Font Size
Romu 6:2
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
Romu 6:2
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
2 (A)Kí a má ri! Àwa ẹni tí ó ti kú sí ẹ̀ṣẹ̀, àwa ó ha ṣe wà láààyè nínú rẹ̀ mọ́?
Read full chapter
Romu 6:11
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
Romu 6:11
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
11 (A)Nítorí náà, ẹ ka ara yín bí òkú sí ẹ̀ṣẹ̀, ṣùgbọ́n bí alààyè sí Ọlọ́run nínú Kristi Jesu.
Read full chapter
Galatia 2:19
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
Galatia 2:19
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
19 “Nítorí pé nípa òfin, mo tí di òkú sí òfin, kí èmi lè wà láààyè sí Ọlọ́run.
Read full chapter
Kolose 1:22
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
Kolose 1:22
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
22 Ṣùgbọ́n nísinsin yìí, ó ti bá yín làjà nípa ara Kristi nípa ikú láti mú un yín lọ sí iwájú rẹ̀ ní mímọ́, aláìlábàwọ́n àti kúrò nínú ìdálẹ́bi,
Read full chapter
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn (BYO)
Copyright: Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní Ẹ̀tọ́ àdàkọ © 2009, 2017 by Biblica, Inc. A lò ó nípa ìgbàyọ̀ǹda láti ọwọ́ Bíbílíkà Inc. Ààbò lórí ẹ̀tọ́ àdàkọ yìí múlẹ̀ jákèjádò àgbáyé. Yoruba Contemporary Bible Copyright © 2009, 2017 by Biblica, Inc.® Used by permission of Biblica, Inc.® All rights reserved worldwide.