Add parallel Print Page Options

Peteru bọ́ kúrò ní ẹ̀wọ̀n pẹ̀lú ìyanu

12 Ní àkókò ìgbà náà ni Herodu ọba sì nawọ́ rẹ̀ mú àwọn kan nínú ìjọ, pẹ̀lú èrò láti pọ́n wọn lójú. Ó sì fi idà pa Jakọbu arákùnrin Johanu.

Read full chapter