Add parallel Print Page Options

Olúwa ni, kì í ṣe ère òrìṣà

(A)“Ohun tí Olúwa wí nìyìí
    ọba Israẹli àti Olùdáǹdè, àní
Olúwa àwọn ọmọ-ogun:
    Èmi ni ẹni àkọ́kọ́ àti ẹni ìgbẹ̀yìn,
    lẹ́yìn mi kò sí Ọlọ́run kan.

Read full chapter

17 (A)Nígbà tí mo rí i, mo wólẹ̀ ní ẹsẹ̀ rẹ̀ bí ẹni tí ó kú. Ó sì fi ọwọ́ ọ̀tún rẹ̀ lé mi, ó ń wí fún mi pé, “Má ṣe bẹ̀rù. Èmi ni ẹni ìṣáájú àti ẹni ìkẹyìn.

Read full chapter

Sí Ìjọ ní Smirna

(A)“Àti sí angẹli ìjọ ní Smirna kọ̀wé:

Nǹkan wọ̀nyí ni ẹni tí í ṣe ẹni ìṣáájú àti ẹni ìkẹyìn wí, ẹni tí ó ti kú, tí ó sì tún yè:

Read full chapter

13 (A)Èmi ni Alfa àti Omega, ẹni ìṣáájú àti ẹni ìkẹyìn, ìpilẹ̀ṣẹ̀ àti òpin.

Read full chapter