

33 “Nítorí náà, èyí ni ohun tí Olúwa wí nípa ọba Asiria:

“Òun kì yóò wọ ìlú yìí wá
    tàbí ta ẹyọ ọfà kan níhìn-ín
Òun kì yóò wá síwájú rẹ pẹ̀lú asà
    tàbí kí ó kó dágunró sílẹ̀ fún un.
34 Nípa ọ̀nà tí ó gbà wá náà ni yóò padà lọ;
    òun kì yóò wọ inú ìlú yìí,”
    ni Olúwa wí.
35 “Èmi yóò dáàbò bo ìlú yìí èmi ó sì gbà á là,
    nítorí mi àti nítorí Dafidi ìránṣẹ́ mi!”

36 Lẹ́yìn náà ni angẹli Olúwa jáde lọ ó sì pa ọ̀kẹ́ mẹ́sàn-án ó lé ẹgbẹ̀ẹ́dọ́gbọ̀n ènìyàn ní i ibùdó àwọn Asiria. Nígbà tí àwọn ènìyàn yìí jí ní òwúrọ̀ ọjọ́ kejì gbogbo wọn ti dòkú! 37 Nítorí náà Sennakeribu ọba Asiria fọ́ bùdó ó sì pẹsẹ̀dà. Òun sì padà sí Ninefe, ó sì dúró síbẹ̀.

38 Ní ọjọ́ kan, bí ó ti ń jọ́sìn nínú tẹmpili Nisroki òrìṣà rẹ̀, àwọn ọmọ rẹ̀ Adrameleki àti Ṣareseri gé e lulẹ̀ pẹ̀lú idà, wọ́n sì sálọ sí ilẹ̀ Ararati. Bẹ́ẹ̀ ni Esarhadoni ọmọ rẹ̀ sì gba ipò rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí ọba.

37 And it came to pass, when king Hezekiah heard it, that he rent his clothes, and covered himself with sackcloth, and went into the house of the Lord.

And he sent Eliakim, who was over the household, and Shebna the scribe, and the elders of the priests covered with sackcloth, unto Isaiah the prophet the son of Amoz.

And they said unto him, Thus saith Hezekiah, This day is a day of trouble, and of rebuke, and of blasphemy: for the children are come to the birth, and there is not strength to bring forth.

It may be the Lord thy God will hear the words of Rabshakeh, whom the king of Assyria his master hath sent to reproach the living God, and will reprove the words which the Lord thy God hath heard: wherefore lift up thy prayer for the remnant that is left.

So the servants of king Hezekiah came to Isaiah.

And Isaiah said unto them, Thus shall ye say unto your master, Thus saith the Lord, Be not afraid of the words that thou hast heard, wherewith the servants of the king of Assyria have blasphemed me.

Behold, I will send a blast upon him, and he shall hear a rumour, and return to his own land; and I will cause him to fall by the sword in his own land.

So Rabshakeh returned, and found the king of Assyria warring against Libnah: for he had heard that he was departed from Lachish.

And he heard say concerning Tirhakah king of Ethiopia, He is come forth to make war with thee. And when he heard it, he sent messengers to Hezekiah, saying,

10 Thus shall ye speak to Hezekiah king of Judah, saying, Let not thy God, in whom thou trustest, deceive thee, saying, Jerusalem shall not be given into the hand of the king of Assyria.

11 Behold, thou hast heard what the kings of Assyria have done to all lands by destroying them utterly; and shalt thou be delivered?

12 Have the gods of the nations delivered them which my fathers have destroyed, as Gozan, and Haran, and Rezeph, and the children of Eden which were in Telassar?

13 Where is the king of Hamath, and the king of Arphad, and the king of the city of Sepharvaim, Hena, and Ivah?

14 And Hezekiah received the letter from the hand of the messengers, and read it: and Hezekiah went up unto the house of the Lord, and spread it before the Lord.

