Hosea 7
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
7 nígbà tí èmi ìbá mú Israẹli láradá.
Ẹ̀ṣẹ̀ Efraimu ń farahàn
ìwà búburú Samaria sì ń hàn síta.
Wọ́n ń ṣe ẹ̀tàn,
àwọn olè ń fọ́ ilé;
àwọn ọlọ́ṣà ń jalè ní òpópónà;
2 Ṣùgbọ́n wọn kò mọ̀ pé
mo rántí gbogbo ìwà búburú wọn:
Ẹ̀ṣẹ̀ wọn gbé wọn mì pátápátá;
wọ́n wà níwájú mi nígbà gbogbo.
3 “Wọ́n ń mú inú ọba dùn pẹ̀lú ìwà búburú wọn,
àti inú ọmọ-aládé dùn pẹ̀lú irọ́ wọn
4 Alágbèrè ni gbogbo wọn
wọ́n gbóná bí ààrò àkàrà
tí a dáwọ́ kíkoná dúró,
lẹ́yìn ìgbà tí o ti pò ìyẹ̀fun tán, títí ìgbà tí yóò wú.
5 Ní ọjọ́ àjọ̀dún ọba wa
wáìnì mú ara ọmọ-aládé gbóná
ó sì darapọ̀ mọ́ àwọn oníyẹ̀yẹ́.
6 Ọkàn wọn ń gbóná bí i ààrò
wọ́n sì tọ̀ ọ́ lọ pẹ̀lú rìkíṣí,
ìbínú wọn pa lọ́lọ́ ní gbogbo òru
ó sì bú jáde bí ọ̀wọ́-iná ní òwúrọ̀.
7 Gbogbo wọn gbóná bí ààrò
wọ́n pa gbogbo olórí wọn run,
gbogbo ọba wọn si ṣubú
kò sì ṣí ẹnìkan nínú wọn tí ó ké pè mí.
8 “Efraimu ti darapọ̀ mọ́ àwọn ènìyàn náà;
Efraimu jẹ́ àkàrà tí a kò yípadà
9 Àwọn àlejò ti jẹ agbára rẹ̀ run
ṣùgbọ́n kò sì mọ̀,
Ewú ti wà ní orí rẹ̀ káàkiri
bẹ́ẹ̀ ni kò kíyèsi i
10 Ìgbéraga Israẹli ń jẹ́rìí sí i
ṣùgbọ́n pẹ̀lú gbogbo èyí
kò padà sí ọ̀dọ̀ Olúwa
Ọlọ́run, tàbí kí ó wá a.
11 “Efraimu dàbí àdàbà
tó rọrùn láti tànjẹ àti aláìgbọ́n
tó wá ń pé Ejibiti nísinsin yìí
tó sì tún ń padà lọ si Asiria.
12 Nígbà tí wọ́n bá lọ, èmi ó ta àwọ̀n mi sórí wọn
Èmi ó fà wọ́n lulẹ̀ gẹ́gẹ́ bí ẹyẹ ojú ọ̀run
Nígbà tí mo bá gbọ́ pé wọ́n rìn pọ̀
Èmi ó nà wọ́n fún iṣẹ́ búburú ọwọ́ wọn.
13 Ègbé ní fún wọn,
nítorí pé wọ́n ti yà kúrò lọ́dọ̀ mi!
Ìparun wà lórí wọn,
nítorí pé wọ́n ti ṣọ̀tẹ̀ sí mi!
Èmi fẹ́ láti rà wọ́n padà.
Ṣùgbọ́n wọ́n ń parọ́ mọ́ mi
14 Wọn kò kégbe pè mí láti ọkàn wọn,
Ṣùgbọ́n wọ́n ń pohùnréré ẹkún lórí ibùsùn wọn.
Wọ́n kó ara wọn jọ, nítorí ọkà àti wáìnì
ṣùgbọ́n wọ́n yípadà kúrò ní ọ̀dọ̀ mi.
