Saamu 88
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
Orin. Saamu ti àwọn ọmọ Kora. Fún adarí orin. Gẹ́gẹ́ bí ti mahalati leannoti. Maskili ti Hemani ará Esra.
88 Olúwa, Ọlọ́run tí ó gbà mí là,
ní ọ̀sán àti ní òru ni mo kígbe sókè sí Ọ.
2 Jẹ́ kí àdúrà mi kí ó wá sí iwájú rẹ;
dẹ etí rẹ sí igbe mi.
3 Nítorí ọkàn mi kún fún ìpọ́njú
ọkàn mi sì súnmọ́ isà òkú.
4 A kà mí mọ́ àwọn tí wọ́n lọ sí ọ̀gbun ilẹ̀
èmi dàbí ọkùnrin tí kò ni agbára.
5 A yà mí sọ́tọ̀ pẹ̀lú àwọn òkú
bí ẹni tí a pa tí ó dùbúlẹ̀ ní ipò ikú,
ẹni tí ìwọ kò rántí mọ́,
ẹni tí a gé kúrò lára àwọn tí ìwọ ń tọ́jú.
6 Ìwọ tí ó fi mí sí kòtò jíjìn,
ní ibi ọ̀gbun tó ṣókùnkùn.
7 Ìbínú rẹ ṣubú lé mi gidigidi;
ìwọ ti fi àwọn ìjì rẹ borí mi.
8 Ìwọ tí gba ọ̀rẹ́ mi tí ó súnmọ́ mi kúrò lọ́wọ́ mi
ìwọ sì sọ mi di ìríra sí wọn.
A há mi mọ́, èmi kò sì le è jáde;
9 Ojú mi káàánú nítorí ìpọ́njú.
Mo kígbe pè ọ́, Olúwa, ní gbogbo ọjọ́;
mo na ọwọ́ mi jáde sí ọ.
10 Ìwọ ó fi iṣẹ́ ìyanu rẹ hàn fún òkú bi?
Àwọn òkú yóò ha dìde láti yìn ọ́ bí?
11 A ó ha fi ìṣeun ìfẹ́ rẹ hàn ní ibojì bí:
Tàbí òtítọ́ rẹ ní ipò ìparun?
12 A ha lè mọ iṣẹ́ ìyanu rẹ ní òkùnkùn bí
àti òdodo rẹ ní ilẹ̀ ìgbàgbé?
13 Ṣùgbọ́n mo kígbe sí ọ fún ìrànlọ́wọ́, Olúwa;
ní òwúrọ̀ ni àdúrà mí wá sọ́dọ̀ rẹ.
14 Olúwa, èéṣe tí ìwọ fi kọ̀ mí
tí ìwọ fi ojú rẹ pamọ́ fún mi?
15 Láti ìgbà èwe mi, ìṣẹ́ ń ṣẹ́ mi,
èmi múra àti kú;
nígbà tí ẹ̀rù rẹ bá ń bà mí,
èmi di gbére-gbère
16 Ìbínú rẹ ti kọjá lára mi;
ìbẹ̀rù rẹ ti gé mi kúrò
17 Ní gbogbo ọjọ́ ni wọn yí mi ká bí ìkún omi;
wọ́n mù mí pátápátá.
18 Ìwọ ti mú ọ̀rẹ́ àti olùfẹ́ mi kúrò lọ́dọ̀ mi;
òkùnkùn sì jẹ́ ọ̀rẹ́ tímọ́tímọ́ mi.
Psalm 88
New English Translation
Psalm 88[a]
A song, a psalm written by the Korahites, for the music director, according to the machalath-leannoth style;[b] a well-written song[c] by Heman the Ezrahite.
88 O Lord God who delivers me,[d]
by day I cry out
and at night I pray before you.[e]
2 Listen to my prayer.[f]
Pay attention[g] to my cry for help.
3 For my life[h] is filled with troubles,
and I am ready to enter Sheol.[i]
4 They treat me like[j] those who descend into the grave.[k]
I am like a helpless man,[l]
5 adrift[m] among the dead,
like corpses lying in the grave,
whom you remember no more,
and who are cut off from your power.[n]
6 You place me in the lowest regions of the Pit,[o]
in the dark places, in the watery depths.
7 Your anger bears down on me,
and you overwhelm me with all your waves. (Selah)
8 You cause those who know me to keep their distance;
you make me an appalling sight to them.
I am trapped and cannot get free.[p]
9 My eyes grow weak because of oppression.
I call out to you, O Lord, all day long;
I spread out my hands in prayer to you.[q]
10 Do you accomplish amazing things for the dead?
Do the departed spirits[r] rise up and give you thanks? (Selah)
11 Is your loyal love proclaimed in the grave,
or your faithfulness in the place of the dead?[s]
12 Are your amazing deeds experienced[t] in the dark region,[u]
or your deliverance in the land of oblivion?[v]
13 As for me, I cry out to you, O Lord;
in the morning my prayer confronts you.
14 O Lord, why do you reject me,
and pay no attention to me?[w]
15 I am oppressed and have been on the verge of death since my youth.[x]
I have been subjected to your horrors and am numb with pain.[y]
16 Your anger overwhelms me;[z]
your terrors destroy me.
