Add parallel Print Page Options

Ìyè nípa ti ẹ̀mí

16 Ǹjẹ́ mo ní, Ẹ máa rìn nípa ti Ẹ̀mí, ẹ̀yin kì yóò sì mú ìfẹ́kúfẹ̀ẹ́ ti ara ṣẹ. 17 (A)Nítorí ti ara ń ṣe ìfẹ́kúfẹ̀ẹ́ lòdì sí Ẹ̀mí, àti Ẹ̀mí lòdì sí ara: àwọn wọ̀nyí sì lòdì sí ara wọn; kí ẹ má ba à lè ṣe ohun tí ẹ̀yin ń fẹ́.

Read full chapter

16 So I say, walk by the Spirit,(A) and you will not gratify the desires of the flesh.(B) 17 For the flesh desires what is contrary to the Spirit, and the Spirit what is contrary to the flesh.(C) They are in conflict with each other, so that you are not to do whatever[a] you want.(D)

Read full chapter

Footnotes

  1. Galatians 5:17 Or you do not do what