15 Mo kọ́ wọn, mo sì fún wọn ní agbára,
síbẹ̀ wọ́n tún ń dìtẹ̀ mọ́ mi.
16 Wọn kò padà sí ọ̀dọ̀ Ọ̀gá-ògo;
wọ́n dàbí ọfà tí ó ti bàjẹ́
Àwọn aṣíwájú wọn yóò ti ipa idà ṣubú
nítorí ìrunú ahọ́n wọn.
Torí èyí, wọn ó fi wọ́n ṣe
ẹlẹ́yà ní ilẹ̀ Ejibiti.
Hosea 7
New International Version
7 1 whenever I would heal Israel,
the sins of Ephraim are exposed
and the crimes of Samaria revealed.(A)
They practice deceit,(B)
thieves break into houses,(C)
bandits rob in the streets;(D)
2 but they do not realize
that I remember(E) all their evil deeds.(F)
Their sins engulf them;(G)
they are always before me.
3 “They delight the king with their wickedness,
the princes with their lies.(H)
4 They are all adulterers,(I)
burning like an oven
whose fire the baker need not stir
from the kneading of the dough till it rises.
5 On the day of the festival of our king
the princes become inflamed with wine,(J)
and he joins hands with the mockers.(K)
6 Their hearts are like an oven;(L)
they approach him with intrigue.
Their passion smolders all night;
in the morning it blazes like a flaming fire.
7 All of them are hot as an oven;
they devour their rulers.
All their kings fall,(M)
and none of them calls(N) on me.
8 “Ephraim mixes(O) with the nations;
Ephraim is a flat loaf not turned over.
9 Foreigners sap his strength,(P)
but he does not realize it.
His hair is sprinkled with gray,
but he does not notice.
10 Israel’s arrogance testifies against him,(Q)
but despite all this
he does not return(R) to the Lord his God
or search(S) for him.
11 “Ephraim is like a dove,(T)
easily deceived and senseless—
now calling to Egypt,(U)
now turning to Assyria.(V)
12 When they go, I will throw my net(W) over them;
I will pull them down like the birds in the sky.
When I hear them flocking together,
I will catch them.
13 Woe(X) to them,
because they have strayed(Y) from me!
Destruction to them,
because they have rebelled against me!
I long to redeem them
but they speak about me(Z) falsely.(AA)
14 They do not cry out to me from their hearts(AB)
but wail on their beds.
They slash themselves,[a] appealing to their gods
for grain and new wine,(AC)
but they turn away from me.(AD)
15 I trained(AE) them and strengthened their arms,
but they plot evil(AF) against me.
16 They do not turn to the Most High;(AG)
they are like a faulty bow.(AH)
Their leaders will fall by the sword
because of their insolent(AI) words.
For this they will be ridiculed(AJ)
in the land of Egypt.(AK)
Footnotes
- Hosea 7:14 Some Hebrew manuscripts and Septuagint; most Hebrew manuscripts They gather together
Hosea 7
King James Version
7 When I would have healed Israel, then the iniquity of Ephraim was discovered, and the wickedness of Samaria: for they commit falsehood; and the thief cometh in, and the troop of robbers spoileth without.
2 And they consider not in their hearts that I remember all their wickedness: now their own doings have beset them about; they are before my face.
3 They make the king glad with their wickedness, and the princes with their lies.
4 They are all adulterers, as an oven heated by the baker, who ceaseth from raising after he hath kneaded the dough, until it be leavened.
5 In the day of our king the princes have made him sick with bottles of wine; he stretched out his hand with scorners.
6 For they have made ready their heart like an oven, whiles they lie in wait: their baker sleepeth all the night; in the morning it burneth as a flaming fire.
7 They are all hot as an oven, and have devoured their judges; all their kings are fallen: there is none among them that calleth unto me.
8 Ephraim, he hath mixed himself among the people; Ephraim is a cake not turned.
9 Strangers have devoured his strength, and he knoweth it not: yea, gray hairs are here and there upon him, yet he knoweth not.
10 And the pride of Israel testifieth to his face: and they do not return to the Lord their God, nor seek him for all this.
