Font Size
Matiu 27:32
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
Matiu 27:32
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
A kan Jesu mọ́ àgbélébùú
32 (A)Bí wọ́n sì ti ń jáde, wọ́n rí ọkùnrin kan ará Kirene tí à ń pè ní Simoni. Wọ́n sì mú ọkùnrin náà ní túláàsì láti ru àgbélébùú Jesu.
Read full chapter
Marku 15:21
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
Marku 15:21
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
Wọ́n kan Jesu mọ́ àgbélébùú
21 (A)Wọ́n rí ọkùnrin kan tí ń kọjá lọ. Simoni ará Kirene. Òun ni baba Aleksanderu àti Rufusi. Wọ́n sì mú un ní tipátipá, pé kí ó rú àgbélébùú Jesu.
Read full chapter
Johanu 19:17
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
Johanu 19:17
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
17 (A)Nítorí náà, wọ́n mú Jesu, ó sì jáde lọ, ó ru àgbélébùú fúnrarẹ̀ sí ibi tí à ń pè ní ibi agbárí, ní èdè Heberu tí à ń pè ní Gọlgọta:
Read full chapter
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn (BYO)
Copyright: Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní Ẹ̀tọ́ àdàkọ © 2009, 2017 by Biblica, Inc. A lò ó nípa ìgbàyọ̀ǹda láti ọwọ́ Bíbílíkà Inc. Ààbò lórí ẹ̀tọ́ àdàkọ yìí múlẹ̀ jákèjádò àgbáyé. Yoruba Contemporary Bible Copyright © 2009, 2017 by Biblica, Inc.® Used by permission of Biblica, Inc.® All rights reserved worldwide.