Add parallel Print Page Options

Onírúurú òfin

22 (A)Bí ọkùnrin kan tí ó jẹ̀bi ẹ̀sùn bá ní láti kú tí ó sì kú, tí a sì gbé òkú rẹ̀ kọ́ sára igi, 23 (B)o kò gbọdọ̀ fi òkú rẹ̀ sílẹ̀ sára igi ní gbogbo òru. Gbìyànjú láti sin ín ní ọjọ́ náà gan an, nítorí ẹni tí a bá gbé kọ́ sórí igi wà lábẹ́ ègún Ọlọ́run. Ìwọ kò gbọdọ̀ ba ilẹ̀ tí Olúwa Ọlọ́run rẹ fún ọ gẹ́gẹ́ bí ogún jẹ́.

Read full chapter

Various Laws

22 If someone guilty of a capital offense(A) is put to death and their body is exposed on a pole, 23 you must not leave the body hanging on the pole overnight.(B) Be sure to bury(C) it that same day, because anyone who is hung on a pole is under God’s curse.(D) You must not desecrate(E) the land the Lord your God is giving you as an inheritance.

Read full chapter