15 And Hezekiah prayed unto the Lord, saying,

16 O Lord of hosts, God of Israel, that dwellest between the cherubims, thou art the God, even thou alone, of all the kingdoms of the earth: thou hast made heaven and earth.

17 Incline thine ear, O Lord, and hear; open thine eyes, O Lord, and see: and hear all the words of Sennacherib, which hath sent to reproach the living God.

18 Of a truth, Lord, the kings of Assyria have laid waste all the nations, and their countries,

19 And have cast their gods into the fire: for they were no gods, but the work of men's hands, wood and stone: therefore they have destroyed them.

20 Now therefore, O Lord our God, save us from his hand, that all the kingdoms of the earth may know that thou art the Lord, even thou only.

21 Then Isaiah the son of Amoz sent unto Hezekiah, saying, Thus saith the Lord God of Israel, Whereas thou hast prayed to me against Sennacherib king of Assyria:

22 This is the word which the Lord hath spoken concerning him; The virgin, the daughter of Zion, hath despised thee, and laughed thee to scorn; the daughter of Jerusalem hath shaken her head at thee.

23 Whom hast thou reproached and blasphemed? and against whom hast thou exalted thy voice, and lifted up thine eyes on high? even against the Holy One of Israel.

24 By thy servants hast thou reproached the Lord, and hast said, By the multitude of my chariots am I come up to the height of the mountains, to the sides of Lebanon; and I will cut down the tall cedars thereof, and the choice fir trees thereof: and I will enter into the height of his border, and the forest of his Carmel.

25 I have digged, and drunk water; and with the sole of my feet have I dried up all the rivers of the besieged places.

26 Hast thou not heard long ago, how I have done it; and of ancient times, that I have formed it? now have I brought it to pass, that thou shouldest be to lay waste defenced cities into ruinous heaps.

27 Therefore their inhabitants were of small power, they were dismayed and confounded: they were as the grass of the field, and as the green herb, as the grass on the housetops, and as corn blasted before it be grown up.

28 But I know thy abode, and thy going out, and thy coming in, and thy rage against me.

29 Because thy rage against me, and thy tumult, is come up into mine ears, therefore will I put my hook in thy nose, and my bridle in thy lips, and I will turn thee back by the way by which thou camest.

30 And this shall be a sign unto thee, Ye shall eat this year such as groweth of itself; and the second year that which springeth of the same: and in the third year sow ye, and reap, and plant vineyards, and eat the fruit thereof.

31 And the remnant that is escaped of the house of Judah shall again take root downward, and bear fruit upward:

32 For out of Jerusalem shall go forth a remnant, and they that escape out of mount Zion: the zeal of the Lord of hosts shall do this.

33 Therefore thus saith the Lord concerning the king of Assyria, He shall not come into this city, nor shoot an arrow there, nor come before it with shields, nor cast a bank against it.

34 By the way that he came, by the same shall he return, and shall not come into this city, saith the Lord.

35 For I will defend this city to save it for mine own sake, and for my servant David's sake.

36 Then the angel of the Lord went forth, and smote in the camp of the Assyrians a hundred and fourscore and five thousand: and when they arose early in the morning, behold, they were all dead corpses.

37 So Sennacherib king of Assyria departed, and went and returned, and dwelt at Nineveh.

38 And it came to pass, as he was worshipping in the house of Nisroch his god, that Adrammelech and Sharezer his sons smote him with the sword; and they escaped into the land of Armenia: and Esarhaddon his son reigned in his stead.

