Font Size
1 Tẹsalonika 5:25
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
1 Tẹsalonika 5:25
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
25 Ẹ̀yin ará, ẹ gbàdúrà fún wa.
Read full chapter
1 Tẹsalonika 1:8
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
1 Tẹsalonika 1:8
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
8 (A)Ọ̀rọ̀ Olúwa ti gbilẹ̀ níbi gbogbo láti ọ̀dọ̀ yín láti agbègbè Makedonia àti Akaia lọ, ìgbàgbọ́ yín nínú Ọlọ́run tàn káàkiri. Nítorí náà, a kò ni láti ṣẹ̀ṣẹ̀ ń sọ fún wọn nípa rẹ̀.
Read full chapter
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn (BYO)
Copyright: Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní Ẹ̀tọ́ àdàkọ © 2009, 2017 by Biblica, Inc. A lò ó nípa ìgbàyọ̀ǹda láti ọwọ́ Bíbílíkà Inc. Ààbò lórí ẹ̀tọ́ àdàkọ yìí múlẹ̀ jákèjádò àgbáyé. Yoruba Contemporary Bible Copyright © 2009, 2017 by Biblica, Inc.® Used by permission of Biblica, Inc.® All rights reserved worldwide.