Ìṣe àwọn Aposteli 18:27
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
27 Nígbà tí ó sì ń fẹ́ kọjá lọ sì Akaia, àwọn arákùnrin gbà á ní ìyànjú, wọ́n sì kọ̀wé sí àwọn ọmọ-ẹ̀yìn kí wọ́n gbà á: nígbà tí ó sì dé, ó ràn àwọn tí ó gbàgbọ́ nípasẹ̀ oore-ọ̀fẹ́ lọ́wọ́ púpọ̀.
Read full chapter
Acts 18:27
New International Version
27 When Apollos wanted to go to Achaia,(A) the brothers and sisters(B) encouraged him and wrote to the disciples there to welcome him. When he arrived, he was a great help to those who by grace had believed.
Romu 16:1
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
Ìkíni
16 Mo fi Febe arábìnrin wa le yin lọ́wọ́, ẹni tí ó jẹ́ díákónì nínú ìjọ tí ó wà ní Kenkerea.
Read full chapter
Romans 16:1
New International Version
Personal Greetings
16 I commend(A) to you our sister Phoebe, a deacon[a][b] of the church in Cenchreae.(B)
Footnotes
- Romans 16:1 Or servant
- Romans 16:1 The word deacon refers here to a Christian designated to serve with the overseers/elders of the church in a variety of ways; similarly in Phil. 1:1 and 1 Tim. 3:8,12.
1 Kọrinti 16:3
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
3 (A)Àti nígbà ti mo bá dé, àwọn ẹni tí ẹ bá yàn, àwọn ni èmi ó rán láti mú ẹ̀bùn yín gòkè lọ si Jerusalẹmu.
Read full chapter
1 Corinthians 16:3
New International Version
3 Then, when I arrive, I will give letters of introduction to the men you approve(A) and send them with your gift to Jerusalem.
Copyright: Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní Ẹ̀tọ́ àdàkọ © 2009, 2017 by Biblica, Inc. A lò ó nípa ìgbàyọ̀ǹda láti ọwọ́ Bíbílíkà Inc. Ààbò lórí ẹ̀tọ́ àdàkọ yìí múlẹ̀ jákèjádò àgbáyé. Yoruba Contemporary Bible Copyright © 2009, 2017 by Biblica, Inc.® Used by permission of Biblica, Inc.® All rights reserved worldwide.
Holy Bible, New International Version®, NIV® Copyright ©1973, 1978, 1984, 2011 by Biblica, Inc.® Used by permission. All rights reserved worldwide.
NIV Reverse Interlinear Bible: English to Hebrew and English to Greek. Copyright © 2019 by Zondervan.