Add parallel Print Page Options

11 (A)Lẹ́yìn náà ni àwọn ènìyàn rẹ̀ rántí ọjọ́ ìgbà n nì,
    àwọn ọjọ́ Mose àti àwọn ènìyàn rẹ̀
níbo ni ẹni náà wà tí ó mú wọn la Òkun já,
    pẹ̀lú olùṣọ́-àgùntàn agbo ẹran rẹ̀?
Níbo ni ẹni náà wà tí ó rán
    Ẹ̀mí Mímọ́ rẹ̀ sáàrín wọn,

Read full chapter

11 Then his people recalled[a] the days of old,
    the days of Moses and his people—
where is he who brought them through the sea,(A)
    with the shepherd of his flock?(B)
Where is he who set
    his Holy Spirit(C) among them,

Read full chapter

Footnotes

  1. Isaiah 63:11 Or But may he recall

11 Ní tìrẹ, nítorí ẹ̀jẹ̀ májẹ̀mú mi pẹ̀lú rẹ,
    Èmi ó dá àwọn ìgbèkùn rẹ̀ sílẹ̀ kúrò nínú ọ̀gbun.

Read full chapter

11 As for you, because of the blood of my covenant(A) with you,
    I will free your prisoners(B) from the waterless pit.(C)

Read full chapter

(A)Tẹ́tí sílẹ̀ kí o sì wá sọ́dọ̀ mi
    gbọ́ tèmi, kí ọkàn rẹ lè wà láààyè.
Èmi yóò dá májẹ̀mú ayérayé pẹ̀lú rẹ,
    ìfẹ́ òtítọ́ tí mo ṣèlérí fún Dafidi.

Read full chapter

Give ear and come to me;
    listen,(A) that you may live.(B)
I will make an everlasting covenant(C) with you,
    my faithful love(D) promised to David.(E)

Read full chapter

26 (A)Èmi yóò dá májẹ̀mú àlàáfíà pẹ̀lú wọn, yóò sì jẹ́ májẹ̀mú títí ayérayé. Èmi yóò gbé wọn kalẹ̀, èmi yóò sì sọ wọ́n di púpọ̀ ní iye, èmi yóò sì gbé ilé mímọ́ mi kalẹ̀ ní àárín wọn títí láé.

Read full chapter

26 I will make a covenant of peace(A) with them; it will be an everlasting covenant.(B) I will establish them and increase their numbers,(C) and I will put my sanctuary among them(D) forever.(E)

Read full chapter