17 They surround me like water all day long;
they join forces and encircle me.[aa]
18 You cause my friends and neighbors to keep their distance;[ab]
those who know me leave me alone in the darkness.[ac]
Footnotes
- Psalm 88:1 sn Psalm 88. The psalmist cries out in pain to the Lord, begging him for relief from his intense and constant suffering. The psalmist regards God as the ultimate cause of his distress, but nevertheless clings to God in hope.
- Psalm 88:1 tn The Hebrew phrase מָחֲלַת לְעַנּוֹת (makhalat leʿannot) may mean “illness to afflict.” Perhaps it refers to a particular style of music, a tune title, or a musical instrument. The term מָחֲלַת also appears in the superscription of Ps 53.
- Psalm 88:1 tn The meaning of the Hebrew term מַשְׂכִּיל (maskil) is uncertain. The word is derived from a verb meaning “to be prudent; to be wise.” Various options are: “a contemplative song,” “a song imparting moral wisdom,” or “a skillful [i.e., well-written] song.” The term occurs in the superscriptions of Pss 32, 42, 44, 45, 52-55, 74, 78, 88, 89, and 142, as well as in Ps 47:7.
- Psalm 88:1 tn Heb “O Lord God of my deliverance.” In light of the content of the psalm, this reference to God as the one who delivers seems overly positive. For this reason some assume dittography of the י (yod) and emend the text from אֱלֹהֵי יְשׁוּעָתִי (ʾelohe yeshuʿati) to אֱלֹהַי שִׁוַּעְתִּי (ʾelohay shivvaʿtiy, “[O Lord] my God, I cry out”). See v. 13.
- Psalm 88:1 tn Heb “[by] day I cry out, in the night before you.”
- Psalm 88:2 tn Heb “may my prayer come before you.” The prefixed verbal form is understood as a jussive, indicating the psalmist’s desire or prayer.
- Psalm 88:2 tn Heb “turn your ear.”
- Psalm 88:3 tn Or “my soul.”
- Psalm 88:3 tn Heb “and my life approaches Sheol.”
- Psalm 88:4 tn Heb “I am considered with.”
- Psalm 88:4 tn Heb “the pit.” The noun בּוֹר (bor, “pit,” “cistern”) is sometimes used of the grave and/or the realm of the dead.
- Psalm 88:4 tn Heb “I am like a man [for whom] there is no help.”
- Psalm 88:5 tn Heb “set free.”
- Psalm 88:5 tn Heb “from your hand.”
- Psalm 88:6 tn The noun בּוֹר (bor, “pit,” “cistern”) is sometimes used of the grave and/or the realm of the dead. See v. 4.
- Psalm 88:8 tn Heb “[I am] confined and I cannot go out.”
- Psalm 88:9 tn Heb “I spread out my hands to you.” Spreading out the hands toward God was a prayer gesture (see Exod 9:29, 33; 1 Kgs 8:22, 38; 2 Chr 6:12-13, 29; Ezra 9:15; Job 11:13; Isa 1:15). The words “in prayer” have been supplied in the translation to clarify this.
- Psalm 88:10 tn Heb “Rephaim,” a term that refers to those who occupy the land of the dead (see Isa 14:9; 26:14, 19).
- Psalm 88:11 tn Heb “in Abaddon,” a name for Sheol. The noun is derived from a verbal root meaning “to perish,” “to die.”
- Psalm 88:12 tn Heb “known.”
- Psalm 88:12 tn Heb “darkness,” here a title for Sheol.
- Psalm 88:12 tn Heb “forgetfulness.” The noun, which occurs only here in the OT, is derived from a verbal root meaning “to forget.”sn The rhetorical questions in vv. 10-12 expect the answer, “Of course not!”
- Psalm 88:14 tn Heb “[why] do you hide your face from me?”
- Psalm 88:15 tn Heb “and am dying from youth.”
- Psalm 88:15 tn Heb “I carry your horrors [?].” The meaning of the Hebrew form אָפוּנָה (ʾafunah), which occurs only here in the OT, is unclear. It may be an adverb meaning “very much” (BDB 67 s.v.), though some prefer to emend the text to אָפוּגָה (ʾafugah, “I am numb”) from the verb פוּג (pug; see Pss 38:8; 77:2).
- Psalm 88:16 tn Heb “passes over me.”
- Psalm 88:17 tn Heb “they encircle me together.”
- Psalm 88:18 tn Heb “you cause to be far from me friend and neighbor.”
- Psalm 88:18 tn Heb “those known by me, darkness.”
Copyright: Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní Ẹ̀tọ́ àdàkọ © 2009, 2017 by Biblica, Inc. A lò ó nípa ìgbàyọ̀ǹda láti ọwọ́ Bíbílíkà Inc. Ààbò lórí ẹ̀tọ́ àdàkọ yìí múlẹ̀ jákèjádò àgbáyé. Yoruba Contemporary Bible Copyright © 2009, 2017 by Biblica, Inc.® Used by permission of Biblica, Inc.® All rights reserved worldwide.
NET Bible® copyright ©1996-2017 by Biblical Studies Press, L.L.C. http://netbible.com All rights reserved.