Isaiah Assures Deliverance(A)

37 And (B)so it was, when King Hezekiah heard it, that he tore his clothes, covered himself with sackcloth, and went into the house of the Lord. Then he sent Eliakim, who was over the household, Shebna the scribe, and the elders of the priests, covered with sackcloth, to Isaiah the prophet, the son of Amoz. And they said to him, “Thus says Hezekiah: ‘This day is a day of (C)trouble and rebuke and [a]blasphemy; for the children have come to birth, but there is no strength to bring them forth. It may be that the Lord your God will hear the words of the Rabshakeh, whom his master the king of Assyria has sent to (D)reproach the living God, and will rebuke the words which the Lord your God has heard. Therefore lift up your prayer for the remnant that is left.’ ”

So the servants of King Hezekiah came to Isaiah. And Isaiah said to them, “Thus you shall say to your master, ‘Thus says the Lord: “Do not be afraid of the words which you have heard, with which the servants of the king of Assyria have blasphemed Me. Surely I will send a spirit upon him, and he shall hear a rumor and return to his own land; and I will cause him to fall by the sword in his own land.” ’ ”

Sennacherib’s Threat and Hezekiah’s Prayer(E)

Then the Rabshakeh returned, and found the king of Assyria warring against Libnah, for he heard that he had departed from Lachish. And the king heard concerning Tirhakah king of Ethiopia, “He has come out to make war with you.” So when he heard it, he sent messengers to Hezekiah, saying, 10 “Thus you shall speak to Hezekiah king of Judah, saying: ‘Do not let your God in whom you trust deceive you, saying, “Jerusalem shall not be given into the hand of the king of Assyria.” 11 Look! You have heard what the kings of Assyria have done to all lands by utterly destroying them; and shall you be delivered? 12 Have the (F)gods of the nations delivered those whom my fathers have destroyed, Gozan and Haran and Rezeph, and the people of Eden who were in Telassar? 13 Where is the king of (G)Hamath, the king of Arpad, and the king of the city of Sepharvaim, Hena, and Ivah?’ ”

14 And Hezekiah received the letter from the hand of the messengers, and read it; and Hezekiah went up to the house of the Lord, and spread it before the Lord. 15 Then Hezekiah prayed to the Lord, saying: 16 “O Lord of hosts, God of Israel, the One who dwells between the cherubim, You are God, You (H)alone, of all the kingdoms of the earth. You have made heaven and earth. 17 (I)Incline Your ear, O Lord, and hear; open Your eyes, O Lord, and see; and (J)hear all the words of Sennacherib, which he has sent to reproach the living God. 18 Truly, Lord, the kings of Assyria have laid waste all the nations and their (K)lands, 19 and have cast their gods into the fire; for they were (L)not gods, but the work of men’s hands—wood and stone. Therefore they destroyed them. 20 Now therefore, O Lord our God, (M)save us from his hand, that all the kingdoms of the earth may (N)know that You are the Lord, You alone.”

The Word of the Lord Concerning Sennacherib(O)

21 Then Isaiah the son of Amoz sent to Hezekiah, saying, “Thus says the Lord God of Israel, ‘Because you have prayed to Me against Sennacherib king of Assyria, 22 this is the word which the Lord has spoken concerning him:

“The virgin, the daughter of Zion,
Has despised you, laughed you to scorn;
The daughter of Jerusalem
Has shaken her head behind your back!

23 “Whom have you reproached and blasphemed?
Against whom have you raised your voice,
And lifted up your eyes on high?
Against the Holy One of Israel.
24 By your servants you have reproached the Lord,
And said, ‘By the multitude of my chariots
I have come up to the height of the mountains,
To the limits of Lebanon;
I will cut down its tall cedars
And its choice cypress trees;
I will enter its farthest height,
To its fruitful forest.
25 I have dug and drunk water,
And with the soles of my feet I have dried up
All the brooks of [b]defense.’

26 “Did you not hear (P)long ago
How I made it,
From ancient times that I formed it?
Now I have brought it to pass,
That you should be
For crushing fortified cities into heaps of ruins.
27 Therefore their inhabitants had little power;
They were dismayed and confounded;
They were as the grass of the field
And the green herb,
As the grass on the housetops
And grain blighted before it is grown.

