1 Korintierne 9
En Levende Bok
Paulus nekter å ta imot lønn
9 Noen påstår at jeg ikke har de samme rettighetene som de andre utsendingene, og at jeg ikke er en sann utsending av Jesus. Jeg har virkelig med egne øyne sett vår Herre Jesus, og dere er selv resultatet av det arbeidet jeg har utført for ham. 2 Ja, dersom jeg ikke har vært en utsending for Jesus til andre, så har jeg i det minste vært det for dere. At dere tilhører Herren Jesus er jo beviset på at han har sendt meg for å spre budskapet om ham. 3 Derfor vil jeg stille noen spørsmål til dem som kritiserer meg:
4 Har ikke Barnabas og jeg den samme retten som de andre utsendingene til å bo hos dere og spise av maten deres? 5 Har ikke vi den samme retten til å ta med oss en troende kone på reisene våre som de andre utsendingene og Herren Jesu egne brødre og Peter? 6 Er det bare vi som må arbeide for å forsørge oss selv? 7 Dersom noen blir soldat, har han ikke da rett til lønn? Dersom noen planter og bygger en vingård, vil han ikke da spise av druene? Dersom noen vokter en saueflokk, vil han ikke da drikke av melken?
8-9 Eller dere sier kanskje at dette bare er en menneskelig måte å forsvare seg på? Da glemmer dere at disse reglene faktisk kommer fra Gud. I loven han ga til Moses, står det: ”Du skal ikke binde munnen på den oksen som tresker.” Dere tror vel ikke at det bare var oksene Gud tenkte på? 10 Nei, han tenkte naturligvis på oss som arbeider for ham. Reglene om at den som pløyer og den som tresker skal få sin del av avlingen, står fast for å vise at vi som arbeider på Guds åker, skal ha lønn for det vi gjør.
11 Vi har sådd et åndelig budskap i hjertene deres. Er det da for mye forlangt at vi får høste litt av de materielle godene dere rår over? 12 Dere gir jo andre det de trenger når de kommer for å undervise dere. Har ikke vi som først lot dere høre Guds budskap, en enda større rett til det samme? Vi har aldri utnyttet denne retten, men forsøkt å klare oss selv så godt vi kan. Vi ville vise dere at vi har rene motiv, slik at ikke noe skulle hindre dere fra å ta imot det glade budskapet om Jesus Kristus.
13 Dere vet at prestene i Guds tempel får spise av den maten som blir brakt dit som offergave, og at de får spise en viss del av kjøttet fra dyrene de ofret på alteret? 14 På samme måten har Herren Jesus bestemt at de som sprer det glade budskapet om ham, skal bli forsørget av arbeidet sitt. 15 Som sagt har jeg aldri benyttet meg av denne fordelen. Jeg skriver ikke dette for å kreve noe av dere nå heller. Nei, jeg ville heller sulte i hjel enn å ta imot noe fra dere, for jeg er ganske stolt over å spre budskapet uten betaling. 16 At jeg sprer budskapet, er derimot ikke noe jeg vil skryte av. Det er noe jeg ganske enkelt er nødt til å gjøre. Gud ville straffe meg om jeg ikke spredde det glade budskapet om Jesus!
17 Dersom jeg selv hadde bestemt meg for å spre budskapet, da kunne jeg kreve å få lønn av dere. Nå er det et oppdrag fra Gud, og derfor er det min plikt å spre budskapet. 18 Skal jeg slett ikke få noen lønn? Jo, min lønn er å få spre det glade budskapet om Jesus uten kostnad for noen og uten å kreve det jeg egentlig har rett til.
Paulus ønsker å vinne så mange som mulig
19 Jeg er altså fri og uavhengig av alle mennesker. Jeg har likevel gjort meg til slave for alle, for at jeg skal kunne vinne så mange som mulig for Jesus Kristus. 20 Når jeg er sammen med jødene, er jeg som en av dem, for at de skal begynne tro på Kristus. Til tross for at jeg selv ikke lenger er nødt til å følge den jødiske loven, respekterer jeg alle bud i loven når jeg er sammen med jødene, etter som jeg vil vinne dem for Kristus. 21 Når jeg er sammen med folk som ikke er jøder, lever jeg som dem for å vinne dem for Kristus. Dette betyr ikke at jeg ikke følger noen lov fra Gud, for jeg lyder den kjærlighetens lov som Kristus har gitt oss. 22 Når jeg er sammen med dem som ennå har svak tro på Kristus, unngår jeg å utnytte min frihet til å gjøre noe som kan lokke dem til å forlate troen. Jeg gjør alt for å identifisere meg med de menneskene jeg møter, slik at jeg i det minste kan frelse noen. 23 Alt dette gjør jeg for at det glade budskapet om Jesus skal bli spredd til så mange som mulig, og for at jeg selv en dag skal oppnå alt det gode som Gud har lovet dem som tror på Jesus.
