Add parallel Print Page Options

16 (A)Bí bẹ́ẹ̀ kọ́, bí ìwọ bá yin Ọlọ́run nípa ẹ̀mí, báwo ni ẹni tí ń bẹ ni ipò òpè yóò ṣe ṣe “Àmín” si ìdúpẹ́ rẹ, nígbà tí kò mọ ohun tí ìwọ wí?

Read full chapter

16 Otherwise when you are praising God in the Spirit, how can someone else, who is now put in the position of an inquirer,[a] say “Amen”(A) to your thanksgiving,(B) since they do not know what you are saying?

Read full chapter

Footnotes

  1. 1 Corinthians 14:16 The Greek word for inquirer is a technical term for someone not fully initiated into a religion; also in verses 23 and 24.

Sí ìjọ Laodikea

14 (A)“Àti sí angẹli ìjọ ní Laodikea kọ̀wé:

Ọ̀rọ̀ wọ̀nyí ni ẹni tí ń jẹ́ Àmín wí, ẹlẹ́rìí olódodo àti olóòtítọ́, olórí ìṣẹ̀dá Ọlọ́run:

Read full chapter

To the Church in Laodicea

14 “To the angel of the church in Laodicea(A) write:

These are the words of the Amen, the faithful and true witness,(B) the ruler of God’s creation.(C)

Read full chapter