Add parallel Print Page Options

(A)Ẹni tí ó ba ń dẹ́ṣẹ̀ tí èṣù ni; nítorí láti àtètèkọ́ṣe ni èṣù ti ń dẹ́ṣẹ̀. Nítorí èyí ni ọmọ Ọlọ́run ṣe farahàn, kí ó lè pa iṣẹ́ èṣù run.

Read full chapter

The one who does what is sinful is of the devil,(A) because the devil has been sinning from the beginning. The reason the Son of God(B) appeared was to destroy the devil’s work.(C)

Read full chapter

15 Ẹnikẹ́ni tí ó ba kórìíra arákùnrin rẹ̀ apànìyàn ni: ẹ̀yin sì mọ́ pé kò sí apànìyàn tí ó ni ìyè àìnípẹ̀kun láti máa gbé inú rẹ̀.

Read full chapter

15 Anyone who hates a brother or sister(A) is a murderer,(B) and you know that no murderer has eternal life residing in him.(C)

Read full chapter

(A)Ejò wí fún obìnrin náà pé, “Ẹ̀yin kì yóò kú ikúkíkú kan.”

Read full chapter

“You will not certainly die,” the serpent said to the woman.(A)

Read full chapter

(A)Ẹni tí ó bá wí pé, “Èmi mọ̀ ọ́n,” tí kò sì pa òfin rẹ̀ mọ́, èké ni, òtítọ́ kò sì ṣí nínú rẹ̀.

Read full chapter

Whoever says, “I know him,”(A) but does not do what he commands is a liar, and the truth is not in that person.(B)

Read full chapter

34 Ẹ̀yin ọmọ paramọ́lẹ̀, báwo ni ẹ̀yin tí ẹ jẹ búburú ṣe lè sọ̀rọ̀ rere? Ọkàn ènìyàn ni ó ń darí irú ọ̀rọ̀ tí ó lè jáde lẹ́nu rẹ̀.

Read full chapter

34 You brood of vipers,(A) how can you who are evil say anything good? For the mouth speaks(B) what the heart is full of.

Read full chapter