24 Tenk på løperne i en stor idrettskonkurranse. Alle kjemper hardt for å vinne gullmedaljen som venter på vinneren, men bare en får førsteplassen. Gjør som disse løperne. Kjemp slik at dere en dag vinner den utmerkelsen som venter den som holder fast ved troen på Jesus. 25 Vær beredt til å avstå fra alt annet. Idrettsutøveren kjemper for å vinne en seierskrans som snart visner og dør. Vi kjemper for å få det evige livets seierskrans. 26 Selv løper jeg ikke hit og dit uten mål, og jeg er ikke lik en bokser som slår i løse luften. 27 Nei, for å vinne seiersprisen tvinger jeg min egen kropp til å bli en slave under Guds vilje. Jeg vil jo ikke spre Guds budskap til andre, og så etterpå selv miste det evige livet.
1 Corinthians 9
New International Version
Paul’s Rights as an Apostle
9 Am I not free?(A) Am I not an apostle?(B) Have I not seen Jesus our Lord?(C) Are you not the result of my work in the Lord?(D) 2 Even though I may not be an apostle to others, surely I am to you! For you are the seal(E) of my apostleship in the Lord.
3 This is my defense to those who sit in judgment on me. 4 Don’t we have the right to food and drink?(F) 5 Don’t we have the right to take a believing wife(G) along with us, as do the other apostles and the Lord’s brothers(H) and Cephas[a]?(I) 6 Or is it only I and Barnabas(J) who lack the right to not work for a living?
7 Who serves as a soldier(K) at his own expense? Who plants a vineyard(L) and does not eat its grapes? Who tends a flock and does not drink the milk? 8 Do I say this merely on human authority? Doesn’t the Law say the same thing? 9 For it is written in the Law of Moses: “Do not muzzle an ox while it is treading out the grain.”[b](M) Is it about oxen that God is concerned?(N) 10 Surely he says this for us, doesn’t he? Yes, this was written for us,(O) because whoever plows and threshes should be able to do so in the hope of sharing in the harvest.(P) 11 If we have sown spiritual seed among you, is it too much if we reap a material harvest from you?(Q) 12 If others have this right of support from you, shouldn’t we have it all the more?
But we did not use this right.(R) On the contrary, we put up with anything rather than hinder(S) the gospel of Christ.
13 Don’t you know that those who serve in the temple get their food from the temple, and that those who serve at the altar share in what is offered on the altar?(T) 14 In the same way, the Lord has commanded that those who preach the gospel should receive their living from the gospel.(U)
15 But I have not used any of these rights.(V) And I am not writing this in the hope that you will do such things for me, for I would rather die than allow anyone to deprive me of this boast.(W) 16 For when I preach the gospel, I cannot boast, since I am compelled to preach.(X) Woe to me if I do not preach the gospel! 17 If I preach voluntarily, I have a reward;(Y) if not voluntarily, I am simply discharging the trust committed to me.(Z) 18 What then is my reward? Just this: that in preaching the gospel I may offer it free of charge,(AA) and so not make full use of my rights(AB) as a preacher of the gospel.
Paul’s Use of His Freedom
19 Though I am free(AC) and belong to no one, I have made myself a slave to everyone,(AD) to win as many as possible.(AE) 20 To the Jews I became like a Jew, to win the Jews.(AF) To those under the law I became like one under the law (though I myself am not under the law),(AG) so as to win those under the law. 21 To those not having the law I became like one not having the law(AH) (though I am not free from God’s law but am under Christ’s law),(AI) so as to win those not having the law. 22 To the weak I became weak, to win the weak.(AJ) I have become all things to all people(AK) so that by all possible means I might save some.(AL) 23 I do all this for the sake of the gospel, that I may share in its blessings.
The Need for Self-Discipline
24 Do you not know that in a race all the runners run, but only one gets the prize?(AM) Run(AN) in such a way as to get the prize. 25 Everyone who competes in the games goes into strict training. They do it to get a crown(AO) that will not last, but we do it to get a crown that will last forever.(AP) 26 Therefore I do not run like someone running aimlessly;(AQ) I do not fight like a boxer beating the air.(AR) 27 No, I strike a blow to my body(AS) and make it my slave so that after I have preached to others, I myself will not be disqualified for the prize.(AT)
Footnotes
- 1 Corinthians 9:5 That is, Peter
- 1 Corinthians 9:9 Deut. 25:4
1 Kọrinti 9
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
Àwọn ẹ̀tọ́ aposteli
9 (A)Èmi kò ha ni òmìnira bí? Èmi kò ha ń ṣe aposteli bí? Èmi kò ha ti rí Jesu Olúwa bí? Ẹ̀yìn ha kọ́ ní èrè iṣẹ́ mi nínú Olúwa bí? 2 Ní ìrònú àwọn ẹlòmíràn, èmi kì í ṣe aposteli. Dájúdájú aposteli ni mo jẹ́ fún un yín, tí n kì bá ṣe fún àwọn ẹlòmíràn. Nítorí èdìdì iṣẹ́ aposteli mi ni ẹ̀yin jẹ́ nínú Olúwa.
