Font Size
1 Kọrinti 10:17
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
1 Kọrinti 10:17
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
17 Nítorí àkàrà kan ni ó ń bẹ, àwa tí a pọ̀ níye, tí a sì jẹ ara kan ń pín nínú àkàrà kan ṣoṣo.
Read full chapter
1 Kọrinti 12:20
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
1 Kọrinti 12:20
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
20 Ọlọ́run dá ẹ̀yà ara púpọ̀, ṣùgbọ́n ara kan ṣoṣo ni.
Read full chapter
1 Kọrinti 12:27
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
1 Kọrinti 12:27
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
27 (A)Gbogbo yín jẹ́ ara Kristi, ẹnìkọ̀ọ̀kan yín sì jẹ́ ẹ̀yà ara ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀ nínú ara Kristi.
Read full chapter
Efesu 4:25
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
Efesu 4:25
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
25 (A)Nítorí náà ẹ fi èké ṣíṣe sílẹ̀, ki olúkúlùkù yín kí ó máa ba ọmọnìkejì rẹ̀ sọ òtítọ́, nítorí ẹ̀yà ara ọmọnìkejì wa ni àwa jẹ́.
Read full chapter
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn (BYO)
Copyright: Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní Ẹ̀tọ́ àdàkọ © 2009, 2017 by Biblica, Inc. A lò ó nípa ìgbàyọ̀ǹda láti ọwọ́ Bíbílíkà Inc. Ààbò lórí ẹ̀tọ́ àdàkọ yìí múlẹ̀ jákèjádò àgbáyé. Yoruba Contemporary Bible Copyright © 2009, 2017 by Biblica, Inc.® Used by permission of Biblica, Inc.® All rights reserved worldwide.