Add parallel Print Page Options

14 (A)Ǹjẹ́ ohunkóhun wà tí ó ṣòro jù fún Olúwa? Èmi ó padà tọ̀ ọ́ wá ní ìwòyí àmọ́dún, Sara yóò sì bí ọmọkùnrin.”

Read full chapter

“Èmi mọ̀ pé, ìwọ lè e ṣe ohun gbogbo,
    àti pé, kò si ìrò inú tí a lè fa sẹ́yìn kúrò lọ́dọ̀ rẹ.

Read full chapter

17 “Háà! Olúwa Olódùmarè, ìwọ tí o dá ọ̀run àti ayé pẹ̀lú títóbi agbára rẹ àti gbogbo ọ̀rọ̀ apá rẹ. Kò sí ohun tí ó ṣòro fún ọ láti ṣe.

Read full chapter

37 (A)Nítorí kò sí ohun tí Ọlọ́run kò le ṣe.”

Read full chapter