Saamu 85
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
Fún adarí orin. Ti àwọn ọmọ Kora. Saamu.
85 Ìwọ fi ojúrere hàn fún ilé rẹ, Olúwa;
ìwọ mú ohun ìní Jakọbu bọ̀ sí ipò.
2 Ìwọ dárí àìṣedéédéé àwọn ènìyàn rẹ jì
ìwọ sì bó ẹ̀ṣẹ̀ wọn mọ́lẹ̀. Sela.
3 Ìwọ fi àwọn ìbínú rẹ sápá kan
ìwọ sì yípadà kúrò nínú ìbínú gbígbóná rẹ.
4 Yí wa padà, Ọlọ́run ìgbàlà wa,
kí o sì yí ìbínú rẹ̀ padà kúrò lọ́dọ̀ wa.
5 Ìwọ yóò ha máa bínú sí wa títí láé?
Ìwọ yóò ha mú ìbínú rẹ pẹ́ yí gbogbo ìran ká?
6 Ìwọ kì yóò ha sọ wá jí padà mọ́,
pé kí àwọn ènìyàn rẹ lè yọ nínú rẹ?
7 Fi ìfẹ́ rẹ tí kò le è kùnà hàn wá, Olúwa,
Kí o sì fún wa ní ìgbàlà rẹ.
8 Èmi ó gbọ́ ohun tí Olúwa Ọlọ́run yóò wí;
ó ṣèlérí àlàáfíà fún àwọn ènìyàn rẹ̀, àní ẹni mímọ́ rẹ̀:
Ṣùgbọ́n má ṣe jẹ́ kí wọn padà sí àìmoye.
9 Nítòótọ́ ìgbàlà rẹ̀ súnmọ́ àwọn tí ó bẹ̀rù rẹ̀,
pé kí ògo rẹ̀ kí ó lè gbé ní ilẹ̀ wa.
10 Ìfẹ́ àti òtítọ́ parapọ̀;
òdodo àti àlàáfíà fẹnu ko ara wọn.
11 Òtítọ́ ń sun jáde láti ilẹ̀ wá
òdodo sì bojú wolẹ̀ láti ọ̀run.
12 Olúwa yóò fi ohun dídára fún ni nítòótọ́,
ilẹ̀ wa yóò sì mú ìkórè rẹ̀ jáde.
13 Òdodo síwájú rẹ lọ
o sì pèsè ọ̀nà fún ìgbésẹ̀ rẹ̀.
Psalm 85
The Voice
Psalm 85
For the worship leader. A song of the sons of Korah.
1 O Eternal One, there was a time when You were gracious to Your land;
You returned Jacob’s descendants from their captivity.
2 You forgave the iniquity of Your people,
covered all of their sins.
[pause][a]
3 There was a time when You restrained all of Your fierce wrath,
when You cooled Your hot anger.
4 O God of our salvation, bring us back again—as You did before—
and put away Your anger toward us.
5 Will You be mad at us forever?
Will You continue to be angry with our children and theirs?
6 Will You not bring us back to life once more
so that we, Your people, will find joy and pleasure in You?
7 O Eternal One, show us Your unfailing love;
give us what we truly need: Your salvation.
8 I will hear what the True God—the Eternal—will say,
for He will speak peace over His people,
peace over those who faithfully follow Him, [but do not let them abuse His gift and return to foolish ways].[b]
9 Without a doubt, His salvation is near for those who revere Him
so that He will be with us again and all His glory will fill this land.
10 Unfailing love and truth have met on their way;
righteousness and peace have kissed one another.
11 Truth will spring from the earth like a plant,
and justice will look down from the sky.
12 Yes, the Eternal will plant goodness in the earth,
and our land will yield great abundance.
13 Justice will come before Him,
marking out a path, setting a way for His feet.
Psalm 85
New King James Version
Prayer that the Lord Will Restore Favor to the Land
To the Chief Musician. A Psalm (A)of the sons of Korah.
85 Lord, You have been favorable to Your land;
You have (B)brought back the captivity of Jacob.
2 You have forgiven the iniquity of Your people;
You have covered all their sin. Selah
3 You have taken away all Your wrath;
You have turned from the fierceness of Your anger.
4 (C)Restore us, O God of our salvation,
And cause Your anger toward us to cease.
5 (D)Will You be angry with us forever?
Will You prolong Your anger to all generations?
6 Will You not (E)revive us again,
That Your people may rejoice in You?
7 Show us Your mercy, Lord,
And grant us Your salvation.
8 I will hear what God the Lord will speak,
For He will speak peace
To His people and to His saints;
But let them not turn back to [a]folly.
9 Surely (F)His salvation is near to those who fear Him,
(G)That glory may dwell in our land.
10 Mercy and truth have met together;
(H)Righteousness and peace have kissed.
11 Truth shall spring out of the earth,
And righteousness shall look down from heaven.
12 (I)Yes, the Lord will give what is good;
And our land will yield its increase.
13 Righteousness will go before Him,
And shall make His footsteps our pathway.
Footnotes
- Psalm 85:8 foolishness
Psalm 85
New International Version
Psalm 85[a]
For the director of music. Of the Sons of Korah. A psalm.
1 You, Lord, showed favor to your land;
you restored the fortunes(A) of Jacob.
2 You forgave(B) the iniquity(C) of your people
and covered all their sins.[b]
3 You set aside all your wrath(D)
and turned from your fierce anger.(E)
4 Restore(F) us again, God our Savior,(G)
and put away your displeasure toward us.
5 Will you be angry with us forever?(H)
Will you prolong your anger through all generations?
6 Will you not revive(I) us again,
that your people may rejoice(J) in you?
7 Show us your unfailing love,(K) Lord,
and grant us your salvation.(L)
8 I will listen to what God the Lord says;
he promises peace(M) to his people, his faithful servants—
but let them not turn to folly.(N)
9 Surely his salvation(O) is near those who fear him,
that his glory(P) may dwell in our land.
10 Love and faithfulness(Q) meet together;
righteousness(R) and peace kiss each other.
11 Faithfulness springs forth from the earth,
and righteousness(S) looks down from heaven.
12 The Lord will indeed give what is good,(T)
and our land will yield(U) its harvest.
13 Righteousness goes before him
and prepares the way for his steps.
Footnotes
- Psalm 85:1 In Hebrew texts 85:1-13 is numbered 85:2-14.
- Psalm 85:2 The Hebrew has Selah (a word of uncertain meaning) here.
Copyright: Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní Ẹ̀tọ́ àdàkọ © 2009, 2017 by Biblica, Inc. A lò ó nípa ìgbàyọ̀ǹda láti ọwọ́ Bíbílíkà Inc. Ààbò lórí ẹ̀tọ́ àdàkọ yìí múlẹ̀ jákèjádò àgbáyé. Yoruba Contemporary Bible Copyright © 2009, 2017 by Biblica, Inc.® Used by permission of Biblica, Inc.® All rights reserved worldwide.
The Voice Bible Copyright © 2012 Thomas Nelson, Inc. The Voice™ translation © 2012 Ecclesia Bible Society All rights reserved.
Scripture taken from the New King James Version®. Copyright © 1982 by Thomas Nelson. Used by permission. All rights reserved.
Holy Bible, New International Version®, NIV® Copyright ©1973, 1978, 1984, 2011 by Biblica, Inc.® Used by permission. All rights reserved worldwide.
NIV Reverse Interlinear Bible: English to Hebrew and English to Greek. Copyright © 2019 by Zondervan.