3 Èyí ni ìdáhùn mi sí àwọn tí ń béèrè ẹ̀tọ́ aposteli mi. 4 (B)Ṣé a kò ní ẹ̀tọ́ láti máa jẹ àti láti máa mu bí? 5 (C)Ṣé àwa kò ní ẹ̀tọ́ láti máa mú ìyàwó tí í ṣe onígbàgbọ́ káàkiri gẹ́gẹ́ bí àwọn aposteli mìíràn? Àti bí arákùnrin Olúwa, àti Kefa. 6 (D)Ṣé èmi nìkan àti Barnaba, àwa kò ha ní agbára láti máa ṣiṣẹ́ bọ́ ara wa ni?
7 Ta ni ó ṣíṣẹ́ ológun tí ó sanwó ara rẹ̀? Ta ní gbin ọgbà àjàrà tí kì í jẹ nínú èso rẹ̀? Tàbí ta ní ń bọ ọ̀wọ́ ẹran tí kì í sí ì jẹ nínú wàrà ọ̀wọ́ ẹran? 8 Èmi ha sọ nǹkan wọ̀nyí bí ènìyàn? Tàbí òfin kò wí bákan náà bì? 9 (E)Nítorí nínú òfin tí Ọlọ́run fún Mose, ni a tí kọ ọ́ pé, “Ìwọ kò gbọdọ̀ di màlúù ti ń tẹ ọkà lẹ́nu.” Ǹjẹ́ màlúù ni Ọlọ́run n ṣe ìtọ́jú rẹ̀ bi? 10 (F)Dájúdájú ó sọ eléyìí fún wa pé, nítorí wa ni a ṣe kọ̀wé yìí kí ẹni tí ń tulẹ̀ lè máa tulẹ̀ ní ìrètí àti ẹni tí ń pakà lè ni ìrètí láti ní ìpín nínú ìkórè. 11 (G)Bí àwa ti fún irúgbìn ohun ti ẹ̀mí sínú ọkàn yín, ohun ńlá ha ni bí àwa ó ba ká ohun ti yín tí ṣe ti ara? 12 (H)Bí àwọn ẹlòmíràn bá ní ẹ̀tọ́ tí ìrànlọ́wọ́ sì wá láti ọ̀dọ̀ yín, àwa ha kọ́ ni ó tọ́ sí jù?
Ṣùgbọ́n àwa kò lo agbára yìí ṣùgbọ́n àwa faradà ohun gbogbo, kí àwa má ba à ṣe ìdènà fún ìhìnrere Kristi.
13 (I)Ǹjẹ́ ó yé e yín pé Ọlọ́run sọ fún àwọn tí ó ń ṣiṣẹ́ nínú tẹmpili pé kí wọ́n mú oúnjẹ tàbí àwọn ẹ̀bùn tí wọ́n mú wá fún òun, láti fi ṣe ìtọ́jú ara wọn? Àti àwọn tí ń dúró tí pẹpẹ wọn a máa ṣe àjọpín pẹ̀lú pẹpẹ. 14 (J)Gẹ́gẹ́ bẹ́ẹ̀ ni Olúwa ti fi àṣẹ lélẹ̀ pé, àwọn tí ń wàásù ìhìnrere kí wọn sì máa jẹ́ nípa ìhìnrere.
15 (K)Síbẹ̀síbẹ̀ n kò ì tí ì lo irú àwọn ẹ̀tọ́ wọ̀nyí rí. Bẹ́ẹ̀ ni èmi kò sì kọ ìwé yìí láti fi sọ fún un yín pé, mo fẹ́ bẹ̀rẹ̀ sí í gbà irú nǹkan bẹ̀ ẹ́ lọ́wọ́ yín. Kí a sọ òtítọ́, ó sàn fún mi láti kú sínú ebi ju pé kí n sọ ògo tí mo ní láti wàásù nù. 16 Nítorí pé bí mo ti ń wàásù ìhìnrere, kì í ṣe ohun tí mo lè máa ṣògo lè. Èmi kò tilẹ̀ le è ṣe é ní, kí a tilẹ̀ sọ pé mo fẹ́ kọ̀ ọ́ sílẹ̀. Ègbé ni fún mi tí mo bá kọ̀ láti wàásù ìhìnrere. 17 (L)Tó bá jẹ́ pé mò ń wàásù tinútinú mi, mo ní èrè kan, ṣùgbọ́n tí ń kò bá ṣe tinútinú mi, a ti fi iṣẹ́ ìríjú lé mi lọ́wọ́. 18 (M)Ní irú ipò báyìí, kín ni ẹ rò pé yóò jẹ èrè mi ni láti jẹ́? Èrè mi ní àgbàyanu ayọ̀ tí mo ń rí gbà nípa ìwàásù ìhìnrere láìgba owó lọ́wọ́ ẹnikẹ́ni, láìbéèrè ẹ̀tọ́ mi lọ́wọ́ ẹnikẹ́ni.