28 “But I know your dwelling place,
Your going out and your coming in,
And your rage against Me.
29 Because your rage against Me and your tumult
Have come up to My ears,
Therefore (Q)I will put My hook in your nose
And My bridle in your lips,
And I will (R)turn you back
By the way which you came.” ’

30 “This shall be a sign to you:

You shall eat this year such as grows of itself,
And the second year what springs from the same;
Also in the third year sow and reap,
Plant vineyards and eat the fruit of them.
31 And the remnant who have escaped of the house of Judah
Shall again take root downward,
And bear fruit upward.
32 For out of Jerusalem shall go a remnant,
And those who escape from Mount Zion.
The (S)zeal of the Lord of hosts will do this.

33 “Therefore thus says the Lord concerning the king of Assyria:

‘He shall not come into this city,
Nor shoot an arrow there,
Nor come before it with shield,
Nor build a siege mound against it.
34 By the way that he came,
By the same shall he return;
And he shall not come into this city,’
Says the Lord.
35 ‘For I will (T)defend this city, to save it
For My own sake and for My servant (U)David’s sake.’ ”

Sennacherib’s Defeat and Death(V)

36 Then the (W)angel[c] of the Lord went out, and [d]killed in the camp of the Assyrians one hundred and eighty-five thousand; and when people arose early in the morning, there were the corpses—all dead. 37 So Sennacherib king of Assyria departed and went away, returned home, and remained at Nineveh. 38 Now it came to pass, as he was worshiping in the house of Nisroch his god, that his sons Adrammelech and Sharezer struck him down with the sword; and they escaped into the land of Ararat. Then (X)Esarhaddon his son reigned in his place.

Footnotes

  1. Isaiah 37:3 contempt
  2. Isaiah 37:25 Or perhaps Egypt
  3. Isaiah 37:36 Or Angel
  4. Isaiah 37:36 Lit. struck

Hezekiah Seeks Isaiah's Help

37 (A)As soon as King Hezekiah heard it, he tore his clothes and covered himself with sackcloth and went into the house of the Lord. And he sent Eliakim, who was over the household, and Shebna the secretary, and the senior priests, covered with sackcloth, to the prophet (B)Isaiah the son of Amoz. They said to him, “Thus says Hezekiah, ‘This day is a (C)day of distress, of rebuke, and of disgrace; (D)children have come to the point of birth, and there is no strength to bring them forth. (E)It may be that the Lord your God will hear the words of the Rabshakeh, whom his master the king of Assyria has sent to mock the living God, and will rebuke the words that the Lord your God has heard; therefore lift up your prayer for (F)the remnant that is left.’”

When the servants of King Hezekiah came to Isaiah, Isaiah said to them, “Say to your master, ‘Thus says the Lord: Do not be afraid because of the words that you have heard, with which the young men of the king of Assyria have reviled me. Behold, (G)I will put a spirit in him, so that (H)he shall hear a rumor and return to his own land, and (I)I will make him fall by the sword in his own land.’”

The Rabshakeh returned, and found the king of Assyria fighting against (J)Libnah, for he had heard that the king had left (K)Lachish. Now the king heard concerning Tirhakah king of (L)Cush,[a] “He has set out to fight against you.” And when he heard it, he sent messengers to Hezekiah, saying, 10 “Thus shall you speak to Hezekiah king of Judah: (M)‘Do not let your God in whom you trust deceive you by promising that Jerusalem will not be given into the hand of the king of Assyria. 11 Behold, you have heard what the kings of Assyria have done to all lands, devoting them to destruction. And shall you be delivered? 12 (N)Have the gods of the nations delivered them, the nations that my fathers destroyed, (O)Gozan, (P)Haran, Rezeph, and the people of Eden who were in Telassar? 13 (Q)Where is the king of Hamath, the king of Arpad, the king of the city of Sepharvaim, the king of Hena, or the king of Ivvah?’”

