Font Size
Ìṣe àwọn Aposteli 2:39
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
Ìṣe àwọn Aposteli 2:39
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
39 (A)Nítorí fún yín ni ìlérí náà, àti fún àwọn ọmọ yín, àti fún gbogbo àwọn tí ó jìnnà réré, àní gbogbo àwọn tí Olúwa Ọlọ́run wa yóò pè.”
Read full chapter
Efesu 2:13
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
Efesu 2:13
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
13 Ṣùgbọ́n nísinsin yìí nínú Kristi Jesu ẹ̀yin tí ó ti jìnà réré nígbà àtijọ́ rí ni a mú súnmọ́ tòsí, nípa ẹ̀jẹ̀ Kristi.
Read full chapter
Efesu 2:17
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
Efesu 2:17
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
17 (A)Ó sì ti wá, ó sì ti wàásù àlàáfíà fún ẹ̀yin tí o jìnnà réré, àti àlàáfíà fún àwọn tí o súnmọ́ tòsí.
Read full chapter
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn (BYO)
Copyright: Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní Ẹ̀tọ́ àdàkọ © 2009, 2017 by Biblica, Inc. A lò ó nípa ìgbàyọ̀ǹda láti ọwọ́ Bíbílíkà Inc. Ààbò lórí ẹ̀tọ́ àdàkọ yìí múlẹ̀ jákèjádò àgbáyé. Yoruba Contemporary Bible Copyright © 2009, 2017 by Biblica, Inc.® Used by permission of Biblica, Inc.® All rights reserved worldwide.