Add parallel Print Page Options

10 (A)Wò ó, Olúwa Olódùmarè náà ń bọ̀ wá pẹ̀lú agbára,
    apá rẹ̀ sì ń jẹ ọba fún un.
Wò ó, èrè rẹ̀ sì wà pẹ̀lú rẹ̀,
    àti ìdápadà rẹ̀ tí ń bá a bọ̀ wá.

Read full chapter

10 (A)“Èmi Olúwa ń wo ọkàn àti èrò
    inú ọmọ ènìyàn láti san èrè
iṣẹ́ rẹ̀ fún un, gẹ́gẹ́ bí ọ̀nà rẹ̀
    àti gẹ́gẹ́ bí iṣẹ́ ọwọ́ rẹ̀.”

Read full chapter