Hezekiah's Prayer for Deliverance

14 Hezekiah received the letter from the hand of the messengers, and read it; and Hezekiah went up to the house of the Lord, and spread it before the Lord. 15 And Hezekiah prayed to the Lord: 16 “O Lord of hosts, God of Israel, (R)enthroned above the cherubim, you are the God, you alone, of all the kingdoms of the earth; (S)you have made the heavens and the earth. 17 (T)Incline your ear, O Lord, and hear; open your eyes, O Lord, and see; and hear (U)all the words of Sennacherib, which he has sent to mock the living God. 18 Truly, O Lord, (V)the kings of Assyria have laid waste all the nations and their lands, 19 and have cast their gods into the fire. For they were no gods, but the work of men's hands, wood and stone. Therefore they were destroyed. 20 So now, O Lord our God, save us from his hand, that all the kingdoms of the earth may know that you alone are the Lord.”

Sennacherib's Fall

21 Then Isaiah the son of Amoz sent to Hezekiah, saying, “Thus says the Lord, the God of Israel: Because you have prayed to me concerning Sennacherib king of Assyria, 22 this is the word that the Lord has spoken concerning him:

“‘She despises you, she scorns you—
    (W)the virgin daughter of Zion;
she wags her head behind you—
    the daughter of Jerusalem.

23 “‘Whom have you mocked and reviled?
    Against whom have you raised your voice
and lifted your eyes to the heights?
    Against (X)the Holy One of Israel!
24 By your servants you have mocked the Lord,
    and you have said, (Y)With my many chariots
I have gone up the heights of the mountains,
    to the far recesses of Lebanon,
(Z)to cut down its tallest cedars,
    its choicest cypresses,
to come to its remotest height,
    its most fruitful forest.
25 I dug wells
    and drank waters,
to dry up with the sole of my foot
    all (AA)the streams (AB)of Egypt.

26 (AC)“‘Have you not heard
    that I determined it long ago?
I planned from days of old
    what now I bring to pass,
that you should make fortified cities
    crash into heaps of ruins,
27 while their inhabitants, shorn of strength,
    are dismayed and confounded,
and have become like plants of the field
    and like tender grass,
like grass on the housetops,
    blighted[b] before it is grown.

28 “‘I know your sitting down
    and your going out and coming in,
    and your raging against me.
29 (AD)Because you have raged against me
    and your complacency has come to my ears,
I will put my hook in your nose
    and my bit in your mouth,
and (AE)I will turn you back on the way
    by which you came.’

30 “And this shall be the sign for you: this year you shall eat what grows of itself, and in the second year what springs from that. Then in the third year sow and reap, and plant vineyards, and eat their fruit. 31 And the surviving remnant of the house of Judah (AF)shall again take root downward and bear fruit upward. 32 (AG)For out of Jerusalem shall go a remnant, and out of Mount Zion a band of survivors. (AH)The zeal of the Lord of hosts will do this.

33 “Therefore thus says the Lord concerning the king of Assyria: He shall not come into this city or shoot an arrow there or come before it with a shield or (AI)cast up a siege mound against it. 34 By the way that he came, by the same he shall return, and he shall not come into this city, declares the Lord. 35 (AJ)For I will defend this city to save it, for my own sake and for (AK)the sake of my servant David.”

36 (AL)And the angel of the Lord went out and struck down 185,000 in the camp of the Assyrians. And when people arose early in the morning, behold, these were all dead bodies. 37 Then Sennacherib king of Assyria departed and returned home and lived at (AM)Nineveh. 38 And as he was worshiping in the house of Nisroch his god, Adrammelech and Sharezer, his sons, struck him down with the sword. And after they escaped into the land of (AN)Ararat, (AO)Esarhaddon his son reigned in his place.

Footnotes

  1. Isaiah 37:9 Probably Nubia
  2. Isaiah 37:27 Some Hebrew manuscripts and 2 Kings 19:26; most Hebrew manuscripts a field