19 Bí mo ti jẹ́ òmìnira tí ń kò sì darapọ̀ mọ́ ẹnikẹ́ni, mo sọ ara mi di ẹrú lọ́dọ̀ gbogbo ènìyàn, láti lè jèrè ọ̀pọ̀lọpọ̀ sí i. 20 (N)Nígbà tí mó wà lọ́dọ̀ àwọn Júù, mo dàbí ọ̀kan nínú wọn, kí wọn ba à lè tẹ́tí sí ìwàásù ìhìnrere mi àti ki n le jèrè wọn fún Kristi. Nígbà tí mo bá wà láàrín àwọn tó wà lábẹ́ òfin èmi kì í bá wọn jiyàn rárá (bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé èmi kò sí lábẹ́ òfin), kí èmi lè jèrè àwọn ti ń bẹ lábẹ́ òfin. 21 (O)Nígbà tí mo bá wà láàrín àwọn tí kò sí lábẹ́ òfin, èmi náà yóò dàbí ẹni tí kò sí lábẹ́ òfin (èmi kì í ṣe aláìlófin sí Ọlọ́run, ṣùgbọ́n èmí ń bẹ lábẹ́ òfin Kristi), kí èmi le jèrè àwọn tí kò sí lábẹ́ òfin. 22 (P)Nígbà tí mo bá wà láàrín àwọn aláìlera, èmi náà yóò di aláìlera, kí èmi lé jèrè àwọn aláìlera. Mo di ohun gbogbo fún gbogbo ènìyàn, kí èmi ba à lè gba díẹ̀ là lábẹ́ bí ó ti wù kí ó rí. 23 Èmi sì ń ṣe ohun gbogbo nítorí ti ìhìnrere, kí èmi kí ó lè jẹ́ alábápín nínú rẹ̀ pẹ̀lú yín.
24 (Q)Ẹ̀yin kò mọ̀ pé, olúkúlùkù ẹni tí ó ní ipa nínú eré ìje ni ó máa ń sáré, ṣùgbọ́n ẹnìkan ṣoṣo ni ń gba ipò ẹ̀bùn tí ó ga jù. Nítorí náà, ẹ sá eré ìje yín kí ẹ ba à le borí. 25 (R)Gbogbo ẹni tí ó ń sáré ìje a máa lọ nínú ìsẹ́ra-ẹni tí ó lágbára. Wọ́n ń ṣe èyí láti gba adé ìdíbàjẹ́. Ṣùgbọ́n àwa ń sá eré ìje tiwa láti fi gba adé ọ̀run àìdíbàjẹ́ láéláé. 26 Nítorí náà, mo ń sá eré ìje lọ sójú ààmì, kì í ṣe bí ẹni ti kò dá lójú. Mò ń jà kí n lè borí, kì í ṣe bí ẹni tí ń bá afẹ́fẹ́ jà. 27 Ṣùgbọ́n èmi ń kó ara mi ní ìjánu, mo sì ń mú un wá sí abẹ́ ìtẹríba, pé lẹ́yìn tí mo ti wàásù fún àwọn ẹlòmíràn, nítorí ohunkóhun, kí èmi fún rara mi má ṣe di ẹni ìtanù fún ẹ̀bùn náà.
En Levende Bok: Det Nye Testamentet Copyright © 1978, 1988 by Biblica, Inc.®
Used by permission. All rights reserved worldwide.
Holy Bible, New International Version®, NIV® Copyright ©1973, 1978, 1984, 2011 by Biblica, Inc.® Used by permission. All rights reserved worldwide.
NIV Reverse Interlinear Bible: English to Hebrew and English to Greek. Copyright © 2019 by Zondervan.
Copyright: Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní Ẹ̀tọ́ àdàkọ © 2009, 2017 by Biblica, Inc. A lò ó nípa ìgbàyọ̀ǹda láti ọwọ́ Bíbílíkà Inc. Ààbò lórí ẹ̀tọ́ àdàkọ yìí múlẹ̀ jákèjádò àgbáyé. Yoruba Contemporary Bible Copyright © 2009, 2017 by Biblica, Inc.® Used by permission of Biblica, Inc.® All rights reserved worldwide.
