Gẹnẹsisi 15:6
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
6 (A)Abramu gba Ọlọ́run gbọ́, a sì kà á sí òdodo fún un.
Read full chapter
Romu 4:9
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
9 Ìbùkún yìí ha jẹ́ ti àwọn akọlà nìkan, tàbí ti àwọn aláìkọlà pẹ̀lú? Nítorí tí a wí pé, Abrahamu gba Ọlọ́run gbọ́, a sì kà á sí òdodo fún un.
Read full chapter
Romu 4:22
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
22 (A)Nítorí náà ni a sì ṣe kà á sí òdodo fún un.
Read full chapter
Galatia 3:6
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
6 (A)Gẹ́gẹ́ bí Abrahamu “Ó gba Ọlọ́run gbọ́, a sì kà á sí òdodo fún un.”
Read full chapter
Jakọbu 2:23
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
23 (A)Ìwé Mímọ́ sì ṣẹ́ tí ó wí pé, “Abrahamu gba Ọlọ́run gbọ́, a sì kà á sí òdodo fún un,” a sì pè é ní ọ̀rẹ́ Ọlọ́run.
Read full chapterCopyright: Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní Ẹ̀tọ́ àdàkọ © 2009, 2017 by Biblica, Inc. A lò ó nípa ìgbàyọ̀ǹda láti ọwọ́ Bíbílíkà Inc. Ààbò lórí ẹ̀tọ́ àdàkọ yìí múlẹ̀ jákèjádò àgbáyé. Yoruba Contemporary Bible Copyright © 2009, 2017 by Biblica, Inc.® Used by permission of Biblica, Inc.® All rights reserved worldwide.