Add parallel Print Page Options

11 “Nítorí náà èmi dámọ̀ràn pé: Kí gbogbo Israẹli wọ́jọ pọ̀ sọ́dọ̀ rẹ, láti Dani títí dé Beerṣeba, gẹ́gẹ́ bí iyanrìn létí Òkun fún ọ̀pọ̀lọpọ̀; àti pé, kí ìwọ tìkára rẹ̀ ó lọ sí ogun náà.

Read full chapter

11 “So I advise you: Let all Israel, from Dan to Beersheba(A)—as numerous as the sand(B) on the seashore—be gathered to you, with you yourself leading them into battle.

Read full chapter