Add parallel Print Page Options

(A)Nígbà náà ní ó wí pé, “Èmi ni Ọlọ́run baba rẹ, Ọlọ́run Abrahamu, Ọlọ́run Isaaki àti Ọlọ́run Jakọbu.” Nítorí ìdí èyí, Mose sì pa ojú rẹ̀ mọ́, nítorí ó bẹ̀rù láti bojú wo Ọlọ́run.

Read full chapter

Ìpọ́njú àti ògo ìránṣẹ́ náà

13 Kíyèsi i, ìránṣẹ́ mi yóò hùwà ọlọ́gbọ́n;
    òun ni a ó gbé sókè tí a ó sì gbéga
    a ó sì gbé e lékè gidigidi.

Read full chapter