11 Ephraim also is like a silly dove without heart: they call to Egypt, they go to Assyria.
12 When they shall go, I will spread my net upon them; I will bring them down as the fowls of the heaven; I will chastise them, as their congregation hath heard.
13 Woe unto them! for they have fled from me: destruction unto them! because they have transgressed against me: though I have redeemed them, yet they have spoken lies against me.
14 And they have not cried unto me with their heart, when they howled upon their beds: they assemble themselves for corn and wine, and they rebel against me.
15 Though I have bound and strengthened their arms, yet do they imagine mischief against me.
16 They return, but not to the most High: they are like a deceitful bow: their princes shall fall by the sword for the rage of their tongue: this shall be their derision in the land of Egypt.
Hosea 7
English Standard Version
7 (A)when I would heal Israel,
the iniquity of Ephraim is revealed,
and the evil deeds of (B)Samaria,
for (C)they deal falsely;
the thief breaks in,
and the bandits raid outside.
2 But they do not consider
that (D)I remember all their evil.
Now (E)their deeds surround them;
(F)they are before my face.
3 By their evil (G)they make (H)the king glad,
and the princes by their treachery.
4 (I)They are all adulterers;
they are like a heated oven
whose baker ceases to stir the fire,
from the kneading of the dough
until it is leavened.
5 On the day of (J)our king, the princes
became sick with the heat of wine;
he stretched out his hand with mockers.
6 For with hearts like an oven (K)they approach their intrigue;
all night their anger smolders;
in the morning it blazes like a flaming fire.
7 All of them are hot as an oven,
and they devour their rulers.
All (L)their kings (M)have fallen,
and none of them calls upon me.
8 Ephraim (N)mixes himself with the peoples;
Ephraim is a cake not turned.
9 (O)Strangers devour his strength,
and (P)he knows it not;
gray hairs are sprinkled upon him,
and (Q)he knows it not.
10 (R)The pride of Israel testifies to his face;[a]
(S)yet they do not return to the Lord their God,
nor seek him, for all this.
11 Ephraim is like a dove,
(T)silly and without sense,
calling to (U)Egypt, going to (V)Assyria.
12 As they go, (W)I will spread over them my net;
I will bring them down like birds of the heavens;
(X)I will discipline them (Y)according to the report made to their congregation.
13 (Z)Woe to them, for they have strayed from me!
Destruction to them, for they have rebelled against me!
(AA)I would redeem them,
but (AB)they speak lies against me.
14 (AC)They do not cry to me from the heart,
but (AD)they wail upon their beds;
for grain and wine they gash themselves;
they rebel against me.
15 Although (AE)I trained and strengthened their arms,
yet they devise evil against me.
16 They (AF)return, but not upward;[b]
they are (AG)like a treacherous bow;
their princes shall fall by the sword
because of (AH)the insolence of their tongue.
This shall be their derision (AI)in the land of Egypt.
Footnotes
- Hosea 7:10 Or in his presence
- Hosea 7:16 Or to the Most High
Copyright: Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní Ẹ̀tọ́ àdàkọ © 2009, 2017 by Biblica, Inc. A lò ó nípa ìgbàyọ̀ǹda láti ọwọ́ Bíbílíkà Inc. Ààbò lórí ẹ̀tọ́ àdàkọ yìí múlẹ̀ jákèjádò àgbáyé. Yoruba Contemporary Bible Copyright © 2009, 2017 by Biblica, Inc.® Used by permission of Biblica, Inc.® All rights reserved worldwide.
Holy Bible, New International Version®, NIV® Copyright ©1973, 1978, 1984, 2011 by Biblica, Inc.® Used by permission. All rights reserved worldwide.
NIV Reverse Interlinear Bible: English to Hebrew and English to Greek. Copyright © 2019 by Zondervan.
The ESV® Bible (The Holy Bible, English Standard Version®), © 2001 by Crossway, a publishing ministry of Good News Publishers. ESV Text Edition: 2025.

