Font Size
1 Kọrinti 2:2
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
1 Kọrinti 2:2
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
2 (A)Èmi ti pinnu láti má mọ ohunkóhun nígbà ti mo wà láàrín yín bí kò ṣe Jesu Kristi, ẹni tí a kàn mọ́ àgbélébùú.
Read full chapter
Galatia 3:1
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
Galatia 3:1
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
Ìgbàgbọ́ tàbí iṣẹ́ òfin
3 Ẹ̀yin aláìnírònú ará Galatia! Ta ní ha tàn yín jẹ, kí ẹ̀yin má ṣe gba òtítọ́ gbọ́? Ní ojú ẹni tí a fi Jesu Kristi hàn gbangba láàrín yín ni ẹni tí a kàn mọ́ àgbélébùú.
Read full chapter
Galatia 5:11
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
Galatia 5:11
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
11 Ṣùgbọ́n, ará, bí èmi bá ń wàásù ìkọlà síbẹ̀, kín ni ìdí tí a fi ń ṣe inúnibíni sí mi síbẹ̀? Ǹjẹ́ ìkọ̀sẹ̀ àgbélébùú ti kúrò.
Read full chapter
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn (BYO)
Copyright: Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní Ẹ̀tọ́ àdàkọ © 2009, 2017 by Biblica, Inc. A lò ó nípa ìgbàyọ̀ǹda láti ọwọ́ Bíbílíkà Inc. Ààbò lórí ẹ̀tọ́ àdàkọ yìí múlẹ̀ jákèjádò àgbáyé. Yoruba Contemporary Bible Copyright © 2009, 2017 by Biblica, Inc.® Used by permission of Biblica, Inc.® All rights reserved worldwide.