Add parallel Print Page Options

(A)“Èmi, Olúwa, ti pè ọ́ ní òdodo;
    Èmi yóò di ọwọ́ rẹ mú.
Èmi yóò pa ọ́ mọ́, n ó sì ṣe ọ́
    láti jẹ́ májẹ̀mú fún àwọn ènìyàn
    àti ìmọ́lẹ̀ fún àwọn aláìkọlà

Read full chapter

32 (A)ìmọ́lẹ̀ láti mọ́ sí àwọn aláìkọlà,
    àti ògo Israẹli ènìyàn rẹ̀.”

Read full chapter

47 (A)Bẹ́ẹ̀ ni Olúwa ṣa ti pàṣẹ fún wa pé:

“ ‘Mo ti gbé ọ kalẹ̀ láti tan ìmọ́lẹ̀ fún àwọn aláìkọlà,
    kí ìwọ lè mú ìgbàlà wá títí dé òpin ayé.’ ”

Read full chapter

23 Pé, Kristi yóò jìyà, àti pé òun ni yóò jẹ́ ẹni àkọ́kọ́ láti jíǹde kúrò nínú òkú, òun ni yóò sí kéde ìmọ́lẹ̀ fún àwọn ènìyàn àti fún àwọn aláìgbàgbọ́.”

Read full chapter