Font Size
Luku 9:51
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
Luku 9:51
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
Ìtakò àwọn ará Samaria
51 (A)Nígbà tí ọjọ́ àti gbà á sókè ń súnmọ́, ó pinnu láti lọ sí Jerusalẹmu.
Read full chapter
Johanu 10:40
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
Johanu 10:40
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
40 (A)Ó sì tún kọjá lọ sí apá kejì Jordani sí ibi tí Johanu ti kọ́kọ́ ń bamitiisi; níbẹ̀ ni ó sì jókòó.
Read full chapter
Johanu 11:7
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
Johanu 11:7
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
7 Ǹjẹ́ lẹ́yìn èyí ni ó wí fún àwọn ọmọ-ẹ̀yìn rẹ̀ pé, “Ẹ jẹ́ kí a tún padà lọ sí Judea.”
Read full chapter
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn (BYO)
Copyright: Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní Ẹ̀tọ́ àdàkọ © 2009, 2017 by Biblica, Inc. A lò ó nípa ìgbàyọ̀ǹda láti ọwọ́ Bíbílíkà Inc. Ààbò lórí ẹ̀tọ́ àdàkọ yìí múlẹ̀ jákèjádò àgbáyé. Yoruba Contemporary Bible Copyright © 2009, 2017 by Biblica, Inc.® Used by permission of Biblica, Inc.® All rights reserved worldwide.